ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jémíìsì 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

      • Ìkìlọ̀ fún àwọn ọlọ́rọ̀ (1-6)

      • Ọlọ́run ń bù kún àwọn tó ní sùúrù àti ìfaradà (7-11)

      • Ẹ jẹ́ kí “bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni (12)

      • Àdúrà ìgbàgbọ́ lágbára (13-18)

      • Ran ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́ kó lè yí pa dà (19, 20)

Jémíìsì 5:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:28; Lk 6:24; 18:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21-22

Jémíìsì 5:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kòkòrò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 6:19; Lk 12:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21-22

Jémíìsì 5:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 7:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21-22

Jémíìsì 5:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:13; Di 24:14, 15; Jer 22:13; Mal 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22

Jémíìsì 5:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 12:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22

Jémíìsì 5:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22

Jémíìsì 5:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:3
  • +Di 11:14; Jer 5:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2017, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2012, ojú ìwé 21

    5/1/1999, ojú ìwé 24

    11/15/1997, ojú ìwé 19, 22

Jémíìsì 5:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 6:12
  • +1Tẹ 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1999, ojú ìwé 24

    11/15/1997, ojú ìwé 19, 22

Jémíìsì 5:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kùn sí; ráhùn sí.” Ní Grk., “mí ìmí ẹ̀dùn lòdì sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 4:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22

Jémíìsì 5:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:16
  • +Mt 5:12
  • +Heb 6:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2006, ojú ìwé 19-20

    9/15/1994, ojú ìwé 15-20

Jémíìsì 5:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹni ìbùkún.”

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Tàbí “máa ń gba tẹni rò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:2-4
  • +Job 1:20, 21
  • +Job 42:10
  • +Sm 103:8; Lk 6:36

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2022, ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 15

    2/2021, ojú ìwé 31

    1/2021, ojú ìwé 21

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2006, ojú ìwé 29

    10/1/2004, ojú ìwé 19

    12/15/1995, ojú ìwé 18

    11/15/1994, ojú ìwé 23-24

    11/1/1994, ojú ìwé 9-15

Jémíìsì 5:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:34-37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22

Jémíìsì 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 50:15
  • +Kol 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 22-23

    5/15/1993, ojú ìwé 15

Jémíìsì 5:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:28, 35; 1Pe 5:2
  • +Sm 141:5; Mk 6:13; Lk 10:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 30

    6/15/2011, ojú ìwé 22

    9/1/2010, ojú ìwé 24

    11/15/2006, ojú ìwé 28

    10/1/2002, ojú ìwé 31

    6/1/2001, ojú ìwé 30-31

    11/15/1997, ojú ìwé 23

    8/15/1997, ojú ìwé 29

    9/1/1996, ojú ìwé 30

    5/15/1993, ojú ìwé 15-16

    9/15/1992, ojú ìwé 12

    6/1/1992, ojú ìwé 19

    3/15/1991, ojú ìwé 6-7

Jémíìsì 5:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ẹni tó ti rẹ̀ náà.”

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 24

    6/1/2001, ojú ìwé 30-31

    11/15/1997, ojú ìwé 23

    8/15/1997, ojú ìwé 29

    9/1/1996, ojú ìwé 30

    5/15/1993, ojú ìwé 15-17

    3/15/1991, ojú ìwé 6-7

Jémíìsì 5:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “máa ń ní ipa púpọ̀ tó bá wà lẹ́nu iṣẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 12:13; Sm 32:5; Owe 28:13; 1Jo 1:9
  • +1Sa 12:18; 1Ọb 13:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 23-24

    11/15/1997, ojú ìwé 23-24

    5/15/1993, ojú ìwé 15

    3/15/1991, ojú ìwé 6-7

Jémíìsì 5:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 17:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2008, ojú ìwé 19

    4/1/2005, ojú ìwé 27-28

    3/1/1998, ojú ìwé 27

    7/15/1992, ojú ìwé 19

    4/1/1992, ojú ìwé 17

Jémíìsì 5:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 18:42, 45

Jémíìsì 5:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 24

Jémíìsì 5:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gba ọkàn rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 6:1
  • +1Ti 4:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 20

    11/15/1997, ojú ìwé 24

Àwọn míì

Jém. 5:1Owe 11:28; Lk 6:24; 18:25
Jém. 5:2Mt 6:19; Lk 12:33
Jém. 5:3Isk 7:19
Jém. 5:4Le 19:13; Di 24:14, 15; Jer 22:13; Mal 3:5
Jém. 5:5Jer 12:3
Jém. 5:7Mt 24:3
Jém. 5:7Di 11:14; Jer 5:24
Jém. 5:8Heb 6:12
Jém. 5:81Tẹ 3:13
Jém. 5:91Kọ 4:5
Jém. 5:102Kr 36:16
Jém. 5:10Mt 5:12
Jém. 5:10Heb 6:12
Jém. 5:11Jem 1:2-4
Jém. 5:11Job 1:20, 21
Jém. 5:11Job 42:10
Jém. 5:11Sm 103:8; Lk 6:36
Jém. 5:12Mt 5:34-37
Jém. 5:13Sm 50:15
Jém. 5:13Kol 3:16
Jém. 5:14Iṣe 20:28, 35; 1Pe 5:2
Jém. 5:14Sm 141:5; Mk 6:13; Lk 10:34
Jém. 5:162Sa 12:13; Sm 32:5; Owe 28:13; 1Jo 1:9
Jém. 5:161Sa 12:18; 1Ọb 13:6
Jém. 5:171Ọb 17:1
Jém. 5:181Ọb 18:42, 45
Jém. 5:20Ga 6:1
Jém. 5:201Ti 4:16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jémíìsì 5:1-20

