ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóṣúà

      • Jèhófà fún Jóṣúà níṣìírí (1-9)

        • Máa fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka Òfin (8)

      • Wọ́n ń múra láti sọdá Jọ́dánì (10-18)

Jóṣúà 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Jèhóṣúà,” ó túmọ̀ sí “Jèhófà Ni Ìgbàlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:14
  • +Ẹk 24:13; Nọ 11:28

Jóṣúà 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 34:5
  • +Di 3:28

Jóṣúà 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 11:24

Jóṣúà 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Mẹditaréníà.

  • *

    Tàbí “lápá ibi tí oòrùn ti ń wọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 13:29
  • +Jẹ 15:18; Ẹk 23:31; Nọ 34:2, 3; Di 1:7; Joṣ 15:1, 4

Jóṣúà 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:24; 11:25
  • +Ẹk 3:12; Joṣ 3:7
  • +Di 31:6

Jóṣúà 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:23
  • +Jẹ 12:7; 15:18; 26:3

Jóṣúà 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:32
  • +Di 29:9; 1Ọb 2:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1995, ojú ìwé 12

Jóṣúà 1:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣàṣàrò lórí rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:6; 30:14
  • +Di 17:18, 19; Sm 1:1, 2; 1Ti 4:15; Jem 1:25
  • +1Kr 22:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 11

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2015, ojú ìwé 27

    4/15/2013, ojú ìwé 7-8

    12/15/2012, ojú ìwé 4

    12/1/2009, ojú ìwé 17

    12/15/2004, ojú ìwé 15

    5/15/1996, ojú ìwé 11, 16

    5/1/1995, ojú ìwé 12

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    10/2015, ojú ìwé 3

Jóṣúà 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:27; Di 31:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 10

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2013, ojú ìwé 8

    Ìwé Ọdọọdún—2013, ojú ìwé 2

Jóṣúà 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:1; Joṣ 3:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2004, ojú ìwé 9

Jóṣúà 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:20-22; Joṣ 22:1-4

Jóṣúà 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ní apá ìlà oòrùn.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:19, 20; 29:8; Joṣ 13:8
  • +Nọ 1:3; 26:2
  • +Di 3:18

Jóṣúà 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:33; Joṣ 22:4, 9

Jóṣúà 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:17, 25

Jóṣúà 1:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 27:18, 20; Di 34:9

Jóṣúà 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 17:12
  • +Di 31:7; Joṣ 1:6, 9

Àwọn míì

Jóṣ. 1:1Di 31:14
Jóṣ. 1:1Ẹk 24:13; Nọ 11:28
Jóṣ. 1:2Di 34:5
Jóṣ. 1:2Di 3:28
Jóṣ. 1:3Di 11:24
Jóṣ. 1:4Nọ 13:29
Jóṣ. 1:4Jẹ 15:18; Ẹk 23:31; Nọ 34:2, 3; Di 1:7; Joṣ 15:1, 4
Jóṣ. 1:5Di 7:24; 11:25
Jóṣ. 1:5Ẹk 3:12; Joṣ 3:7
Jóṣ. 1:5Di 31:6
Jóṣ. 1:6Di 31:23
Jóṣ. 1:6Jẹ 12:7; 15:18; 26:3
Jóṣ. 1:7Di 5:32
Jóṣ. 1:7Di 29:9; 1Ọb 2:3
Jóṣ. 1:8Di 6:6; 30:14
Jóṣ. 1:8Di 17:18, 19; Sm 1:1, 2; 1Ti 4:15; Jem 1:25
Jóṣ. 1:81Kr 22:13
Jóṣ. 1:9Ẹk 23:27; Di 31:7, 8
Jóṣ. 1:11Di 9:1; Joṣ 3:2, 3
Jóṣ. 1:13Nọ 32:20-22; Joṣ 22:1-4
Jóṣ. 1:14Di 3:19, 20; 29:8; Joṣ 13:8
Jóṣ. 1:14Nọ 1:3; 26:2
Jóṣ. 1:14Di 3:18
Jóṣ. 1:15Nọ 32:33; Joṣ 22:4, 9
Jóṣ. 1:16Nọ 32:17, 25
Jóṣ. 1:17Nọ 27:18, 20; Di 34:9
Jóṣ. 1:18Di 17:12
Jóṣ. 1:18Di 31:7; Joṣ 1:6, 9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jóṣúà 1:1-18

