ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Gálátíà 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Gálátíà

      • Ẹ máa bá ara yín gbé ẹrù (1-10)

        • Ohun tí èèyàn bá gbìn ló máa ká (7, 8)

      • Ìdádọ̀dọ́ kò ṣàǹfààní (11-16)

        • Ẹ̀dá tuntun (15)

      • Ìparí (17, 18)

Gálátíà 6:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ẹ̀mí ìwà tútù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 15:1; Kol 3:12; 1Ti 6:11; Tit 3:2
  • +1Kọ 10:12
  • +Jem 3:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2012, ojú ìwé 29

    8/15/2008, ojú ìwé 26

    11/15/2006, ojú ìwé 29-30

    4/1/2003, ojú ìwé 24-25

    1/15/1999, ojú ìwé 21-22

    5/15/1993, ojú ìwé 21-22

    11/15/1992, ojú ìwé 26-29

    11/15/1991, ojú ìwé 20

Gálátíà 6:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 5:14
  • +Jo 13:34; 15:12; 1Jo 4:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2019, ojú ìwé 3-4

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2015, ojú ìwé 29

    8/15/2008, ojú ìwé 26

    5/1/2006, ojú ìwé 29-30

    8/15/2005, ojú ìwé 25-29

    3/15/2002, ojú ìwé 27-28

    9/1/1996, ojú ìwé 19-24

    5/15/1993, ojú ìwé 16

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 153-156

Gálátíà 6:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:3

Gálátíà 6:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 13:5
  • +Ga 5:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2021, ojú ìwé 20-25

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2020, ojú ìwé 24

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 13

    11/1/2010, ojú ìwé 5

    6/1/2006, ojú ìwé 15

    6/1/2005, ojú ìwé 16-17

    11/15/1995, ojú ìwé 22-23

    9/1/1994, ojú ìwé 12

    10/15/1991, ojú ìwé 22

    5/15/1991, ojú ìwé 30

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    7/2012, ojú ìwé 1

Gálátíà 6:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe ojúṣe tirẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:4; 2Kọ 5:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 13

    8/15/2008, ojú ìwé 26

    3/15/2002, ojú ìwé 28

    5/15/1993, ojú ìwé 16

Gálátíà 6:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fi ọ̀rọ̀ ẹnu kọ́.”

  • *

    Tàbí “fi ọ̀rọ̀ ẹnu kọ́ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:9, 10; Lk 10:7; Ro 15:27; 1Kọ 9:11, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2002, ojú ìwé 16-17

Gálátíà 6:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “fi ṣe ẹlẹ́yà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 2:6-8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 11

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 267-268

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/1998, ojú ìwé 7

    12/1/1997, ojú ìwé 13

Gálátíà 6:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:6, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2008, ojú ìwé 26

    6/15/1995, ojú ìwé 31

Gálátíà 6:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “juwọ́ sílẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:14; 12:3; Ifi 2:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2021, ojú ìwé 24-28

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2013, ojú ìwé 27-28

    6/1/2005, ojú ìwé 29-30

    12/1/1995, ojú ìwé 9-14

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    6/2001, ojú ìwé 1

Gálátíà 6:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ní àkókò tí a yàn kalẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 44

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 226

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2006, ojú ìwé 23

    6/1/2004, ojú ìwé 30-31

    6/1/2001, ojú ìwé 15

    8/1/1999, ojú ìwé 20-21

    12/1/1998, ojú ìwé 11

    10/1/1997, ojú ìwé 32

    7/1/1993, ojú ìwé 22

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    6/2002, ojú ìwé 1

    Jí!,

    9/8/1997, ojú ìwé 13

Gálátíà 6:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí wọ́n fẹ́ lẹ́wà lóde ara.”

  • *

    Tàbí “kọlà.”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Gálátíà 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 2:10

Gálátíà 6:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “kan ayé mọ́gi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 2:2

Gálátíà 6:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkọlà.”

  • *

    Tàbí “àìkọlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:19; Ga 5:6; Kol 3:10, 11
  • +2Kọ 5:17; Ef 2:10

Gálátíà 6:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 9:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1995, ojú ìwé 11-12

Gálátíà 6:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:10; Flp 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2010, ojú ìwé 15

Gálátíà 6:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 12-13

Àwọn míì

Gál. 6:1Owe 15:1; Kol 3:12; 1Ti 6:11; Tit 3:2
Gál. 6:11Kọ 10:12
Gál. 6:1Jem 3:2
Gál. 6:21Tẹ 5:14
Gál. 6:2Jo 13:34; 15:12; 1Jo 4:21
Gál. 6:3Ro 12:3
Gál. 6:42Kọ 13:5
Gál. 6:4Ga 5:26
Gál. 6:5Ro 14:4; 2Kọ 5:10
Gál. 6:6Mt 10:9, 10; Lk 10:7; Ro 15:27; 1Kọ 9:11, 14
Gál. 6:7Ro 2:6-8
Gál. 6:8Ro 8:6, 13
Gál. 6:9Heb 3:14; 12:3; Ifi 2:10
Gál. 6:13Jem 2:10
Gál. 6:141Kọ 2:2
Gál. 6:151Kọ 7:19; Ga 5:6; Kol 3:10, 11
Gál. 6:152Kọ 5:17; Ef 2:10
Gál. 6:16Ro 9:6
Gál. 6:172Kọ 4:10; Flp 3:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Gálátíà 6:1-18

