ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g96 12/22 ojú ìwé 31
  • Atọ́ka Fún Ìdìpọ̀ 77 Jí!

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Atọ́ka Fún Ìdìpọ̀ 77 Jí!
  • Jí!—1996
  • Ìsọ̀rí
  • ÀJỌṢEPỌ̀ Ẹ̀DÁ ÈNÌYÀN
  • ÀWỌN ÀLÁMỌ̀RÍ ÀTI IPÒ AYÉ
  • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
  • ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
  • ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
  • ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́
  • ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
  • ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
  • ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀
  • ÌSÌN
  • OJÚ-ÌWÒYE BÍBÉLÌ
  • Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Jí!—1996
g96 12/22 ojú ìwé 31

Atọ́ka Fún Ìdìpọ̀ 77 Jí!

ÀJỌṢEPỌ̀ Ẹ̀DÁ ÈNÌYÀN

Abúlé Kárí Ayé Ṣùgbọ́n Tí Ó Pín Yẹ́lẹyẹ̀lẹ Síbẹ̀, 7/8

A Óò Ha Jíhìn fún Ohun Tí A Bá Ṣe Bí?, 9/22

Àṣà Lílo Tẹlifóònù, 6/8

Fífi Ìbálòpọ̀ Fòòró Ẹni, 5/22

Ìgbàṣọmọ, 5/8

Kí N Lè Bá Ọmọ Mi Sọ̀rọ̀, Mo Kọ́ Èdè Míràn (Odi), 11/8

Ọ̀rẹ́ Mi Ọ̀wọ́n, 2/22

Ọ̀rọ̀ Dídunni sí Ọ̀rọ̀ Atunilára, 10/22

Ta Ló Yẹ Kó Pinnu Bí Ìdílé Yóò Ṣe Tóbi Tó?, 10/8

Ta Ni O Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé?, 2/8

ÀWỌN ÀLÁMỌ̀RÍ ÀTI IPÒ AYÉ

Àjọ Ìpàǹpá Àwọn Obìnrin, 10/22

Àwọn Ìjábá Àdánidá—Ríran Àwọn Ọmọdé Lọ́wọ́ Láti Kojú Wọn, 6/22

“Ètò Ayé Tuntun”—Ìbẹ̀rẹ̀ Tí Kò Fara Rọ, 7/22

Fífi Ìbálòpọ̀ Fòòró Ẹni—Ìṣòro Kárí Ayé, 5/22

Ìbàjẹ́ Tí Ohun Ìrìnnà Ń Ṣe, 6/8

Ìjọba Ha Lè Fòpin sí Ìwà Ọ̀daràn Bí?, 10/8

Ìṣòro Wíwá Ibi Ìsádi, 8/22

Nígbà Tí Ogun Kì Yóò Sí Mọ́, 4/22

Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ, 7/22

Òpin Sànmánì Kan, 7/8

Pílánẹ́ẹ̀tì Wa Tí A Ń Wu Léwu, 1/8

Ṣíṣe Ayédèrú Nǹkan—Ìṣòro Gbogbo Àgbáyé, 3/22

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

‘Ahọ́n Àwọn Akólòlò Pàápàá Yóò Sọ̀rọ̀’ (P. Kunc), 8/22

Àlàyé Jessica, 1/8

Bíbá Àwọn Ènìyàn Sọ̀rọ̀ Pẹ̀lú Ọwọ́ Tí Ń Ṣàpèjúwe (Àpéjọpọ̀ Àwọn Adití), 4/8

Ẹ̀rí Ìgbàgbọ́ Wọn (Ìpakúpa Rẹpẹtẹ Ìjọba Nazi), 6/8

Ìgárá Arúfin Ni Mí Tẹ́lẹ̀ (F. Mannino), 6/22

Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run Ṣàkóso Mi ní Ilẹ̀ Kọ́múníìsì (O. Kadlec), 4/22

“Ká Ní Mo Lè Yí Ìgbà Padà Ni,” 2/22

Kíkojú Ọ̀ràn Ìṣègùn Àìròtẹ́lẹ̀ (C. Vila Ugarte), 6/22

Mímú Èrò Òdì Kúrò (U.S.A.), 11/22

Mo Gba Okun Láti Kojú Àwọn Àdánwò Níwájú (E. Michalec), 12/22

Mo Ń Ráre Kiri, àmọ́ Mo Rí Ète Nínú Ìgbésí Ayé (D. Partrick), 1/8

Òdòdó Tẹ̀mí Hù ní Àfonífojì Ìpọntí (U.S.A.), 7/22

Òtítọ́ Fún Mi Ní Ìwàláàyè Mi Padà (D. Horry), 10/22

Ó Yí Ohun Àkọ́múṣe Rẹ̀ Pa Dà (J. Sorensen), 7/22

Ọlọ́run Jẹ́ Kí A Rí Òun (S. and S. Davis), 3/22

Ọmọ Àkèré (S. Takahashi), 2/22

Ṣíṣèrànwọ́ Láti Mú Kí Iṣẹ́ Abẹ Ọkàn-Àyà Sunwọ̀n Sí I, 1/22

Ṣíṣẹ́pá Ọ̀ràn Ìbànújẹ́ Pẹ̀lú Okun Láti Ọ̀dọ̀ Jèhófà (Sípéènì), 8/22

Wíwà Ní Àmúdá Nígbà Ìrúkèrúdò Ọgbà Ẹ̀wọ̀n (D. