ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì

      • Ọlọ́run sọ Ìsíkíẹ́lì di wòlíì (1-10)

        • “Bóyá wọ́n gbọ́ tàbí wọn ò gbọ́” (5)

        • Ó rí àkájọ ìwé tí orin arò wà nínú rẹ̀ (9, 10)

Ìsíkíẹ́lì 2:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    “Ọmọ èèyàn”; èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìgbà 93 tí ọ̀rọ̀ yìí fara hàn nínú ìwé Ìsíkíẹ́lì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 76

Ìsíkíẹ́lì 2:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:24

Ìsíkíẹ́lì 2:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:15; Isk 33:7
  • +Ais 1:4; Jer 16:12
  • +Di 9:24; Sm 78:8; Jer 3:25; Iṣe 7:51

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2017, ojú ìwé 2

Ìsíkíẹ́lì 2:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olórí kunkun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 77

Ìsíkíẹ́lì 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 12:2
  • +Isk 3:11; 33:4, 15, 33; Jo 15:22; Iṣe 20:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 11

    5/1/1997, ojú ìwé 23

Ìsíkíẹ́lì 2:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “bó tilẹ̀ jẹ́ pé alágídí làwọn èèyàn náà tí wọ́n sì dà bí ohun tó ń gún ọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 1:15; Lk 12:4
  • +Mik 7:4
  • +Ais 51:7
  • +Jer 1:8; Isk 3:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2007, ojú ìwé 12

Ìsíkíẹ́lì 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 1:17

Ìsíkíẹ́lì 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 15:16; Ifi 10:9, 10

Ìsíkíẹ́lì 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 1:9
  • +Isk 3:1

Ìsíkíẹ́lì 2:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Orin ọ̀fọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 5:1
  • +Isk 19:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 12/2019, ojú ìwé 1

Àwọn míì

Ìsík. 2:1Da 10:11
Ìsík. 2:2Isk 3:24
Ìsík. 2:32Kr 36:15; Isk 33:7
Ìsík. 2:3Ais 1:4; Jer 16:12
Ìsík. 2:3Di 9:24; Sm 78:8; Jer 3:25; Iṣe 7:51
Ìsík. 2:4Isk 3:7
Ìsík. 2:5Isk 12:2
Ìsík. 2:5Isk 3:11; 33:4, 15, 33; Jo 15:22; Iṣe 20:26
Ìsík. 2:62Ọb 1:15; Lk 12:4
Ìsík. 2:6Mik 7:4
Ìsík. 2:6Ais 51:7
Ìsík. 2:6Jer 1:8; Isk 3:9
Ìsík. 2:7Jer 1:17
Ìsík. 2:8Jer 15:16; Ifi 10:9, 10
Ìsík. 2:9Jer 1:9
Ìsík. 2:9Isk 3:1
Ìsík. 2:10Ifi 5:1
Ìsík. 2:10Isk 19:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ìsíkíẹ́lì 2:1-10

Ìsíkíẹ́lì

2 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn,* dìde dúró kí n lè bá ọ sọ̀rọ̀.”+ 2 Nígbà tó bá mi sọ̀rọ̀, ẹ̀mí wọ inú mi, ó sì mú kí n dìde dúró+ kí n lè gbọ́ ọ̀rọ̀ Ẹni tó ń bá mi sọ̀rọ̀.

3 Ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, màá rán ọ sí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,+ sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Àwọn àti àwọn baba ńlá wọn ti ṣẹ̀ mí títí di òní yìí.+ 4 Màá rán ọ sí àwọn aláìgbọràn* ọmọ àti ọlọ́kàn líle,+ kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí.’ 5 Ní tiwọn, bóyá wọ́n gbọ́ tàbí wọn ò gbọ́, torí ọlọ̀tẹ̀ ilé+ ni wọ́n, ó dájú pé wọ́n á mọ̀ pé wòlíì kan wà láàárín wọn.+

6 “Àmọ́ ìwọ, ọmọ èèyàn, má bẹ̀rù wọn;+ má ṣe jẹ́ kí ọ̀rọ̀ wọn dẹ́rù bà ọ́, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀gún àti òṣùṣú+ yí ọ ká,* tí o sì ń gbé láàárín àwọn àkekèé. Má ṣe jẹ́ kí ọ̀rọ̀ wọn dẹ́rù bà ọ́,+ má sì jẹ́ kí ojú wọn bà ọ́ lẹ́rù,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n. 7 O gbọ́dọ̀ sọ ọ̀rọ̀ mi fún wọn, bóyá wọ́n gbọ́ tàbí wọn ò gbọ́, torí ọlọ̀tẹ̀ ni wọ́n.+

8 “Àmọ́ ìwọ, ọmọ èèyàn, gbọ́ ohun tí mò ń sọ fún ọ. Má ṣọ̀tẹ̀ bí ọlọ̀tẹ̀ ilé yìí. La ẹnu rẹ, kí o sì jẹ ohun tí mo fẹ́ fún ọ.”+

9 Ni mo bá wò, mo sì rí ọwọ́ tí ẹnì kan nà sí mi,+ mo rí àkájọ ìwé tí wọ́n kọ nǹkan sí ní ọwọ́ náà.+ 10 Nígbà tó tẹ́ ẹ síwájú mi, mo rí i pé wọ́n kọ ọ̀rọ̀ sí i níwájú àti lẹ́yìn.+ Orin arò,* ọ̀rọ̀ ìbànújẹ́ àti ìpohùnréré ẹkún ló wà nínú rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́