ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Ábúrámù dá (1-21)

        • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìjìyà fún 400 ọdún (13)

        • Ọlọ́run tún ṣèlérí fún Ábúrámù (18-21)

Jẹ́nẹ́sísì 15:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 27:1; Ais 41:10; Ro 8:31; Heb 13:6
  • +Di 33:29; Owe 30:5
  • +Jẹ 17:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2010, ojú ìwé 8

Jẹ́nẹ́sísì 15:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 24:2, 3

Jẹ́nẹ́sísì 15:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:7; Iṣe 7:5

Jẹ́nẹ́sísì 15:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹni tó wá látinú ara rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 17:15, 16; 21:12

Jẹ́nẹ́sísì 15:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 22:17; Di 1:10; Ro 4:18; Heb 11:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 27-28

    1/15/1998, ojú ìwé 10-11

Jẹ́nẹ́sísì 15:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 11:8
  • +Ro 4:13, 22; Ga 3:6; Jem 2:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2008, ojú ìwé 21

    1/15/2004, ojú ìwé 27-28

    1/15/1998, ojú ìwé 10-11

Jẹ́nẹ́sísì 15:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:31; Ne 9:7

Jẹ́nẹ́sísì 15:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ó sì kọjú wọn síra kí wọ́n lè bára mu.”

Jẹ́nẹ́sísì 15:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 21:9; Ẹk 1:13, 14; 3:7; Iṣe 7:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2016, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 27

    9/15/1998, ojú ìwé 12-13

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 101

Jẹ́nẹ́sísì 15:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 7:4; Nọ 33:4
  • +Ẹk 3:22; Sm 105:37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/1998, ojú ìwé 12-13

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 10

Jẹ́nẹ́sísì 15:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 25:8

Jẹ́nẹ́sísì 15:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 14:1; Iṣe 7:7
  • +1Ọb 21:26; 2Ọb 21:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 62-63

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2010, ojú ìwé 14

    1/15/2004, ojú ìwé 28

    6/1/1999, ojú ìwé 5

    4/1/1997, ojú ìwé 17-18

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 101

Jẹ́nẹ́sísì 15:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 17:19; 22:17
  • +Ẹk 3:8
  • +1Ọb 4:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2010, ojú ìwé 13

    10/1/2005, ojú ìwé 11

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 74-75

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 101

Jẹ́nẹ́sísì 15:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 15:6

Jẹ́nẹ́sísì 15:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 1:4
  • +Ẹk 3:17
  • +Joṣ 17:15

Jẹ́nẹ́sísì 15:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:1

Àwọn míì

Jẹ́n. 15:1Sm 27:1; Ais 41:10; Ro 8:31; Heb 13:6
Jẹ́n. 15:1Di 33:29; Owe 30:5
Jẹ́n. 15:1Jẹ 17:5, 6
Jẹ́n. 15:2Jẹ 24:2, 3
Jẹ́n. 15:3Jẹ 12:7; Iṣe 7:5
Jẹ́n. 15:4Jẹ 17:15, 16; 21:12
Jẹ́n. 15:5Jẹ 22:17; Di 1:10; Ro 4:18; Heb 11:12
Jẹ́n. 15:6Heb 11:8
Jẹ́n. 15:6Ro 4:13, 22; Ga 3:6; Jem 2:23
Jẹ́n. 15:7Jẹ 11:31; Ne 9:7
Jẹ́n. 15:13Jẹ 21:9; Ẹk 1:13, 14; 3:7; Iṣe 7:6, 7
Jẹ́n. 15:14Ẹk 7:4; Nọ 33:4
Jẹ́n. 15:14Ẹk 3:22; Sm 105:37
Jẹ́n. 15:15Jẹ 25:8
Jẹ́n. 15:16Joṣ 14:1; Iṣe 7:7
Jẹ́n. 15:161Ọb 21:26; 2Ọb 21:11
Jẹ́n. 15:18Jẹ 17:19; 22:17
Jẹ́n. 15:18Ẹk 3:8
Jẹ́n. 15:181Ọb 4:21
Jẹ́n. 15:191Sa 15:6
Jẹ́n. 15:20Joṣ 1:4
Jẹ́n. 15:20Ẹk 3:17
Jẹ́n. 15:20Joṣ 17:15
Jẹ́n. 15:21Di 7:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 15:1-21

