ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hábákúkù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hábákúkù

      • “Èmi yóò máa ṣọ́nà kí n lè mọ ohun tí yóò sọ” (1)

      • Èsì tí Jèhófà fún wòlíì náà (2-​20)

        • ‘Ṣáà máa retí ìran náà’ (3)

        • Ìṣòtítọ́ yóò mú kí olódodo máa wà láàyè (4)

        • Nǹkan márùn-ún tó mú kí àwọn ará Kálídíà gbé (6-20)

          • Gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa Jèhófà (14)

Hábákúkù 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 21:8; Mik 7:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 15-16

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 10

    2/1/2000, ojú ìwé 12-14

Hábákúkù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lọ́nà tó já geere.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 17:14
  • +Di 31:9, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 13-14

Hábákúkù 2:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ti fẹ́rẹ̀ẹ́ ṣẹ.”

  • *

    Tàbí “dà bíi pé ó falẹ̀.”

  • *

    Tàbí “máa fojú sọ́nà fún un.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 7:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2015, ojú ìwé 16-17

    12/15/2006, ojú ìwé 17

    2/1/2000, ojú ìwé 14-15

    1/15/2000, ojú ìwé 10

    11/15/1998, ojú ìwé 16-17

    1/1/1997, ojú ìwé 12-13

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 152-154, 164

Hábákúkù 2:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Wò ó! Ọkàn rẹ̀ ń wú fùkẹ̀.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ìgbàgbọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:36; Ro 1:17; Ga 3:11; Heb 10:38

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 16-17

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 25, 187-188

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 15

    12/15/1999, ojú ìwé 20-21

    Ayọ, ojú ìwé 138-139

Hábákúkù 2:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn rẹ̀ kì í.”

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 14:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 10

    2/1/2000, ojú ìwé 15-16

Hábákúkù 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 14:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 16

Hábákúkù 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:11

Hábákúkù 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:19; Jer 27:6, 7; Sek 2:7-9
  • +2Kr 36:17; Sm 137:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 16

Hábákúkù 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 16

Hábákúkù 2:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 14:20

Hábákúkù 2:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 10

    2/1/2000, ojú ìwé 16

Hábákúkù 2:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 17

Hábákúkù 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:58

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 17

Hábákúkù 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 72:19; Ais 11:9; Sek 14:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 17-18

Hábákúkù 2:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 18

Hábákúkù 2:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “kí o sì máa ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 75:8; Ais 51:22, 23; Jer 25:28; 51:57

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 18

Hábákúkù 2:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 137:8; Jer 50:28; 51:24

Hábákúkù 2:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ère dídà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:17; 44:19, 20; 45:20

Hábákúkù 2:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:19; 46:6
  • +Jer 51:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 18-19

Hábákúkù 2:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:1
  • +Sm 76:8; 115:3; Sek 2:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 19

Àwọn míì

Háb. 2:1Ais 21:8; Mik 7:7
Háb. 2:2Ẹk 17:14
Háb. 2:2Di 31:9, 11
Háb. 2:3Mik 7:7
Háb. 2:4Jo 3:36; Ro 1:17; Ga 3:11; Heb 10:38
Háb. 2:5Ais 14:16, 17
Háb. 2:6Ais 14:4
Háb. 2:7Jer 51:11
Háb. 2:8Ais 13:19; Jer 27:6, 7; Sek 2:7-9
Háb. 2:82Kr 36:17; Sm 137:8
Háb. 2:10Ais 14:20
Háb. 2:13Jer 51:58
Háb. 2:14Sm 72:19; Ais 11:9; Sek 14:9
Háb. 2:16Sm 75:8; Ais 51:22, 23; Jer 25:28; 51:57
Háb. 2:17Sm 137:8; Jer 50:28; 51:24
Háb. 2:18Ais 42:17; 44:19, 20; 45:20
Háb. 2:19Ais 40:19; 46:6
Háb. 2:19Jer 51:17
Háb. 2:20Ais 6:1
Háb. 2:20Sm 76:8; 115:3; Sek 2:13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Hábákúkù 2:1-20

Hábákúkù

2 Ibi tí mo ti ń ṣe olùṣọ́ ni èmi yóò dúró sí,+

Èmi yóò sì dúró lórí odi ààbò.

Èmi yóò máa ṣọ́nà kí n lè mọ ohun tí yóò sọ nípasẹ̀ mi

Àti ohun tí èmi yóò sọ nígbà tó bá bá mi wí.

 2 Jèhófà wá dá mi lóhùn pé:

“Kọ ìran náà sílẹ̀, kí o sì kọ ọ́ sára wàláà,+ kó hàn kedere,

Kí ẹni tó ń kà á sókè lè rí i kà dáadáa.*+

 3 Àkókò tí ìran náà máa ṣẹ kò tíì tó,

Ó ń yára sún mọ́lé,* kò sì ní lọ láìṣẹ.

Tó bá tiẹ̀ falẹ̀,* ṣáà máa retí rẹ̀!*+

Torí yóò ṣẹ láìkùnà.

