ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sefanáyà 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sefanáyà

      • Ọjọ́ ìdájọ́ Jèhófà ti sún mọ́lé (1-18)

        • Ọjọ́ Jèhófà ń yára bọ̀ kánkán (14)

        • Fàdákà àti wúrà kò ní lè gba àwọn èèyàn là (18)

Sefanáyà 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Jèhófà Ti Pa Á Mọ́ (Fi Ṣúra).”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:1, 2; Jer 1:2
  • +2Ọb 21:18-20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12

    3/1/1996, ojú ìwé 8

Sefanáyà 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:16; Ais 6:11; Jer 6:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12

Sefanáyà 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣe kedere pé, àwọn nǹkan tàbí iṣẹ́ tó jẹ mọ́ ìbọ̀rìṣà ni.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:25
  • +Isk 14:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12

Sefanáyà 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìràlẹ̀rálẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 25:3; Ond 2:11, 13; 2Kr 28:1, 2; Jer 11:17
  • +2Ọb 23:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12-13, 17

    3/1/1996, ojú ìwé 9, 13-14

Sefanáyà 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:1, 3; Jer 19:13
  • +Ais 48:1
  • +Joṣ 23:6, 7; 1Ọb 11:33; Jer 49:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12-13

    3/1/1996, ojú ìwé 9, 13-14

Sefanáyà 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:4; Jer 2:13
  • +Ais 43:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 12-13

    3/1/1996, ojú ìwé 9-10, 16-17

Sefanáyà 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:1; 2Pe 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 13-14

Sefanáyà 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:7; Jer 39:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 11

    2/15/2001, ojú ìwé 14

    3/1/1996, ojú ìwé 8-9

Sefanáyà 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “etí pèpéle.” Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pèpéle tí wọ́n ṣe sí ìtẹ́ ọba.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1996, ojú ìwé 9, 14

Sefanáyà 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:1, 14; Ne 3:3; 12:38, 39
  • +2Kr 34:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 14

    3/1/1996, ojú ìwé 10

Sefanáyà 1:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó jọ pé apá kan Jerúsálẹ́mù nítòsí Ẹnubodè Ẹja ni.

  • *

    Tàbí “àwọn olówò.”

  • *

    Ní Héb., “pa lẹ́nu mọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 14

    3/1/1996, ojú ìwé 10

Sefanáyà 1:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tó ń dì sórí gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ wọn,” bó ṣe máa ń rí nínú àgbá wáìnì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 10:13; 14:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jeremáyà, ojú ìwé 178-179

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 11

    2/15/2001, ojú ìwé 14-15

    3/1/1996, ojú ìwé 10, 16-17

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 83

Sefanáyà 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:11
  • +Di 28:30; Jer 5:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 14-15

    3/1/1996, ojú ìwé 9, 16-17

Sefanáyà 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sáré tete.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:1
  • +Hab 2:3
  • +Ais 66:6
  • +Ais 33:7; Joẹ 1:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2007, ojú ìwé 11

    12/15/2006, ojú ìwé 15

    2/15/2001, ojú ìwé 15-16

    3/1/1996, ojú ìwé 8, 10

Sefanáyà 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 6:17
  • +Jer 30:7
  • +Emọ 5:18, 20; Iṣe 2:20
  • +Joẹ 2:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 15-16

Sefanáyà 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:19
  • +Ais 2:12, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 15-16

Sefanáyà 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìfun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:28, 29; Ais 59:9, 10
  • +Ais 24:5; Da 9:5, 8
  • +Sm 79:2, 3; Jer 9:22; 16:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 16-17

Sefanáyà 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:4; Ais 2:20; Isk 7:19
  • +Di 32:22; Jer 7:20
  • +Jer 4:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 16-17

    3/1/1996, ojú ìwé 14

Àwọn míì

Sef. 1:12Ọb 22:1, 2; Jer 1:2
Sef. 1:12Ọb 21:18-20
Sef. 1:22Ọb 22:16; Ais 6:11; Jer 6:8
Sef. 1:3Jer 4:25
Sef. 1:3Isk 14:3
Sef. 1:4Nọ 25:3; Ond 2:11, 13; 2Kr 28:1, 2; Jer 11:17
Sef. 1:42Ọb 23:5
Sef. 1:52Kr 33:1, 3; Jer 19:13
Sef. 1:5Ais 48:1
Sef. 1:5Joṣ 23:6, 7; 1Ọb 11:33; Jer 49:1
Sef. 1:6Ais 1:4; Jer 2:13
Sef. 1:6Ais 43:22
Sef. 1:7Joẹ 2:1; 2Pe 3:10
Sef. 1:82Ọb 25:7; Jer 39:6
Sef. 1:102Kr 33:1, 14; Ne 3:3; 12:38, 39
Sef. 1:102Kr 34:22
Sef. 1:12Sm 10:13; 14:1
Sef. 1:13Ais 6:11
Sef. 1:13Di 28:30; Jer 5:17
Sef. 1:14Joẹ 2:1
Sef. 1:14Hab 2:3
Sef. 1:14Ais 66:6
Sef. 1:14Ais 33:7; Joẹ 1:15
Sef. 1:15Ifi 6:17
Sef. 1:15Jer 30:7
Sef. 1:15Emọ 5:18, 20; Iṣe 2:20
Sef. 1:15Joẹ 2:2
Sef. 1:16Jer 4:19
Sef. 1:16Ais 2:12, 15
Sef. 1:17Di 28:28, 29; Ais 59:9, 10
Sef. 1:17Ais 24:5; Da 9:5, 8
Sef. 1:17Sm 79:2, 3; Jer 9:22; 16:4
Sef. 1:18Owe 11:4; Ais 2:20; Isk 7:19
Sef. 1:18Di 32:22; Jer 7:20
Sef. 1:18Jer 4:27
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sefanáyà 1:1-18

