ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tímótì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tímótì

      • Ohun tí alábòójútó gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (1-7)

      • Ohun tí ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (8-13)

      • Àṣírí mímọ́ ti ìfọkànsin Ọlọ́run (14-16)

1 Tímótì 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:28; Tit 1:5-9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32-33, 39-40

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 21

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2014, ojú ìwé 3-4

    5/15/2010, ojú ìwé 24

    1/1/2001, ojú ìwé 9

    7/1/2000, ojú ìwé 29

    12/1/1999, ojú ìwé 28

    8/1/1999, ojú ìwé 13-14

1 Tímótì 3:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “làákàyè; òye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:3; 1Pe 4:7
  • +Iṣe 28:7; 1Pe 4:9
  • +1Ti 5:17; 2Ti 2:24; Tit 1:7, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32, 34-37

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 29

    9/15/1999, ojú ìwé 10

    1/1/1997, ojú ìwé 28

    10/15/1996, ojú ìwé 17

    Jí!,

    6/8/1998, ojú ìwé 16-17

1 Tímótì 3:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aluni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:13
  • +Flp 4:5; Jem 3:17
  • +Ro 12:18; Jem 3:18
  • +Heb 13:5; 1Pe 5:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32, 34-36

1 Tímótì 3:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń tọ́jú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32, 34, 133-134

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 26

    10/15/1996, ojú ìwé 20-21

    5/15/1993, ojú ìwé 17-19

1 Tímótì 3:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tọ́jú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32, 34

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2012, ojú ìwé 9

    10/15/1996, ojú ìwé 20-24

    5/15/1993, ojú ìwé 17-19

1 Tímótì 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32-33

1 Tímótì 3:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa sọ pé ó níwà rere.”

  • *

    Tàbí “ìtìjú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 22:12; 1Tẹ 4:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 32, 34

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2005, ojú ìwé 30

1 Tímótì 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fi ọ̀rọ̀ tanni jẹ.”

  • *

    Ní Grk., “wáìnì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 6:3; Tit 1:7; 1Pe 5:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

1 Tímótì 3:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 1:5, 18, 19; 2Ti 1:3; 1Pe 3:16

1 Tímótì 3:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bóyá wọ́n tóótun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 54-55

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2011, ojú ìwé 11

    5/1/2006, ojú ìwé 23-24

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    5/2000, ojú ìwé 8

1 Tímótì 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:13
  • +Tit 2:3-5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 17

1 Tímótì 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 133-134

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/1997, ojú ìwé 28

1 Tímótì 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

1 Tímótì 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2007, ojú ìwé 29

1 Tímótì 3:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:14; Flp 2:7
  • +1Pe 3:18
  • +1Pe 3:19, 20
  • +Kol 1:23
  • +Kol 1:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 196

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 30-31

    6/15/2008, ojú ìwé 13

    2/15/2006, ojú ìwé 19

    10/15/1997, ojú ìwé 11

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 57

Àwọn míì

1 Tím. 3:1Iṣe 20:28; Tit 1:5-9
1 Tím. 3:2Ro 12:3; 1Pe 4:7
1 Tím. 3:2Iṣe 28:7; 1Pe 4:9
1 Tím. 3:21Ti 5:17; 2Ti 2:24; Tit 1:7, 9
1 Tím. 3:3Ro 13:13
1 Tím. 3:3Flp 4:5; Jem 3:17
1 Tím. 3:3Ro 12:18; Jem 3:18
1 Tím. 3:3Heb 13:5; 1Pe 5:2
1 Tím. 3:4Ef 6:4
1 Tím. 3:61Ti 5:22
1 Tím. 3:7Iṣe 22:12; 1Tẹ 4:11, 12
1 Tím. 3:8Iṣe 6:3; Tit 1:7; 1Pe 5:2
1 Tím. 3:91Ti 1:5, 18, 19; 2Ti 1:3; 1Pe 3:16
1 Tím. 3:101Pe 2:12
1 Tím. 3:111Ti 5:13
1 Tím. 3:11Tit 2:3-5
1 Tím. 3:15Heb 3:6
1 Tím. 3:16Jo 1:14; Flp 2:7
1 Tím. 3:161Pe 3:18
1 Tím. 3:161Pe 3:19, 20
1 Tím. 3:16Kol 1:23
1 Tím. 3:16Kol 1:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Tímótì 3:1-16