Jẹ́nẹ́sísì

15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ 2 Ábúrámù fèsì pé: “Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, kí lo máa fún mi, bí o ṣe rí i pé mi ò tíì bímọ, tó sì jẹ́ pé Élíésérì,+ ọkùnrin ará Damásíkù ni yóò jogún ilé mi?” 3 Ábúrámù fi kún un pé: “O ò fún mi ní ọmọ,*+ ará* ilé mi ló sì máa jogún ohun tí mo ní.” 4 Àmọ́, èsì tí Jèhófà fún un ni pé: “Ọkùnrin yìí ò ní jogún rẹ, ọmọ rẹ* ni yóò jogún rẹ.”+

5 Ó wá mú un wá sí ìta, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, gbójú sókè wo ọ̀run, kí o sì ka àwọn ìràwọ̀, tí o bá lè kà á.” Ó sì sọ fún un pé: “Bí ọmọ* rẹ á ṣe pọ̀ nìyẹn.”+ 6 Ábúrámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,+ Ó sì kà á sí òdodo fún un.+ 7 Ó wá fi kún un pé: “Èmi ni Jèhófà, ẹni tó mú ọ kúrò ní Úrì ti àwọn ará Kálídíà láti fún ọ ní ilẹ̀ yìí kó lè di ohun ìní+ rẹ.” 8 Ó bi í pé: “Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, báwo ni màá ṣe mọ̀ pé ilẹ̀ yìí máa di ohun ìní mi?” 9 Ó fèsì pé: “Mú abo ọmọ màlúù ọlọ́dún mẹ́ta kan wá fún mi àti abo ewúrẹ́ ọlọ́dún mẹ́ta kan, àgbò ọlọ́dún mẹ́ta kan, ẹyẹ oriri kan àti ọmọ ẹyẹlé kan.” 10 Ó wá kó gbogbo rẹ̀, ó gé wọn sí méjì-méjì, ó sì kọjú wọn síra,* àmọ́ kò gé àwọn ẹyẹ náà. 11 Àwọn ẹyẹ aṣọdẹ wá ń bà lé àwọn òkú ẹran náà, àmọ́ Ábúrámù ń lé wọn.

12 Nígbà tó kù díẹ̀ kí oòrùn wọ̀, Ábúrámù sùn lọ fọnfọn, òkùnkùn biribiri tó ń dẹ́rù bani sì ṣú bò ó. 13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+ 14 Àmọ́ màá dá orílẹ̀-èdè tí wọn yóò sìn+ lẹ́jọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n á kó ọ̀pọ̀ ẹrù+ jáde. 15 Ní tìrẹ, wàá lọ sọ́dọ̀ àwọn baba ńlá rẹ ní àlàáfíà; wàá dàgbà, wàá darúgbó kí o tó kú.+ 16 Àmọ́ ìran wọn kẹrin á pa dà síbí,+ torí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn Ámórì kò tíì kún rẹ́rẹ́.”+

17 Nígbà tí oòrùn wọ̀, tí ilẹ̀ sì ti ṣú, iná ìléru tó ń rú èéfín fara hàn, iná ògùṣọ̀ sì kọjá láàárín àwọn ẹran tó gé. 18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+ 19 ilẹ̀ àwọn Kénì,+ àwọn ọmọ Kénásì, àwọn Kádímónì, 20 àwọn ọmọ Hétì,+ àwọn Pérísì,+ àwọn Réfáímù,+ 21 àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn Gẹ́gáṣì àti àwọn ará Jébúsì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́