ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Kéènì àti Ébẹ́lì (1-16)

      • Àtọmọdọ́mọ Kéènì (17-24)

      • Sẹ́ẹ̀tì àti Énọ́ṣì ọmọ rẹ̀ (25, 26)

Jẹ́nẹ́sísì 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:28
  • +1Jo 3:10-12; Jud 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 13

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 9-11

Jẹ́nẹ́sísì 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 23:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 13-14

    1/15/2002, ojú ìwé 22

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 11-12

Jẹ́nẹ́sísì 4:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2002, ojú ìwé 21

    2/1/1999, ojú ìwé 21

    6/15/1996, ojú ìwé 4-5

Jẹ́nẹ́sísì 4:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:12
  • +Heb 11:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 17-19

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2015, ojú ìwé 19

    1/1/2013, ojú ìwé 14-15

    1/15/2002, ojú ìwé 21

    8/15/2000, ojú ìwé 13-14

    2/1/1999, ojú ìwé 21

    6/15/1996, ojú ìwé 4

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 14-16

Jẹ́nẹ́sísì 4:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ó sì sorí kodò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 15

    1/15/2002, ojú ìwé 21-22

    2/1/1999, ojú ìwé 21

    6/15/1996, ojú ìwé 4-5

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 16

Jẹ́nẹ́sísì 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/1999, ojú ìwé 21, 23

    1/15/1999, ojú ìwé 21

    6/15/1994, ojú ìwé 14

Jẹ́nẹ́sísì 4:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣé mi ò ní tẹ́wọ́ gbà ọ́ ni?”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2014, ojú ìwé 28

    1/15/2002, ojú ìwé 22

    2/1/1999, ojú ìwé 21-23

    1/15/1999, ojú ìwé 21

    6/15/1996, ojú ìwé 4-5

    6/15/1994, ojú ìwé 14

    2/1/1994, ojú ìwé 31

    Jí!,

    10/2011, ojú ìwé 24

Jẹ́nẹ́sísì 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 23:35; 1Jo 3:10-12; Jud 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 15

    9/15/2002, ojú ìwé 28

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 16

Jẹ́nẹ́sísì 4:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2002, ojú ìwé 22

Jẹ́nẹ́sísì 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 74-75

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 100-101

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2004, ojú ìwé 14

    11/15/1995, ojú ìwé 10

Jẹ́nẹ́sísì 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:5

Jẹ́nẹ́sísì 4:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “agbára.”

Jẹ́nẹ́sísì 4:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ní orí ilẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 4:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbé àmì kan kalẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2004, ojú ìwé 29

    1/15/2002, ojú ìwé 22-23

    2/1/1999, ojú ìwé 21-22

Jẹ́nẹ́sísì 4:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Nódì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:8

Jẹ́nẹ́sísì 4:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 5:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 25

    1/1/2004, ojú ìwé 29

    7/15/1992, ojú ìwé 4

    Jí!,

    10/8/2005, ojú ìwé 22

Jẹ́nẹ́sísì 4:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2002, ojú ìwé 6

Jẹ́nẹ́sísì 4:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 3

Jẹ́nẹ́sísì 4:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 4:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 3

Jẹ́nẹ́sísì 4:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ẹni Tí Wọ́n Yàn; Ẹni Tí Wọ́n Gbé Kalẹ̀.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 5:3; 1Kr 1:1
  • +Jẹ 4:8; Mt 23:35; Heb 11:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2009, ojú ìwé 13

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 62

Jẹ́nẹ́sísì 4:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 5:6; Lk 3:23, 38

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 19

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2017 ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2005, ojú ìwé 15-16

    9/15/2001, ojú ìwé 29

    1/15/1997, ojú ìwé 30

    11/15/1993, ojú ìwé 12

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 62-64

Àwọn míì

Jẹ́n. 4:1Jẹ 1:28
Jẹ́n. 4:11Jo 3:10-12; Jud 11
Jẹ́n. 4:2Mt 23:35
Jẹ́n. 4:4Ẹk 13:12
Jẹ́n. 4:4Heb 11:4
Jẹ́n. 4:8Mt 23:35; 1Jo 3:10-12; Jud 11
Jẹ́n. 4:10Heb 12:24
Jẹ́n. 4:11Jẹ 9:5
Jẹ́n. 4:16Jẹ 2:8
Jẹ́n. 4:17Jẹ 5:4
Jẹ́n. 4:24Jẹ 4:15
Jẹ́n. 4:25Jẹ 4:8; Mt 23:35; Heb 11:4
Jẹ́n. 4:25Jẹ 5:3; 1Kr 1:1
Jẹ́n. 4:26Jẹ 5:6; Lk 3:23, 38
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 4:1-26

Jẹ́nẹ́sísì

4 Ádámù bá Éfà ìyàwó rẹ̀ ní àṣepọ̀, ó sì lóyún.+ Nígbà tó bí Kéènì,+ ó sọ pé: “Jèhófà ti mú kí n ní* ọmọkùnrin kan.” 2 Lẹ́yìn náà, ó tún bí Ébẹ́lì,+ àbúrò rẹ̀.

