ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Ábúrámù pa dà sí Kénáánì (1-4)

      • Ábúrámù àti Lọ́ọ̀tì lọ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ (5-13)

      • Ọlọ́run tún ṣèlérí fún Ábúrámù (14-18)

Jẹ́nẹ́sísì 13:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:9; 20:1

Jẹ́nẹ́sísì 13:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 24:34, 35

Jẹ́nẹ́sísì 13:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:8, 9; Joṣ 7:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 5 2017 ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 21-22

Jẹ́nẹ́sísì 13:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 21-22

Jẹ́nẹ́sísì 13:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 22

Jẹ́nẹ́sísì 13:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 22

Jẹ́nẹ́sísì 13:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2016, ojú ìwé 5-6

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2004, ojú ìwé 27

    8/15/2001, ojú ìwé 26-27

    8/15/2000, ojú ìwé 24

Jẹ́nẹ́sísì 13:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2016, ojú ìwé 5-6

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2004, ojú ìwé 27

    1/15/2004, ojú ìwé 27

    8/15/2001, ojú ìwé 22-23, 26-27

Jẹ́nẹ́sísì 13:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:28
  • +Jẹ 2:8, 9
  • +Jẹ 19:20-22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 22

Jẹ́nẹ́sísì 13:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 22

    11/15/1992, ojú ìwé 13-14

Jẹ́nẹ́sísì 13:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:28, 29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 22

    11/15/1992, ojú ìwé 13-14

Jẹ́nẹ́sísì 13:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 18:20; 19:5; 2Pe 2:6-8; Jud 7

Jẹ́nẹ́sísì 13:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 2/2020, ojú ìwé 1

Jẹ́nẹ́sísì 13:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:7; 15:18; 24:7; Ẹk 33:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 2/2020, ojú ìwé 1

Jẹ́nẹ́sísì 13:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:2; 15:1, 5; Ẹk 1:7; Heb 11:12

Jẹ́nẹ́sísì 13:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 2/2020, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2004, ojú ìwé 13-14

    8/15/2001, ojú ìwé 23

Jẹ́nẹ́sísì 13:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 18:1; 23:19; 25:9, 10; 35:27
  • +Jẹ 23:2
  • +Jẹ 12:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2001, ojú ìwé 23

    2/2020, ojú ìwé 5-6

Àwọn míì

Jẹ́n. 13:1Jẹ 12:9; 20:1
Jẹ́n. 13:2Jẹ 24:34, 35
Jẹ́n. 13:3Jẹ 12:8, 9; Joṣ 7:2
Jẹ́n. 13:7Jẹ 10:19
Jẹ́n. 13:8Jẹ 11:27
Jẹ́n. 13:10Jẹ 19:28
Jẹ́n. 13:10Jẹ 2:8, 9
Jẹ́n. 13:10Jẹ 19:20-22
Jẹ́n. 13:12Jẹ 19:28, 29
Jẹ́n. 13:13Jẹ 18:20; 19:5; 2Pe 2:6-8; Jud 7
Jẹ́n. 13:15Jẹ 12:7; 15:18; 24:7; Ẹk 33:1
Jẹ́n. 13:16Jẹ 12:2; 15:1, 5; Ẹk 1:7; Heb 11:12
Jẹ́n. 13:18Jẹ 18:1; 23:19; 25:9, 10; 35:27
Jẹ́n. 13:18Jẹ 23:2
Jẹ́n. 13:18Jẹ 12:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 13:1-18

Jẹ́nẹ́sísì

13 Ábúrámù kúrò ní Íjíbítì lọ sí Négébù,+ òun àti ìyàwó rẹ̀ àti gbogbo ohun tó ní, pẹ̀lú Lọ́ọ̀tì. 2 Ábúrámù ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran ọ̀sìn, fàdákà àti wúrà.+ 3 Ó ń pàgọ́ láti ibì kan dé ibòmíì lẹ́nu ìrìn àjò rẹ̀ láti Négébù lọ dé Bẹ́tẹ́lì, títí ó fi dé ibi tó pàgọ́ sí tẹ́lẹ̀ láàárín Bẹ́tẹ́lì àti Áì,+ 4 níbi tó mọ pẹpẹ sí tẹ́lẹ̀. Ibẹ̀ ni Ábúrámù ti ké pe orúkọ Jèhófà.

5 Lọ́ọ̀tì, tó ń bá Ábúrámù rìnrìn àjò, pẹ̀lú ní àwọn àgùntàn, màlúù àti àwọn àgọ́. 6 Wọn ò sì lè jọ wà níbì kan náà torí ilẹ̀ náà ò gba gbogbo wọn; ohun ìní wọn ti pọ̀ gan-an débi pé wọn ò lè jọ máa gbé pọ̀ mọ́. 7 Torí náà, ìjà ṣẹlẹ̀ láàárín àwọn tó ń da ẹran ọ̀sìn Ábúrámù àti àwọn tó ń da ẹran ọ̀sìn Lọ́ọ̀tì. (Nígbà yẹn, àwọn ọmọ Kénáánì àti àwọn Pérísì ń gbé ní ilẹ̀ náà.)+ 8 Ábúrámù wá sọ fún Lọ́ọ̀tì+ pé: “Jọ̀ọ́, kò yẹ kí ìjà wáyé láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn tó ń da ẹran mi àti àwọn tó ń da ẹran rẹ, torí arákùnrin ni wá. 9 Ṣebí gbogbo ilẹ̀ ló wà níwájú rẹ yìí? Jọ̀ọ́, jẹ́ ká lọ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Tí o bá lọ sí apá òsì, èmi á lọ sí apá ọ̀tún; àmọ́ tí o bá lọ sí apá ọ̀tún, èmi á lọ sí apá òsì.” 10 Lọ́ọ̀tì wá gbójú sókè, ó sì rí i pé gbogbo agbègbè Jọ́dánì+ lómi dáadáa, (kí Jèhófà tó pa Sódómù àti Gòmórà run), bí ọgbà Jèhófà,+ bí ilẹ̀ Íjíbítì, títí lọ dé Sóárì.+ 11 Lọ́ọ̀tì wá yan gbogbo agbègbè Jọ́dánì fún ara rẹ̀, ó sì ṣí ibùdó rẹ̀ lọ sí ìlà oòrùn. Bí wọ́n ṣe lọ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ nìyẹn. 12 Ábúrámù ń gbé ilẹ̀ Kénáánì, àmọ́ Lọ́ọ̀tì ń gbé láàárín àwọn ìlú tó wà ní agbègbè náà.+ Nígbà tó yá, ó pàgọ́ rẹ̀ sí tòsí Sódómù. 13 Èèyàn burúkú ni àwọn ará Sódómù, ẹlẹ́ṣẹ̀ paraku ni wọ́n jẹ́ lójú Jèhófà.+

14 Jèhófà sọ fún Ábúrámù lẹ́yìn tí Lọ́ọ̀tì kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ pé: “Jọ̀ọ́ gbójú sókè níbi tí o wà, kí o sì wo àríwá àti gúúsù, ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn, 15 torí gbogbo ilẹ̀ tí o rí yìí ni màá fún ìwọ àti ọmọ* rẹ, yóò sì di ohun ìní yín títí láé.+ 16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ. 17 Dìde, kí o sì rin ilẹ̀ náà já, kí o rin gígùn àti fífẹ̀ rẹ̀, torí ìwọ ni màá fún.” 18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́