Sí Àwọn Ará Gálátíà

6 Ẹ̀yin ará, tí ẹnì kan bá tiẹ̀ ṣi ẹsẹ̀ gbé kó tó mọ̀, kí ẹ̀yin tí ẹ kúnjú ìwọ̀n nípa tẹ̀mí sapá láti fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́* tọ́ ẹni náà sọ́nà.+ Àmọ́ kí ẹ máa kíyè sí ara yín lójú méjèèjì,+ kí a má bàa dẹ ẹ̀yin náà wò.+ 2 Ẹ máa bá ara yín gbé ẹrù tó wúwo,+ nípa bẹ́ẹ̀, ẹ ó mú òfin Kristi ṣẹ.+ 3 Tí ẹnì kan bá rò pé òun jẹ́ nǹkan kan nígbà tí kò jẹ́ nǹkan kan,+ ó ń tan ara rẹ̀ jẹ ni. 4 Àmọ́ kí kálukú máa yẹ ohun tó ń ṣe wò,+ nígbà náà, yóò láyọ̀ nítorí ohun tí òun fúnra rẹ̀ ṣe, kì í ṣe torí pé ó fi ara rẹ̀ wé ẹlòmíì.+ 5 Torí kálukú ló máa ru ẹrù ara rẹ̀.*+

6 Yàtọ̀ síyẹn, kí ẹni tí à ń kọ́* ní ọ̀rọ̀ náà máa ṣàjọpín ohun rere gbogbo pẹ̀lú ẹni tó ń kọ́ni* ní irú ẹ̀kọ́ bẹ́ẹ̀.+

7 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ: Ọlọ́run kò ṣeé tàn.* Nítorí ohun tí èèyàn bá gbìn, òun ló máa ká;+ 8 torí pé ẹni tó bá ń fúnrúgbìn nítorí ara rẹ̀ máa ká ìdíbàjẹ́ látinú ara rẹ̀, àmọ́ ẹni tó bá ń fúnrúgbìn nítorí ẹ̀mí máa ká ìyè àìnípẹ̀kun látinú ẹ̀mí.+ 9 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí a jáwọ́ nínú ṣíṣe rere, torí tí àkókò bá tó, a máa kórè rẹ̀ tí a ò bá jẹ́ kó rẹ̀ wá.*+ 10 Tóò, nígbà tí a bá ti láǹfààní rẹ̀,* ẹ jẹ́ ká máa ṣe rere fún gbogbo èèyàn, àmọ́ ní pàtàkì fún àwọn tó bá wa tan nínú ìgbàgbọ́.

11 Ẹ wo àwọn lẹ́tà gàdàgbà tí mo fi kọ̀wé sí yín ní ọwọ́ ara mi.

12 Gbogbo àwọn tí ó fẹ́ kí àwọn èèyàn ní èrò tó dáa nípa wọn nínú ara,* ni àwọn tó fẹ́ sọ ọ́ di dandan fún yín pé kí ẹ dádọ̀dọ́,* wọ́n sì ń ṣe bẹ́ẹ̀ kí a má bàa ṣe inúnibíni sí wọn nítorí òpó igi oró* Kristi. 13 Nítorí àwọn tó ń dádọ̀dọ́* pàápàá kì í pa Òfin mọ́,+ àmọ́ wọ́n fẹ́ kí ẹ dádọ̀dọ́ kí wọ́n lè máa ti ara yín yangàn. 14 Ní tèmi, mi ò ní yangàn láé, àfi nípa òpó igi oró* Olúwa wa Jésù Kristi,+ ẹni tí a tipasẹ̀ rẹ̀ sọ ayé di òkú* lójú tèmi àti èmi lójú ti ayé. 15 Nítorí ìdádọ̀dọ́* tàbí àìdádọ̀dọ́* kọ́ ló ṣe pàtàkì,+ ẹ̀dá tuntun ló ṣe pàtàkì.+ 16 Ní ti gbogbo àwọn tó ń rìn létòlétò nínú ìlànà ìwà rere yìí, kí àlàáfíà àti àánú wà lórí wọn, bẹ́ẹ̀ ni, lórí Ísírẹ́lì Ọlọ́run.+

17 Láti ìsinsìnyí lọ, kí ẹnikẹ́ni má dà mí láàmú mọ́, nítorí àpá ẹrú Jésù wà ní ara mi.+

18 Ẹ̀yin ará, kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Olúwa wa Jésù Kristi wà pẹ̀lú ẹ̀mí tí ẹ̀ ń fi hàn. Àmín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́