Ébẹ́lì di olùṣọ́ àgùntàn, àmọ́ Kéènì di àgbẹ̀. 3 Nígbà tó yá, Kéènì mú àwọn èso kan wá, ó fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà. 4 Àmọ́ Ébẹ́lì mú lára àwọn àkọ́bí ẹran+ rẹ̀ wá, pẹ̀lú ọ̀rá wọn. Jèhófà ṣojúure sí Ébẹ́lì, ó sì gba ọrẹ+ rẹ̀, 5 àmọ́ kò ṣojúure sí Kéènì rárá, kò sì gba ọrẹ rẹ̀. Torí náà, Kéènì bínú gan-an, inú rẹ̀ ò sì dùn.* 6 Jèhófà wá sọ fún Kéènì pé: “Kí ló dé tí inú ń bí ọ tó báyìí, tí inú rẹ ò sì dùn? 7 Tí o bá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe rere, ṣé o ò ní pa dà rí ojúure ni?* Àmọ́ tí o ò bá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe rere, ẹ̀ṣẹ̀ lúgọ sí ẹnu ọ̀nà, ó sì fẹ́ jọba lé ọ lórí; àmọ́ ṣé o máa kápá rẹ̀?”

8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ 9 Lẹ́yìn náà, Jèhófà bi Kéènì pé: “Ibo ni Ébẹ́lì arákùnrin rẹ wà?” Ó fèsì pé: “Mi ò mọ̀. Ṣé èmi ni olùṣọ́ arákùnrin mi ni?” 10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+ 11 Ní báyìí, ègún wà lórí rẹ, màá sì lé ọ kúrò lórí ilẹ̀ tó la ẹnu láti mu ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ tí o ta sílẹ̀.+ 12 Tí o bá dá oko, ilẹ̀ ò ní mú èso* rẹ̀ jáde fún ọ. O sì máa di alárìnká àti ìsáǹsá ní ayé.” 13 Kéènì wá sọ fún Jèhófà pé: “Ìyà ẹ̀ṣẹ̀ mi ti pọ̀ jù fún mi. 14 Lónìí, ò ń lé mi kúrò ní ilẹ̀,* èmi yóò sì kúrò níwájú rẹ; èmi yóò di alárìnká àti ìsáǹsá ní ayé, ó sì dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá rí mi yóò pa mí.” 15 Jèhófà wá sọ fún un pé: “Kí ìyẹn má bàa ṣẹlẹ̀, ẹnikẹ́ni tó bá pa Kéènì yóò jìyà ìlọ́po méje.”

Jèhófà wá ṣe àmì kan* fún Kéènì kí ẹnikẹ́ni tó bá rí i má bàa pa á. 16 Lẹ́yìn náà, Kéènì kúrò níwájú Jèhófà, ó sì lọ ń gbé ní ilẹ̀ Ìgbèkùn,* ní apá ìlà oòrùn Édẹ́nì.+

17 Kéènì wá bá ìyàwó+ rẹ̀ ní àṣepọ̀, ó lóyún, ó sì bí Énọ́kù. Lẹ́yìn náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ìlú kan, ó sì fi orúkọ ọmọ rẹ̀ Énọ́kù pe ìlú náà. 18 Énọ́kù wá bí Írádì. Írádì bí Mèhújáélì, Mèhújáélì bí Mètúṣáélì, Mètúṣáélì sì bí Lámékì.

19 Lámékì fẹ́ ìyàwó méjì. Orúkọ àkọ́kọ́ ni Ádà, orúkọ ìkejì sì ni Síláhì. 20 Ádà bí Jábálì. Òun ni ẹni àkọ́kọ́ tó gbé inú àgọ́ tó sì ní ẹran ọ̀sìn. 21 Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Júbálì. Òun ni ẹni àkọ́kọ́ tó lo háàpù àti fèrè ape. 22 Bákan náà, Síláhì bí Tubali-kéénì, ẹni tó ń rọ onírúurú irinṣẹ́ tí wọ́n fi bàbà àti irin ṣe. Náámà sì ni arábìnrin Tubali-kéénì. 23 Lámékì ń sọ fún àwọn ìyàwó rẹ̀, Ádà àti Síláhì, pé:

“Ẹ gbọ́ ohùn mi, ẹ̀yin ìyàwó Lámékì;

Ẹ fetí sí mi:

Mo pa ọkùnrin kan torí ó ṣe mí léṣe,

Àní ọ̀dọ́kùnrin kan, torí ó lù mí.

24 Tí ẹni tó bá pa Kéènì bá máa jìyà ní ìlọ́po méje,+

Ẹni tó bá pa Lámékì máa jìyà ní ìgbà àádọ́rin ó lé méje (77).”

25 Ádámù tún bá ìyàwó rẹ̀ ní àṣepọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sẹ́ẹ̀tì*+ torí ó sọ pé: “Ọlọ́run ti fi ọmọ* míì rọ́pò Ébẹ́lì fún mi, torí Kéènì pa á.”+ 26 Sẹ́ẹ̀tì náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ ọ́ ní Énọ́ṣì.+ Ìgbà yẹn ni àwọn èèyàn bẹ̀rẹ̀ sí í pe orúkọ Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́