Ojú ìwé 2
Ìkọlù Àrùn Ọkàn-àyà Kí Ni A Lè Ṣe? 3-13
Kí ni ó ń fa ìkọlù àrùn ọkàn-àyà? Báwo ni àwọn ènìyàn tí ó ní àrùn náà àti àwọn olólùfẹ́ wọ́n ṣe lè kojú rẹ̀? Kí ni a lè ṣe láti dín ewu náà kù?
Ìtẹríba Aya —Kí Ni Ó Túmọ̀ Sí? 14
Kí ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ nípa ìtẹríba aya kan fún ọkọ rẹ̀?
Platypus Àràmàǹdà 16
Kí ni ẹ̀dá kékeré onítìjú tí ó ka sáyẹ́ǹsì láyà yìí jẹ́ gan-an?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Leslie’s
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure Healesville Sanctuary