ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 55
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ìkésíni láti jẹ, kí wọ́n sì mu lọ́fẹ̀ẹ́ (1-5)

      • Ẹ wá Jèhófà àti ọ̀rọ̀ rẹ̀ tó ṣeé gbára lé (6-13)

        • Ọ̀nà Ọlọ́run ga ju ti èèyàn lọ (8, 9)

        • Ó dájú pé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa yọrí sí rere (10, 11)

Àìsáyà 55:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 42:2; 63:1; Emọ 8:11; Mt 5:6
  • +Ais 41:17
  • +Joẹ 3:18
  • +Ifi 21:6; 22:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2002, ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 233-235, 241

Àìsáyà 55:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “owó tí ẹ ṣiṣẹ́ kára fún.”

  • *

    Ní Héb., “Ọ̀rá.”

  • *

    Tàbí “ọkàn yín yọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 25:6
  • +Sm 36:7, 8; 63:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 235-237

Àìsáyà 55:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.”

  • *

    Tàbí “tó ṣeé gbọ́kàn lé; tó ṣeé gbára lé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 4:8
  • +Ais 61:8
  • +2Sa 7:8, 16; 23:5; Sm 89:28, 29; Jer 33:25, 26; Iṣe 13:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 236-238

Àìsáyà 55:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 1:5; 3:14
  • +Da 9:25; Mt 23:10
  • +Jẹ 49:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 13-14

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2007, ojú ìwé 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 238-242

Àìsáyà 55:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 8:23
  • +Ais 49:3; 60:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 241-242

Àìsáyà 55:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 28:9
  • +Sm 145:18; Jem 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 243

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1992, ojú ìwé 8

Àìsáyà 55:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lọ́nà títóbi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 18:21; Iṣe 3:19
  • +Ẹk 34:6; 2Kr 33:12, 13
  • +Nọ 14:18; Sm 103:12, 13; Ais 43:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 243

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1992, ojú ìwé 8

Àìsáyà 55:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 243-244

Àìsáyà 55:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 103:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 243-244

Àìsáyà 55:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2008, ojú ìwé 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 244-246

Àìsáyà 55:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa já sí.”

  • *

    Tàbí “tó bá jẹ́ ìfẹ́ mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 23:19; Ais 46:11
  • +Joṣ 23:14; Ais 45:23
  • +Sm 135:6; Ais 46:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 283-284

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2006, ojú ìwé 6

    6/1/2006, ojú ìwé 22-23

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 244-246

Àìsáyà 55:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:10
  • +Ais 54:13; 66:12
  • +Ais 42:11
  • +Ais 44:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 245-246

Àìsáyà 55:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe orúkọ fún Jèhófà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:19; 60:13
  • +Jer 33:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 245-246

Àwọn míì

Àìsá. 55:1Sm 42:2; 63:1; Emọ 8:11; Mt 5:6
Àìsá. 55:1Ais 41:17
Àìsá. 55:1Joẹ 3:18
Àìsá. 55:1Ifi 21:6; 22:17
Àìsá. 55:2Ais 25:6
Àìsá. 55:2Sm 36:7, 8; 63:5
Àìsá. 55:3Jem 4:8
Àìsá. 55:3Ais 61:8
Àìsá. 55:32Sa 7:8, 16; 23:5; Sm 89:28, 29; Jer 33:25, 26; Iṣe 13:34
Àìsá. 55:4Ifi 1:5; 3:14
Àìsá. 55:4Da 9:25; Mt 23:10
Àìsá. 55:4Jẹ 49:10
Àìsá. 55:5Sek 8:23
Àìsá. 55:5Ais 49:3; 60:9
Àìsá. 55:61Kr 28:9
Àìsá. 55:6Sm 145:18; Jem 4:8
Àìsá. 55:7Isk 18:21; Iṣe 3:19
Àìsá. 55:7Ẹk 34:6; 2Kr 33:12, 13
Àìsá. 55:7Nọ 14:18; Sm 103:12, 13; Ais 43:25
Àìsá. 55:8Sm 40:5
Àìsá. 55:9Sm 103:11
Àìsá. 55:11Nọ 23:19; Ais 46:11
Àìsá. 55:11Joṣ 23:14; Ais 45:23
Àìsá. 55:11Sm 135:6; Ais 46:10
Àìsá. 55:12Ais 35:10
Àìsá. 55:12Ais 54:13; 66:12
Àìsá. 55:12Ais 42:11
Àìsá. 55:12Ais 44:23
Àìsá. 55:13Ais 41:19; 60:13
Àìsá. 55:13Jer 33:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 55:1-13

Àìsáyà

55 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òùngbẹ ń gbẹ,+ ẹ wá síbi omi!+

Ẹ̀yin tẹ́ ò ní owó, ẹ wá, ẹ rà, kí ẹ sì jẹ!

Àní, ẹ wá, ẹ ra wáìnì àti wàrà+ lọ́fẹ̀ẹ́, láìsan owó.+

 2 Kí ló dé tí ẹ fi ń sanwó fún ohun tí kì í ṣe oúnjẹ,

Kí ló sì dé tí ẹ fi ń lo ohun tí ẹ ṣiṣẹ́ fún* sórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn?

Ẹ tẹ́tí sí mi dáadáa, kí ẹ sì jẹ ohun tó dáa,+

Ohun tó dọ́ṣọ̀* sì máa mú inú yín dùn* gidigidi.+

 3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+

Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,

Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+

Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+

 4 Wò ó! Mo fi ṣe ẹlẹ́rìí+ fún àwọn orílẹ̀-èdè,

Aṣáájú+ àti aláṣẹ+ àwọn orílẹ̀-èdè.

 5 Wò ó! O máa pe orílẹ̀-èdè tí o kò mọ̀,

Àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́ sì máa sáré wá sọ́dọ̀ rẹ,

Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,

Torí pé ó máa ṣe ọ́ lógo.+

 6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+

Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+

 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+

Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;

Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+

Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+

 8 “Torí èrò mi yàtọ̀ sí èrò yín,+

Ọ̀nà yín sì yàtọ̀ sí ọ̀nà mi,” ni Jèhófà wí.

 9 “Torí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé lọ,

Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín,

Èrò mi sì ga ju èrò yín.+

10 Torí bí òjò àti yìnyín ṣe ń rọ̀ láti ọ̀run gẹ́lẹ́,

Tí kì í sì í pa dà síbẹ̀, àfi tó bá mú kí ilẹ̀ rin, tó jẹ́ kó méso jáde, kí nǹkan sì hù,

Tó jẹ́ kí ẹni tó fúnrúgbìn ká irúgbìn, tí ẹni tó ń jẹun sì rí oúnjẹ,

11 Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tó ti ẹnu mi jáde máa rí.*+

Kò ní pa dà sọ́dọ̀ mi láìṣẹ,+

Àmọ́ ó dájú pé ó máa ṣe ohunkóhun tí inú mi bá dùn sí,*+

Ó sì dájú pé ohun tí mo rán an pé kó ṣe máa yọrí sí rere.

12 Ẹ máa fi ayọ̀ jáde lọ,+

A sì máa mú yín pa dà ní àlàáfíà.+

Àwọn òkè ńlá àtàwọn òkè kéékèèké máa fi igbe ayọ̀ túra ká níwájú yín,+

Gbogbo àwọn igi inú igbó sì máa pàtẹ́wọ́.+

13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+

Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù.

Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+

Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́