Ìwé Kìíní sí Tímótì

3 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé: Tí ọkùnrin kan bá ń sapá láti di alábòójútó,+ iṣẹ́ rere ló fẹ́ ṣe. 2 Nítorí náà, alábòójútó gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tí kò lẹ́gàn, tí kò ní ju ìyàwó kan lọ, tí kì í ṣe àṣejù, tó ní àròjinlẹ̀,*+ tó wà létòlétò, tó ń ṣe aájò àlejò,+ tó kúnjú ìwọ̀n láti kọ́ni,+ 3 kì í ṣe ọ̀mùtí,+ kì í ṣe oníwà ipá,* àmọ́ kó máa fòye báni lò,+ kì í ṣe oníjà,+ kì í ṣe ẹni tó fẹ́ràn owó,+ 4 kó jẹ́ ọkùnrin tó ń bójú tó* ilé rẹ̀ dáadáa, tí àwọn ọmọ rẹ̀ máa ń tẹrí ba, tí wọ́n sì jẹ́ onígbọràn+ 5 (torí tí ọkùnrin kan ò bá mọ bó ṣe máa bójú tó* ilé ara rẹ̀, báwo ló ṣe máa bójú tó ìjọ Ọlọ́run?), 6 kì í ṣe ẹni tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ yí lọ́kàn pa dà,+ torí ó lè bẹ̀rẹ̀ sí í gbéra ga, kó sì ṣubú sínú ìdájọ́ tí a ṣe fún Èṣù. 7 Yàtọ̀ síyẹn, ó yẹ kí àwọn tó wà níta+ máa sọ̀rọ̀ rẹ̀ dáadáa* kó má bàa ṣubú sínú ẹ̀gàn* àti pańpẹ́ Èṣù.

8 Bákan náà, kí àwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ẹni tó ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan, kí wọ́n má ṣe jẹ́ ẹlẹ́nu méjì,* kí wọ́n má ṣe máa mu ọtí* lámujù, kí wọ́n má ṣe máa wá èrè tí kò tọ́,+ 9 kí wọ́n ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́+ bí wọ́n ti ń rọ̀ mọ́ àṣírí mímọ́ ti ìgbàgbọ́.

10 Bákan náà, ká kọ́kọ́ dán wọn wò bóyá wọ́n kúnjú ìwọ̀n;* lẹ́yìn náà kí wọ́n di òjíṣẹ́, nítorí wọn ò ní ẹ̀sùn lọ́rùn.+

11 Kí àwọn obìnrin pẹ̀lú jẹ́ ẹni tó ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan, kí wọ́n má ṣe jẹ́ abanijẹ́,+ kí wọ́n má ṣe jẹ́ aláṣejù, kí wọ́n jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun gbogbo.+

12 Kí àwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ má ṣe ní ju ìyàwó kan lọ, kí wọ́n máa bójú tó àwọn ọmọ wọn àti ìdílé wọn dáadáa. 13 Torí àwọn ọkùnrin tó ń ṣe ìránṣẹ́ lọ́nà tó dáa ń ṣe orúkọ rere fún ara wọn, wọ́n á sì lè sọ̀rọ̀ fàlàlà nípa ìgbàgbọ́ tí a ní nínú Kristi Jésù.

14 Bí mo tiẹ̀ ń retí láti wá sọ́dọ̀ rẹ láìpẹ́, mò ń kọ àwọn nǹkan yìí sí ọ, 15 torí tí mi ò bá tètè dé, kí o lè mọ bó ṣe yẹ kí o máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run,+ tó jẹ́ ìjọ Ọlọ́run alààyè, òpó àti ìtìlẹyìn òtítọ́. 16 Ní tòótọ́, a gbà pé àṣírí mímọ́ ti ìfọkànsin Ọlọ́run yìí ga lọ́lá: ‘A fi í hàn nínú ẹran ara,+ a kéde pé ó jẹ́ olódodo nínú ẹ̀mí,+ ó fara han àwọn áńgẹ́lì,+ a wàásù nípa rẹ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ a gbà á gbọ́ ní ayé,+ a sì gbà á sókè nínú ògo.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́