Sefanáyà

1 Ọ̀rọ̀ Jèhófà sí Sefanáyà* ọmọ Kúúṣì, ọmọ Gẹdaláyà, ọmọ Amaráyà, ọmọ Hẹsikáyà nígbà ayé Jòsáyà+ ọmọ Ámọ́nì+ ọba Júdà:

 2 “Màá pa ohun gbogbo rẹ́ ráúráú kúrò lórí ilẹ̀,” ni Jèhófà wí.+

 3 “Màá pa èèyàn àti ẹranko rẹ́.

Màá pa ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹja inú òkun rẹ́+

Àti àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀*+ pẹ̀lú àwọn èèyàn burúkú;

Màá sì mú àwọn èèyàn kúrò lórí ilẹ̀,” ni Jèhófà wí.

 4 “Màá na ọwọ́ mi sórí Júdà

Àti sórí gbogbo àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù,

Gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn tó ń sin* Báálì+ ní ibí yìí ni màá sì pa rẹ́,

Àti orúkọ àwọn àlùfáà ọlọ́run àjèjì pa pọ̀ pẹ̀lú àwọn àlùfáà míì,+

 5 Àti àwọn tó ń forí balẹ̀ lórí òrùlé fún àwọn ọmọ ogun ọ̀run+

Àti àwọn tó ń forí balẹ̀, tí wọ́n ń jẹ́jẹ̀ẹ́ pé ti Jèhófà+ làwọn ń ṣe

Lẹ́sẹ̀ kan náà, tí wọ́n ń jẹ́jẹ̀ẹ́ pé ti Málíkámù làwọn ń ṣe;+

 6 Àti àwọn tó pa dà lẹ́yìn Jèhófà+

Àti àwọn tí kò wá Jèhófà tàbí àwọn tí kò wádìí nípa rẹ̀.”+

 7 Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, nítorí ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé.+

Jèhófà ti pèsè ẹbọ sílẹ̀, ó sì ti ya àwọn tí ó pè sí mímọ́.

 8 “Ní ọjọ́ tí Jèhófà pèsè ẹbọ, màá pe àwọn ìjòyè wá jíhìn,

Àwọn ọmọ ọba+ àti gbogbo àwọn tó ń wọ aṣọ ilẹ̀ òkèèrè.

 9 Màá sì pe gbogbo ẹni tó ń gun pèpéle* wá jíhìn ní ọjọ́ yẹn,

Àwọn tó ń mú kí ìwà ipá àti ẹ̀tàn gbilẹ̀ ní ilé ọ̀gá wọn.

10 Ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí,

“Igbe ẹkún máa wá láti Ẹnubodè Ẹja+

Àti ìpohùnréré ẹkún láti Apá Kejì ìlú náà+

Àti ìfọ́yángá láti àwọn òkè.

11 Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin tó ń gbé Mákítẹ́ṣì,*

Torí pé gbogbo àwọn oníṣòwò* ni wọ́n ti pa rẹ́;*

Gbogbo àwọn tó ń wọn fàdákà ni wọ́n sì ti pa run.

12 Ní àkókò yẹn, màá fi fìtílà wá inú Jerúsálẹ́mù fínnífínní,

Màá sì pe àwọn tó dẹra nù* wá jíhìn, àwọn tó ń sọ nínú ọkàn wọn pé,

‘Jèhófà kò ní ṣe rere, kò sì ní ṣe búburú.’+

13 Wọ́n á kó ọrọ̀ wọn lọ, wọ́n á sì pa ilé wọn run.+

Wọ́n á kọ́ ilé, ṣùgbọ́n wọn kò ní gbé inú rẹ̀;

Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, ṣùgbọ́n wọn kò ní mu wáìnì rẹ̀.+

14 Ọjọ́ ńlá Jèhófà sún mọ́lé!+

Ó sún mọ́lé, ó sì ń yára bọ̀ kánkán!*+

Ìró ọjọ́ Jèhófà korò.+

Akíkanjú ológun máa figbe ta níbẹ̀.+

15 Ọjọ́ yẹn jẹ́ ọjọ́ ìbínú ńlá,+

Ọjọ́ wàhálà àti ìdààmú,+

Ọjọ́ ìjì àti ìsọdahoro,

Ọjọ́ òkùnkùn àti ìṣúdùdù,+

Ọjọ́ ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà,+

16 Ọjọ́ ìwo àti ariwo ogun,+

Lòdì sí àwọn ìlú olódi àti sí àwọn ilé gogoro tó wà ní àwọn ìkángun odi.+

17 Màá fa wàhálà bá aráyé,

Wọ́n á sì máa rìn bí afọ́jú,+

Nítorí pé wọ́n ti ṣẹ Jèhófà.+

A ó tú ẹ̀jẹ̀ wọn jáde bí eruku

Àti ẹran ara* wọn bí ìgbẹ́.+

18 Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n ní ọjọ́ ìbínú ńlá Jèhófà;+

Torí ìtara rẹ̀ tó ń jó bí iná máa jó gbogbo ayé run,+

Nítorí ó máa pa àwọn èèyàn ayé nípakúpa, àní á pa wọ́n yán-án yán-án.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́