Kò ní pẹ́ rárá!

 4 Wo ẹni tó ń gbéra ga;*

Kì í ṣe olóòótọ́ nínú ọkàn rẹ̀.

Àmọ́ ìṣòtítọ́* yóò mú kí olódodo wà láàyè.+

 5 Torí pé wáìnì ń tanni jẹ lóòótọ́,

Ọwọ́ ẹni tó jọ ara rẹ̀ lójú kò ní tẹ àfojúsùn rẹ̀.

Kì í* ní ìtẹ́lọ́rùn bí Isà Òkú;*

Ó dà bí ikú, kò lè ní ìtẹ́lọ́rùn.

Ó ń kó gbogbo orílẹ̀-èdè jọ,

Ó sì ń kó gbogbo èèyàn sọ́dọ̀ ara rẹ̀.+

 6 Ṣé kì í ṣe gbogbo wọn ló máa pa òwe, àṣamọ̀ àti àlọ́ láti bá a jà?+

Wọ́n á sọ pé:

‘Ẹni tó ń kó ohun tí kì í ṣe tirẹ̀ jọ gbé!

Tó sì ń mú kí gbèsè ọrùn rẹ̀ pọ̀ sí i.

Ìgbà wo ló máa ṣe èyí dà?

 7 Ǹjẹ́ àwọn tó yá ọ lówó kò ní dìde sí ọ lójijì?

Wọ́n á ta jí, wọ́n á sì fipá mì ọ́ jìgìjìgì,

Wọ́n á sì kó ọ bí ẹrù tí wọ́n kó dé látojú ogun.+

 8 Torí ìwọ náà ti kó ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè lẹ́rù,

Gbogbo èèyàn yóò kó ọ lẹ́rù,+

Nítorí ẹ̀jẹ̀ àwọn èèyàn tí o ta sílẹ̀

Àti ìwà ipá tí o hù sí ayé,

Sí àwọn ìlú àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+

 9 Ẹni tó ń kó èrè tí kò tọ́ jọ fún ilé rẹ̀ gbé!

Kó lè kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí ibi gíga,

Kó má bàa kó sínú àjálù.

10 O ti gbèrò ohun tó kó ìtìjú bá ilé rẹ.

O ṣẹ̀ sí ara* rẹ bí o ṣe pa ọ̀pọ̀ èèyàn run.+

11 Òkúta yóò ké jáde láti inú ògiri,

Igi ìrólé yóò sì dá a lóhùn látorí àjà.

12 Ẹni tó ń fi ìtàjẹ̀sílẹ̀ kọ́ ìlú gbé,

Àti ẹni tó ń fi àìṣòdodo tẹ ìlú dó!

13 Wò ó! Ṣé kì í ṣe Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló ń mú kí àwọn èèyàn ṣiṣẹ́ kára fún ohun tó ṣì máa jóná,

Tó sì ń mú kí àwọn orílẹ̀-èdè ṣe wàhálà lásán?+

14 Torí gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa ògo Jèhófà

Bí ìgbà tí omi bo òkun.+

15 Ẹni tó ń fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní nǹkan mu gbé!

Tó ń fi ìbínú àti ìkanra ṣe é, kó lè mú kí wọ́n yó,

Kó lè wo ìhòòhò wọn!

16 Àbùkù ni wọn yóò fi kàn ọ́ dípò ògo.

Ìwọ náà mu ún, kí o sì ṣí adọ̀dọ́ rẹ tí wọn ò dá sí gbangba.*

Ife ọwọ́ ọ̀tún Jèhófà yóò dé ọ̀dọ̀ rẹ,+

Ìtìjú yóò sì bo ògo rẹ mọ́lẹ̀;

17 Torí ìwà ipá tí o hù sí Lẹ́bánónì yóò bò ọ́ mọ́lẹ̀,

Ìparun tó dẹ́rù ba àwọn ẹranko yóò dé bá ọ,

Nítorí ẹ̀jẹ̀ àwọn èèyàn tí o ta sílẹ̀

Àti ìwà ipá tí o hù sí ayé,

Sí àwọn ìlú àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+

18 Kí ni àǹfààní ère,

Nígbà tó jẹ́ pé èèyàn ló gbẹ́ ẹ?

Kí ni àǹfààní ère onírin* àti olùkọ́ èké,

Tí ẹni tó ṣe é bá tiẹ̀ gbẹ́kẹ̀ lé e,

Tó ṣe àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí, tí kò lè sọ̀rọ̀?+

19 O gbé, ìwọ tí ò ń sọ fún igi pé: “Dìde!”

Tàbí fún òkúta tí kò lè sọ̀rọ̀ pé: “Gbéra nílẹ̀! Máa kọ́ wa!”

Wò ó! Wúrà àti fàdákà ni wọ́n fi bò ó,+

Kò sì sí èémí kankan nínú rẹ̀.+

20 Àmọ́ Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+

Gbogbo ayé, ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú rẹ̀!’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́