ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 113
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ọlọ́run lókè máa ń gbé aláìní dìde

        • Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí láé (2)

        • Ọlọ́run máa ń tẹ̀ ba (6)

Sáàmù 113:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/1997, ojú ìwé 16

    11/15/1992, ojú ìwé 8-9

Sáàmù 113:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 16:36; 29:10; Sm 106:48

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 8-9

Sáàmù 113:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 72:19; 86:9; Ais 59:19; Mal 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2006, ojú ìwé 14

    11/15/1992, ojú ìwé 9

Sáàmù 113:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 97:9; 99:2
  • +1Ọb 8:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 9

Sáàmù 113:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó gúnwà sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:11

Sáàmù 113:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 18:35; 138:6; Ais 57:15; 66:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2006, ojú ìwé 14

    6/15/2006, ojú ìwé 31

    10/15/2005, ojú ìwé 27

    11/1/2004, ojú ìwé 29

    12/1/1993, ojú ìwé 14-15

    11/15/1992, ojú ìwé 9

Sáàmù 113:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ààtàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 2:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2006, ojú ìwé 14

    11/15/1992, ojú ìwé 9-10

Sáàmù 113:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 9-10

Sáàmù 113:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin.”

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 2:5; Ais 54:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 10

Àwọn míì

Sm 113:21Kr 16:36; 29:10; Sm 106:48
Sm 113:3Sm 72:19; 86:9; Ais 59:19; Mal 1:11
Sm 113:4Sm 97:9; 99:2
Sm 113:41Ọb 8:27
Sm 113:5Ẹk 15:11
Sm 113:6Sm 18:35; 138:6; Ais 57:15; 66:2
Sm 113:71Sa 2:7
Sm 113:91Sa 2:5; Ais 54:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 113:1-9

Sáàmù

113 Ẹ yin Jáà!*

Ẹ mú ìyìn wá, ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,

Ẹ yin orúkọ Jèhófà.

 2 Kí á máa yin orúkọ Jèhófà

Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.+

 3 Láti yíyọ oòrùn títí dé wíwọ̀ rẹ̀,

Kí á máa yin orúkọ Jèhófà.+

 4 Jèhófà ga ju gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+

Ògo rẹ̀ ga ju ọ̀run lọ.+

 5 Ta ló dà bíi Jèhófà Ọlọ́run wa,+

Ẹni tó ń gbé* ibi gíga?

 6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+

 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku.

Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+

 8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,

Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.

 9 Ó ń fún àgàn ní ilé

Kí ó lè di abiyamọ aláyọ̀, ìyá àwọn ọmọ.*+

Ẹ yin Jáà!*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́