ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Émọ́sì

      • Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn abo màlúù Báṣánì (1-3)

      • Jèhófà kórìíra ìjọsìn èké Ísírẹ́lì (4, 5)

      • Ísírẹ́lì kò gba ìbáwí (6-13)

        • “Múra sílẹ̀ láti pàdé Ọlọ́run rẹ” (12)

        • ‘Ọlọ́run ń sọ èrò rẹ̀ fún àwọn èèyàn’ (13)

Émọ́sì 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn ọ̀gá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 6:1
  • +Ho 4:1, 2; Mik 2:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2007, ojú ìwé 14

Émọ́sì 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣọ̀tẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:28, 29; Ho 4:13; Emọ 3:14
  • +Ho 4:15; 9:15; Emọ 5:5
  • +Ho 8:11, 13
  • +Di 14:28

Émọ́sì 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:12

Émọ́sì 4:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mi ò fún yín lóúnjẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:26; Di 28:38; 32:24; 1Ọb 18:2; 2Ọb 4:38
  • +Jer 3:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2007, ojú ìwé 14

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 60

Émọ́sì 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:23, 24

Émọ́sì 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 18:5
  • +Ho 7:10

Émọ́sì 4:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, kí nǹkan bu.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:22
  • +Di 28:40, 42
  • +Ais 42:24

Émọ́sì 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 9:3; Di 28:27, 60
  • +Le 26:23, 25; 2Ọb 8:12
  • +2Ọb 13:7
  • +Di 28:26

Émọ́sì 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:24, 25
  • +Ho 7:10

Émọ́sì 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 12

Émọ́sì 4:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:12
  • +Jer 10:13
  • +Ẹk 10:22; Ais 5:30; Emọ 8:9
  • +Mik 1:3

Àwọn míì

Émọ́sì 4:1Emọ 6:1
Émọ́sì 4:1Ho 4:1, 2; Mik 2:2
Émọ́sì 4:41Ọb 12:28, 29; Ho 4:13; Emọ 3:14
Émọ́sì 4:4Ho 4:15; 9:15; Emọ 5:5
Émọ́sì 4:4Ho 8:11, 13
Émọ́sì 4:4Di 14:28
Émọ́sì 4:5Le 7:12
Émọ́sì 4:6Le 26:26; Di 28:38; 32:24; 1Ọb 18:2; 2Ọb 4:38
Émọ́sì 4:6Jer 3:6, 7
Émọ́sì 4:7Di 28:23, 24
Émọ́sì 4:81Ọb 18:5
Émọ́sì 4:8Ho 7:10
Émọ́sì 4:9Di 28:22
Émọ́sì 4:9Di 28:40, 42
Émọ́sì 4:9Ais 42:24
Émọ́sì 4:10Ẹk 9:3; Di 28:27, 60
Émọ́sì 4:10Le 26:23, 25; 2Ọb 8:12
Émọ́sì 4:102Ọb 13:7
Émọ́sì 4:10Di 28:26
Émọ́sì 4:11Jẹ 19:24, 25
Émọ́sì 4:11Ho 7:10
Émọ́sì 4:13Ais 40:12
Émọ́sì 4:13Jer 10:13
Émọ́sì 4:13Ẹk 10:22; Ais 5:30; Emọ 8:9
Émọ́sì 4:13Mik 1:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Émọ́sì 4:1-13

Émọ́sì

4 “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin abo màlúù Báṣánì,

Tó wà lórí òkè Samáríà,+

Ẹ̀yin obìnrin tó ń lu àwọn aláìní ní jìbìtì,+ tó sì ń ni àwọn tálákà lára,

Tó ń sọ fún àwọn ọkọ* wọn pé, ‘Ẹ gbé ọtí wá ká mu!’

 2 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fi ìjẹ́mímọ́ rẹ̀ búra pé,

‘“Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ nígbà tó máa fi ìkọ́ alápatà gbé yín sókè

Tí á sì fi ìwọ̀ ẹja gbé àwọn tó ṣẹ́ kù lára yín.

 3 Kálukú yín máa gba àlàfo ara ògiri tó wà níwájú rẹ̀ jáde lọ;

A ó sì lé yín sí Hámọ́nì,” ni Jèhófà wí.’

 4 ‘Ẹ wá sí Bẹ́tẹ́lì, kí ẹ sì dẹ́ṣẹ̀,*+

Àti sí Gílígálì kí ẹ dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀!+

Ẹ mú àwọn ẹbọ yín wá+ ní òwúrọ̀,

Ẹ sì mú ìdá mẹ́wàá+ yín wá ní ọjọ́ kẹta.

 5 Ẹ fi búrẹ́dì tó ní ìwúkàrà rú ẹbọ ìdúpẹ́;+

Ẹ sì kéde àwọn ọrẹ àtinúwá yín!

Nítorí ohun tí ẹ fẹ́ nìyẹn, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.

 6 ‘Ní tèmi, mo mú kí eyín yín mọ́ nítorí àìsí oúnjẹ* ní gbogbo àwọn ìlú yín

Mi ò sì jẹ́ kí oúnjẹ wà ní gbogbo ilé yín;+

Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.

 7 ‘Mo tún fawọ́ òjò sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ yín nígbà tí ìkórè ṣì ku oṣù mẹ́ta;+

Mo mú kí òjò rọ̀ sí ìlú kan àmọ́ mi ò jẹ́ kó rọ̀ sí ìlú míì.

Òjò máa rọ̀ sí ilẹ̀ kan,

Àmọ́ ilẹ̀ tí òjò kò rọ̀ sí máa gbẹ.

 8 Àwọn èèyàn ìlú méjì tàbí mẹ́ta ń rọ́ lọ sí ìlú kan ṣoṣo kí wọ́n lè mu omi,+

Àmọ́ kò tẹ́ wọn lọ́rùn;

Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.

 9 ‘Mo fi ooru tó ń jóni àti èbíbu* kọ lù yín.+

Ẹ̀ ń mú kí àwọn ọgbà yín àti oko àjàrà yín di púpọ̀,+

Ṣùgbọ́n eéṣú ló jẹ igi ọ̀pọ̀tọ́ yín àti igi ólífì yín run;

Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.

10 ‘Mo rán àjàkálẹ̀ àrùn sáàárín yín bíi ti Íjíbítì.+

Mo fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín,+ mo sì gba àwọn ẹṣin yín.+

Mo mú kí òórùn àwọn tó kú ní ibùdó yín gba afẹ́fẹ́ kan;+

Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’ ni Jèhófà wí.

11 ‘Mo pa ilẹ̀ yín run

Bí Ọlọ́run ṣe pa Sódómù àti Gòmórà run.+

Ẹ sì dà bí igi tí a fà yọ kúrò nínú iná;

Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.

12 Torí náà, màá tún fìyà jẹ ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì.

Nítorí ohun tí màá ṣe sí ọ yìí,

Múra sílẹ̀ láti pàdé Ọlọ́run rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì.

13 Nítorí, wò ó! Òun ló dá àwọn òkè+ àti afẹ́fẹ́;+

Ó ń sọ èrò Rẹ̀ fún àwọn èèyàn,

Ó ń sọ ìmọ́lẹ̀ di òkùnkùn,+

Ó ń rìn lórí àwọn ibi gíga ayé;+

Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́