Jóṣúà

1 Lẹ́yìn ikú Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà*+ ọmọ Núnì, ìránṣẹ́+ Mósè pé: 2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 3 Màá fún yín ní gbogbo ibi tí ẹ bá fi ẹsẹ̀ yín tẹ̀, bí mo ṣe ṣèlérí fún Mósè.+ 4 Ilẹ̀ yín máa jẹ́ láti aginjù títí dé Lẹ́bánónì àti odò ńlá, ìyẹn odò Yúfírétì, gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Hétì,+ títí lọ dé Òkun Ńlá* ní ìwọ̀ oòrùn.*+ 5 Kò sẹ́ni tó máa lè dìde sí ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá fi wà láàyè.+ Bí mo ṣe wà pẹ̀lú Mósè ni màá ṣe wà pẹ̀lú rẹ.+ Mi ò ní pa ọ́ tì, mi ò sì ní fi ọ́ sílẹ̀.+ 6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+

7 “Ṣáà rí i pé o jẹ́ onígboyà àti alágbára gidigidi, kí o sì rí i pé ò ń tẹ̀ lé gbogbo Òfin tí Mósè ìránṣẹ́ mi pa láṣẹ fún ọ. Má yà kúrò nínú rẹ̀ sí ọ̀tún tàbí sí òsì,+ kí o lè máa hùwà ọgbọ́n níbikíbi tí o bá lọ.+ 8 Ìwé Òfin yìí kò gbọ́dọ̀ kúrò ní ẹnu rẹ,+ kí o máa fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ kà á* tọ̀sántòru, kí o lè rí i pé ò ń tẹ̀ lé gbogbo ohun tí wọ́n kọ sínú rẹ̀;+ ìgbà yẹn ni ọ̀nà rẹ máa yọrí sí rere, tí wàá sì máa hùwà ọgbọ́n.+ 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+

10 Jóṣúà wá pàṣẹ fún àwọn olórí àwọn èèyàn náà pé: 11 “Ẹ lọ káàkiri ibùdó, kí ẹ sì pa àṣẹ yìí fún àwọn èèyàn náà pé, ‘Ẹ ṣètò oúnjẹ sílẹ̀, torí ní ọjọ́ mẹ́ta òní, ẹ máa sọdá Jọ́dánì láti lọ gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín.’”+

12 Jóṣúà sọ fún àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè pé: 13 “Ẹ rántí ohun tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà pa láṣẹ fún yín pé:+ ‘Jèhófà Ọlọ́run yín máa fún yín ní ìsinmi, ó sì ti fún yín ní ilẹ̀ yìí. 14 Àwọn ìyàwó yín, àwọn ọmọ yín àtàwọn ẹran ọ̀sìn yín á máa gbé ní ilẹ̀ tí Mósè fún yín ní apá ibí yìí* ní Jọ́dánì,+ àmọ́ kí gbogbo ẹ̀yin jagunjagun tó lákíkanjú+ sọdá ṣáájú àwọn arákùnrin yín, kí ẹ tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun.+ Kí ẹ ràn wọ́n lọ́wọ́ 15 títí Jèhófà fi máa fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi, bó ṣe ṣe fún yín, tí àwọn náà á sì gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún wọn. Kí ẹ wá pa dà sí ilẹ̀ tí wọ́n fún yín pé kí ẹ máa gbé, kí ẹ sì gbà á, ilẹ̀ tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín ní ìlà oòrùn Jọ́dánì.’”+

16 Wọ́n dá Jóṣúà lóhùn pé: “A máa ṣe gbogbo ohun tí o pa láṣẹ fún wa, a sì máa lọ sí ibikíbi tí o bá rán wa.+ 17 Bí a ṣe fetí sí gbogbo ohun tí Mósè sọ gẹ́lẹ́ la máa fetí sí ọ. Kí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣáà ti wà pẹ̀lú rẹ bó ṣe wà pẹ̀lú Mósè.+ 18 Ṣe la máa pa ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sí àṣẹ rẹ, tí kò sì tẹ̀ lé gbogbo ohun tí o bá pa láṣẹ fún un.+ Ìwọ ṣáà ti jẹ́ onígboyà àti alágbára.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́