ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 136
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ wà títí láé

        • Ó fi ọgbọ́n dá ọ̀run àti ayé (5, 6)

        • Fáráò kú sínú Òkun Pupa (15)

        • Ọlọ́run ń rántí àwọn tí ìdààmú bá (23)

        • Ó ń fún gbogbo ohun alààyè ní oúnjẹ (25)

Sáàmù 136:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 18:19
  • +2Kr 7:3; 20:21; Sm 106:1; 107:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 284-285

Sáàmù 136:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 97:9; Da 2:47

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

Sáàmù 136:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

Sáàmù 136:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:11; Ifi 15:3
  • +Sm 103:17

Sáàmù 136:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òye.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 38:36; Owe 3:19, 20

Sáàmù 136:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:9; Sm 24:1, 2

Sáàmù 136:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:14

Sáàmù 136:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:16; Jer 31:35

Sáàmù 136:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 8:3

Sáàmù 136:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 12:29

Sáàmù 136:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 12:51

Sáàmù 136:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:14

Sáàmù 136:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:21

Sáàmù 136:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:29

Sáàmù 136:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:27, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2020, ojú ìwé 4

Sáàmù 136:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:18; 15:22

Sáàmù 136:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 12:7, 8

Sáàmù 136:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:21-24

Sáàmù 136:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:33-35

Sáàmù 136:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:33

Sáàmù 136:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:36
  • +Ne 9:32

Sáàmù 136:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 3:9; 6:9

Sáàmù 136:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “gbogbo ẹlẹ́ran ara.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 145:15; 147:9

Àwọn míì

Sm 136:1Lk 18:19
Sm 136:12Kr 7:3; 20:21; Sm 106:1; 107:1
Sm 136:2Sm 97:9; Da 2:47
Sm 136:4Ẹk 15:11; Ifi 15:3
Sm 136:4Sm 103:17
Sm 136:5Job 38:36; Owe 3:19, 20
Sm 136:6Jẹ 1:9; Sm 24:1, 2
Sm 136:7Jẹ 1:14
Sm 136:8Jẹ 1:16; Jer 31:35
Sm 136:9Sm 8:3
Sm 136:10Ẹk 12:29
Sm 136:11Ẹk 12:51
Sm 136:12Ẹk 13:14
Sm 136:13Ẹk 14:21
Sm 136:14Ẹk 14:29
Sm 136:15Ẹk 14:27, 28
Sm 136:16Ẹk 13:18; 15:22
Sm 136:17Joṣ 12:7, 8
Sm 136:19Nọ 21:21-24
Sm 136:20Nọ 21:33-35
Sm 136:21Nọ 32:33
Sm 136:23Di 32:36
Sm 136:23Ne 9:32
Sm 136:24Ond 3:9; 6:9
Sm 136:25Sm 145:15; 147:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 136:1-26

Sáàmù

136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+

Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

2 Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

3 Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa àwọn olúwa,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

4 Òun nìkan ló ń ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

5 Ó fi ọgbọ́n* dá àwọn ọ̀run,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

6 Ó tẹ́ ayé sórí omi,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

7 Ó dá àwọn ìmọ́lẹ̀ ńlá,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

8 Oòrùn láti máa jọba lórí ọ̀sán,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

9 Òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ láti máa jọba lórí òru,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

10 Ó pa àwọn àkọ́bí Íjíbítì,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

11 Ó mú Ísírẹ́lì jáde kúrò láàárín wọn,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

12 Pẹ̀lú ọwọ́ agbára+ àti apá tó nà jáde,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

13 Ó pín Òkun Pupa sí méjì,*+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

14 Ó mú kí Ísírẹ́lì gba àárín rẹ̀ kọjá,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

15 Ó gbọn Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú Òkun Pupa,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

16 Ó mú àwọn èèyàn rẹ̀ gba inú aginjù kọjá,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

17 Ó pa àwọn ọba ńlá,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

18 Ó pa àwọn ọba alágbára,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

19 Síhónì+ ọba àwọn Ámórì,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé

20 Àti Ógù+ ọba Báṣánì,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

21 Ó fi ilẹ̀ wọn ṣe ogún,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

22 Ó fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì ìránṣẹ́ rẹ̀,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

23 Ó rántí wa nígbà tí wọ́n rẹ̀ wá sílẹ̀,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

24 Ó ń gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

25 Ó ń fún gbogbo ohun alààyè* ní oúnjẹ,+

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

26 Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run ọ̀run,

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́