DIUTARÓNÓMÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Wọ́n kúrò ní Òkè Hórébù (1-8)
Wọ́n yan àwọn olórí àti àwọn onídàájọ́ (9-18)
Wọ́n ṣàìgbọràn ní Kadeṣi-bánéà (19-46)
2
3
Wọ́n ṣẹ́gun Ógù ọba Báṣánì (1-7)
Wọ́n pín ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn Jọ́dánì (8-20)
Mósè sọ fún Jóṣúà pé kó má bẹ̀rù (21, 22)
Mósè ò ní wọ ilẹ̀ náà (23-29)
4
Wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ́ onígbọràn (1-14)
Jèhófà fẹ́ kí wọ́n máa jọ́sìn òun nìkan (15-31)
Kò sí Ọlọ́run míì àfi Jèhófà (32-40)
Àwọn ìlú ààbò ní ìlà oòrùn Jọ́dánì (41-43)
Ó fún Ísírẹ́lì ní Òfin (44-49)
5
Jèhófà bá wọn dá májẹ̀mú ní Hórébù (1-5)
Wọ́n tún Òfin Mẹ́wàá sọ (6-22)
Ẹ̀rù ba àwọn èèyàn náà ní Òkè Sínáì (23-33)
6
Fi gbogbo ọkàn rẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà (1-9)
“Fetí sílẹ̀, ìwọ Ísírẹ́lì” (4)
Kí àwọn òbí máa kọ́ àwọn ọmọ wọn (6, 7)
Ẹ má ṣe gbàgbé Jèhófà (10-15)
Ẹ ò gbọ́dọ̀ dán Jèhófà wò (16-19)
Ẹ sọ fún àwọn ọmọ yín (20-25)
7
Orílẹ̀-èdè méje tí wọ́n máa pa run (1-6)
Ìdí tí Ọlọ́run fi yan Ísírẹ́lì (7-11)
Wọ́n á ṣàṣeyọrí tí wọ́n bá ṣègbọràn (12-26)
8
9
10
11
Ẹ ti rí bí Jèhófà ṣe tóbi tó (1-7)
Ilẹ̀ Ìlérí (8-12)
Wọ́n á rí ìbùkún tí wọ́n bá ṣègbọràn (13-17)
Kí wọ́n tẹ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mọ́ ọkàn wọn (18-25)
“Ìbùkún àti ègún” (26-32)
12
Ibi tí Ọlọ́run bá yàn ni kí ẹ ti máa jọ́sìn (1-14)
Wọ́n lè jẹ ẹran àmọ́ wọn ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ (15-28)
Má ṣe kó sí ìdẹkùn àwọn ọlọ́run míì (29-32)
13
14
Ohun tí kò yẹ kí wọ́n ṣe nítorí òkú (1, 2)
Àwọn oúnjẹ tó mọ́ àti èyí tí kò mọ́ (3-21)
Kí wọ́n mú ìdá mẹ́wàá wá fún Jèhófà (22-29)
15
Lẹ́yìn ọdún méje-méje, kí wọ́n má ṣe san gbèsè pa dà (1-6)
Bí wọ́n á ṣe máa ran àwọn aláìní lọ́wọ́ (7-11)
Kí wọ́n máa dá ẹrú sílẹ̀ ní ọdún keje (12-18)
Kí wọ́n ya àwọn àkọ́bí ẹran sí mímọ́ (19-23)
16
Ìrékọjá; Àjọyọ̀ Àkàrà Aláìwú (1-8)
Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (9-12)
Àjọyọ̀ Àtíbàbà (13-17)
Bí wọ́n ṣe máa yan àwọn onídàájọ́ (18-20)
Àwọn ohun tí wọn ò gbọ́dọ̀ jọ́sìn (21, 22)
17
Ẹbọ wọn kò gbọ́dọ̀ ní àbùkù lára (1)
Ohun tí wọ́n máa ṣe fún ẹni tó bá sin ọlọ́run míì (2-7)
Àwọn ẹjọ́ tó bá ṣòroó dá (8-13)
Ìlànà fún ọba tí wọ́n bá yàn (14-20)
18
Ìpín àwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì (1-8)
Wọn ò gbọ́dọ̀ lọ́wọ́ sí ìbẹ́mìílò (9-14)
Wòlíì bíi Mósè (15-19)
Bí wọ́n ṣe máa mọ wòlíì èké (20-22)
19
Ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ àtàwọn ìlú ààbò (1-13)
Wọn ò gbọ́dọ̀ sún ààlà sẹ́yìn (14)
Àwọn ẹlẹ́rìí níbi ìgbẹ́jọ́ (15-21)
20
21
Tí wọn ò bá mọ ẹni tó pààyàn (1-9)
Tí wọ́n bá fẹ́ fi ẹrú ṣaya (10-14)
Ẹ̀tọ́ àkọ́bí (15-17)
Tí ọmọ bá ya alágídí (18-21)
Ẹni ègún ni ẹni tí wọ́n bá gbé kọ́ sórí òpó igi (22, 23)
22
Kí wọ́n máa bójú tó ẹran ọmọnìkejì wọn (1-4)
Obìnrin ò gbọ́dọ̀ wọ aṣọ ọkùnrin, ọkùnrin ò sì gbọ́dọ̀ wọ ti obìnrin (5)
Máa ṣàánú àwọn ẹyẹ (6, 7)
Ṣe ìgbátí sí òrùlé (8)
Àwọn ohun tí wọn ò gbọ́dọ̀ ṣe pọ̀ (9-11)
Kókó wajawaja lára aṣọ (12)
Àwọn òfin nípa ìbálòpọ̀ tí kò tọ́ (13-30)
23
Àwọn tí kò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Ọlọ́run (1-8)
Kí ibùdó máa wà ní mímọ́ (9-14)
Ẹrú tó sá lọ (15, 16)
Wọn ò gbọ́dọ̀ ṣe aṣẹ́wó (17, 18)
Èlé àti ẹ̀jẹ́ (19-23)
Ohun tí ẹni tó ń kọjá lọ lè jẹ (24, 25)
24
Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-5)
Kí wọ́n máa ka ẹ̀mí sí pàtàkì (6-9)
Kí wọ́n máa gba tàwọn aláìní rò (10-18)
Òfin nípa pípèéṣẹ́ (19-22)
25
Iye ẹgba tí wọ́n lè na èèyàn (1-3)
O ò gbọ́dọ̀ dí akọ màlúù tó ń pa ọkà lẹ́nu (4)
Ṣíṣú obìnrin lópó (5-10)
Tí obìnrin bá rá ọkùnrin mú ní abẹ́ (11, 12)
Ìwọ̀n àti òṣùwọ̀n tó péye (13-16)
Kí wọ́n pa àwọn Ámálékì run (17-19)
26
27
Kí wọ́n kọ Òfin sára òkúta (1-10)
Òkè Ébálì àti Òkè Gérísímù (11-14)
Wọ́n tún àwọn ègún náà kà (15-26)
28
29
30
Bí wọ́n ṣe máa pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (1-10)
Àwọn àṣẹ Jèhófà kò nira (11-14)
Kí wọ́n yan ìyè tàbí ikú (15-20)
31
Ikú Mósè sún mọ́lé (1-8)
Kí wọ́n máa ka Òfin Ọlọ́run sí wọn létí (9-13)
Ó faṣẹ́ lé Jóṣúà lọ́wọ́ (14, 15)
Àsọtẹ́lẹ̀ bí Ísírẹ́lì ṣe máa ya ọlọ̀tẹ̀ (16-30)
32
33
34