Lẹ́tà Jémíìsì

5 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọlọ́rọ̀, ẹ sunkún, kí ẹ sì pohùn réré ẹkún torí ìbànújẹ́ tó máa bá yín.+ 2 Ọrọ̀ yín ti jẹrà, òólá* sì ti jẹ àwọn aṣọ yín.+ 3 Wúrà àti fàdákà yín ti dípẹtà, ìpẹtà wọn máa jẹ́ ẹ̀rí lòdì sí yín, ó sì máa jẹ ẹran ara yín. Ohun tí ẹ kó jọ máa dà bí iná ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn.+ 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ 5 Ẹ ti gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ, ẹ sì ti tẹ́ ara yín lọ́rùn ní ayé. Ẹ ti bọ́ ọkàn yín yó ní ọjọ́ pípa.+ 6 Ẹ ti dáni lẹ́bi; ẹ ti pa olódodo. Ṣebí ó ń ta kò yín?

7 Nítorí náà, ẹ̀yin ará, ẹ ní sùúrù, títí di ìgbà tí Olúwa máa wà níhìn-ín.+ Ẹ wò ó! Àgbẹ̀ máa ń dúró kí ilẹ̀ mú èso tó ṣeyebíye jáde, ó máa ń ní sùúrù títí òjò àkọ́rọ̀ àti òjò àrọ̀kẹ́yìn á fi rọ̀.+ 8 Kí ẹ̀yin náà ní sùúrù;+ ẹ mọ́kàn le, torí ìgbà tí Olúwa máa wà níhìn-ín ti sún mọ́lé.+

9 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣàríwísí* ara yín, kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́.+ Ẹ wò ó! Onídàájọ́ ti wà lẹ́nu ilẹ̀kùn. 10 Ẹ̀yin ará, ẹ jẹ́ kí àwọn wòlíì tó sọ̀rọ̀ ní orúkọ Jèhófà*+ jẹ́ àpẹẹrẹ fún yín nínú jíjìyà ibi+ àti níní sùúrù.+ 11 Ẹ wò ó! A ka àwọn tó ní ìfaradà sí aláyọ̀.*+ Ẹ ti gbọ́ nípa ìfaradà Jóòbù,+ ẹ sì ti rí ibi tí Jèhófà* jẹ́ kó yọrí sí,+ pé Jèhófà* ní ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ tó pọ̀ gan-an,* ó sì jẹ́ aláàánú.+

12 Ju gbogbo rẹ̀ lọ ẹ̀yin ará mi, ẹ má ṣe búra mọ́, ì báà jẹ́ ọ̀run tàbí ayé lẹ fi búra tàbí ìbúra èyíkéyìí míì. Àmọ́ kí “Bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni, kí “Bẹ́ẹ̀ kọ́” yín sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ kọ́,+ kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́.

13 Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí nǹkan nira fún? Kó má ṣe dákẹ́ àdúrà.+ Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí inú rẹ̀ ń dùn? Kó máa kọ sáàmù.+ 14 Ṣé ẹnikẹ́ni ń ṣàìsàn láàárín yín? Kó pe àwọn alàgbà+ ìjọ, kí wọ́n gbàdúrà lé e lórí, kí wọ́n fi òróró pa á+ ní orúkọ Jèhófà.* 15 Àdúrà ìgbàgbọ́ sì máa mú aláìsàn náà* lára dá, Jèhófà* máa gbé e dìde. Tó bá sì ti dẹ́ṣẹ̀, a máa dárí jì í.

16 Nítorí náà, ẹ máa jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ fún ara yín láìfi ohunkóhun pa mọ́, kí ẹ sì máa gbàdúrà fún ara yín, ká lè mú yín lára dá. Ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ olódodo lágbára gan-an.*+ 17 Ẹni tó máa ń mọ nǹkan lára bíi tiwa ni Èlíjà, síbẹ̀, nígbà tó gbàdúrà taratara pé kí òjò má rọ̀, òjò ò rọ̀ sórí ilẹ̀ náà fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà.+ 18 Ó tún gbàdúrà, òjò sì rọ̀ láti ọ̀run, ilẹ̀ wá mú èso jáde.+

19 Ẹ̀yin ará mi, tí a bá mú ẹnikẹ́ni láàárín yín ṣìnà kúrò nínú òtítọ́, tí ẹlòmíì sì yí i pa dà, 20 kí ẹ mọ̀ pé ẹni tó bá yí ẹlẹ́ṣẹ̀ pa dà kúrò nínú ìṣìnà+ rẹ̀ máa gbà á* lọ́wọ́ ikú, ó sì máa bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́lẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́