ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 5
  • Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ká mọ̀, ìyẹn ọ̀rọ̀ rẹ̀ ló wà nínú Bíbélì. Ó jẹ́ ká mọ bí a ṣe lè ṣàṣeyọrí nígbèésí ayé àti bí a ṣe lè rí ojú rere Ọlọ́run. Ó tún dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  1. 1 Ta ni Ọlọ́run?

  2. 2 Báwo lo ṣe lè mọ Ọlọ́run?

  3. 3 Ta ló kọ Bíbélì?

  4. 4 Ṣé Bíbélì máa ń tọ̀nà tó bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì?

  5. 5 Kí ló wà nínú Bíbélì?

  6. 6 Kí ni Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà?

  7. 7 Kí ni Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa ọjọ́ wa?

  8. 8 Ṣé Ọlọ́run ló lẹ̀bi ìyà tó ń jẹ aráyé?

  9. 9 Kí nìdí táwọn èèyàn fi ń jìyà?

  10. 10 Kí ni Bíbélì ṣèlérí nípa ọjọ́ ọ̀la?

  11. 11 Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí ẹni tó bá kú?

  12. 12 Ìrètí wo ló wà fún àwọn tó ti kú?

  13. 13 Kí ni Bíbélì sọ nípa iṣẹ́?

  14. 14 Báwo lo ṣe lè fọgbọ́n lo ohun ìní rẹ?

  15. 15 Báwo lo ṣe lè láyọ̀?

  16. 16 Kí lo lè ṣe tí àníyàn bá ń dà ọ́ láàmú?

  17. 17 Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran ìdílé rẹ lọ́wọ́?

  18. 18 Báwo lo ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run?

  19. 19 Kí ló wà nínú oríṣiríṣi ìwé tó para pọ̀ di Bíbélì?

  20. 20 Báwo lo ṣe lè ka Bíbélì kó sì ṣe ọ́ láǹfààní?

BÍ O ṢE LÈ WÁ ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ

Ìwé kéékèèké mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) ló para pọ̀ di Bíbélì. Apá méjì ló pín sí, ìyẹn Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù àti Árámáíkì tí wọ́n ń pè ní (“Májẹ̀mú Láéláé”) àti Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì tí wọ́n ń pè ní (“Májẹ̀mú Tuntun.”) Ìwé kọ̀ọ̀kan tó wà nínú Bíbélì ní àwọn orí àti ẹsẹ. Tí a bá tọ́ka sí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan, nọ́ńbà tó tẹ̀ lé orúkọ ìwé yẹn dúró fún orí, nígbà tí nọ́ńbà tó tẹ̀ lé e dúró fún ẹsẹ. Bí àpẹẹrẹ, Jẹ́nẹ́sísì 1:1 túmọ̀ sí Jẹ́nẹ́sísì orí 1, ẹsẹ 1.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́