JÓṢÚÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Jóṣúà rán amí méjì lọ sí Jẹ́ríkò (1-3)
Ráhábù fi àwọn amí pa mọ́ (4-7)
Wọ́n ṣèlérí fún Ráhábù (8-21a)
Àwọn amí pa dà sọ́dọ̀ Jóṣúà (21b-24)
3
4
5
Wọ́n dádọ̀dọ́ ní Gílígálì (1-9)
Wọ́n ṣe Ìrékọjá; mánà ò rọ̀ mọ́ (10-12)
Olórí àwọn ọmọ ogun Jèhófà (13-15)
6
7
Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì ní ìlú Áì (1-5)
Àdúrà Jóṣúà (6-9)
Ẹ̀ṣẹ̀ mú kí wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (10-15)
Àṣírí Ákánì tú, wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta (16-26)
8
Jóṣúà ní kí wọ́n lúgọ láti gbéjà ko ìlú Áì (1-13)
Wọ́n ṣẹ́gun ìlú Áì (14-29)
Wọ́n ka Òfin ní Òkè Ébálì (30-35)
9
Àwọn ará Gíbíónì dọ́gbọ́n wá àlàáfíà (1-15)
Àṣírí àwọn ará Gíbíónì tú (16-21)
Àwọn ará Gíbíónì á máa ṣẹ́gi, wọ́n á sì máa pọnmi (22-27)
10
Ísírẹ́lì gbèjà Gíbíónì (1-7)
Jèhófà jà fún Ísírẹ́lì (8-15)
Wọ́n pa ọba márààrún tó gbéjà kò wọ́n (16-28)
Wọ́n gba àwọn ìlú tó wà ní gúúsù (29-43)
11
12
13
Àwọn ilẹ̀ tí wọn ò tíì gbà (1-7)
Wọ́n pín ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn Jọ́dánì (8-14)
Ogún Rúbẹ́nì (15-23)
Ogún Gádì (24-28)
Ogún Mánásè ní ìlà oòrùn (29-32)
Jèhófà ni ogún àwọn ọmọ Léfì (33)
14
15
16
17
18
19
20
21
22
Àwọn ẹ̀yà tó wà ní ìlà oòrùn pa dà sílé (1-8)
Wọ́n mọ pẹpẹ sí Jọ́dánì (9-12)
Wọ́n ṣàlàyé ohun tí pẹpẹ náà túmọ̀ sí (13-29)
Wọ́n yanjú ọ̀rọ̀ náà (30-34)
23
24
Jóṣúà sọ ìtàn Ísírẹ́lì (1-13)
Ó rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n sin Jèhófà (14-24)
Jóṣúà bá Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú (25-28)
Jóṣúà kú, wọ́n sì sin ín (29-31)
Wọ́n sin egungun Jósẹ́fù sí Ṣékémù (32)
Élíásárì kú, wọ́n sì sin ín (33)