ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aginjù òkun (1-10)

        • Ó ń ṣọ́nà láti orí ilé ìṣọ́ (8)

        • “Bábílónì ti ṣubú!” (9)

      • Ìkéde lòdì sí Dúmà àti aṣálẹ̀ tó tẹ́jú (11-17)

        • “Olùṣọ́, báwo ni òru ṣe rí?” (11)

Àìsáyà 21:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó jọ pé agbègbè Babilóníà àtijọ́ ló ń sọ.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:1, 20
  • +Ais 13:4, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 11

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 240

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 215-216

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 110

Àìsáyà 21:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:11, 28; Da 5:28, 30
  • +Sm 137:1; Ais 14:4, 7; 35:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 216-217

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 110

Àìsáyà 21:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìrora fi kún ìbàdí mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hab 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 217-218

Àìsáyà 21:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 217-218

Àìsáyà 21:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fi òróró sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 5:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 218-221

Àìsáyà 21:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 7

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 221-223

Àìsáyà 21:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 221-223

Àìsáyà 21:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:17; Hab 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 260

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 30

    1/1/2000, ojú ìwé 8, 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 223

Àìsáyà 21:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:3, 9; 51:27, 28
  • +Ais 13:19; 14:4; 45:1; Jer 51:8; Da 5:28, 30; Ifi 14:8; 18:2
  • +Jer 50:2; 51:44, 52

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 260

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 7-8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 223-224

Àìsáyà 21:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ọmọkùnrin ibi ìpakà mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:46

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 224-225

Àìsáyà 21:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ìpanumọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 32:3; Di 2:8; Sm 137:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 225, 227

Àìsáyà 21:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 225-227

Àìsáyà 21:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 227-228

Àìsáyà 21:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 6:19; Jer 25:17, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 228

Àìsáyà 21:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 228

Àìsáyà 21:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tí wọ́n fara balẹ̀ kà bíi ti alágbàṣe”; ìyẹn, ní ọdún kan géérégé.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 25:13; Sm 120:5; Sol 1:5; Ais 42:11; Jer 49:28; Isk 27:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 228-229

Àìsáyà 21:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 228-229

Àwọn míì

Àìsá. 21:1Ais 13:1, 20
Àìsá. 21:1Ais 13:4, 18
Àìsá. 21:2Jer 51:11, 28; Da 5:28, 30
Àìsá. 21:2Sm 137:1; Ais 14:4, 7; 35:10
Àìsá. 21:3Hab 3:16
Àìsá. 21:5Da 5:1
Àìsá. 21:8Isk 3:17; Hab 2:1
Àìsá. 21:9Jer 50:3, 9; 51:27, 28
Àìsá. 21:9Ais 13:19; 14:4; 45:1; Jer 51:8; Da 5:28, 30; Ifi 14:8; 18:2
Àìsá. 21:9Jer 50:2; 51:44, 52
Àìsá. 21:101Ọb 8:46
Àìsá. 21:11Jẹ 32:3; Di 2:8; Sm 137:7
Àìsá. 21:13Jer 25:17, 23
Àìsá. 21:14Job 6:19; Jer 25:17, 23
Àìsá. 21:16Jẹ 25:13; Sm 120:5; Sol 1:5; Ais 42:11; Jer 49:28; Isk 27:21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 21:1-17

Àìsáyà

21 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aginjù òkun:*+

Ó ń bọ̀ bí ìjì tó fẹ́ kọjá ní gúúsù,

Láti aginjù, láti ilẹ̀ tó ń dẹ́rù bani.+

 2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi:

Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,

Apanirun sì ń pani run.

Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+

Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+

 3 Ìdí nìyẹn tí mo fi ń jẹ̀rora gidigidi.*+

Àwọn iṣan mi ń sún kì,

Bíi ti obìnrin tó ń bímọ.

Ìdààmú tó bá mi ò jẹ́ kí n gbọ́ràn;

Ìyọlẹ́nu tó bá mi ò jẹ́ kí n ríran.

 4 Ọkàn mi dà rú; jìnnìjìnnì bò mí.

Ìrọ̀lẹ́ tí mò ń retí ń dẹ́rù bà mí.

 5 Ẹ tẹ́ tábìlì, kí ẹ sì to àwọn ìjókòó!

Ẹ jẹ, kí ẹ sì mu!+

Ẹ dìde, ẹ̀yin ìjòyè, ẹ fi òróró yan* apata!

 6 Torí ohun tí Jèhófà sọ fún mi nìyí:

“Lọ, yan aṣọ́nà, kí o sì ní kó ròyìn ohun tó bá rí.”

 7 Ó sì rí kẹ̀kẹ́ ogun àtàwọn ẹṣin,

Kẹ̀kẹ́ ogun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,

Kẹ̀kẹ́ ogun ràkúnmí.

Ó fara balẹ̀ wò ó, ó sì kíyè sí i dáadáa.

 8 Ó wá ké jáde bíi kìnnìún, ó ní:

“Jèhófà, orí ilé ìṣọ́ ni mò ń dúró sí nígbà gbogbo ní ọ̀sán,

Mi ò sì kúrò níbi tí a fi mí ṣọ́ ní gbogbo òru.+

 9 Wo ohun tó ń bọ̀:

Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+

Ó wá sọ pé:

“Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+

Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+

10 Ẹ̀yin èèyàn mi tí wọ́n ti pa bí ọkà,

Ohun tó tinú ibi ìpakà mi jáde,*+

Mo ti sọ ohun tí mo gbọ́ fún ọ látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

11 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Dúmà:*

Ẹnì kan ń ké pè mí láti Séírì+ pé:

“Olùṣọ́, báwo ni òru ṣe rí?

Olùṣọ́, báwo ni òru ṣe rí?”

12 Olùṣọ́ sọ pé:

“Òwúrọ̀ ń bọ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni òru.

Tí ẹ bá fẹ́ wádìí, ẹ wádìí.

Ẹ tún pa dà wá!”

13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú:

Inú igbó, nínú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú lẹ máa sùn mọ́jú,

Ẹ̀yin ará Dédánì+ tó ń rìnrìn àjò.

14 Ẹ gbé omi wá pàdé ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ,

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ Témà,+

Kí ẹ sì gbé oúnjẹ wá fún ẹni tó ń sá lọ.

15 Torí wọ́n ti sá fún àwọn idà, idà tí wọ́n fà yọ,

Fún ọrun tí wọ́n fà àti ogun tó gbóná janjan.

16 Torí ohun tí Jèhófà sọ fún mi nìyí: “Láàárín ọdún kan, bíi ti ọdún alágbàṣe,* gbogbo ògo Kídárì+ máa wá sí òpin. 17 Àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú àwọn jagunjagun Kídárì tí wọ́n ń ta ọfà máa kéré, torí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti sọ ọ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́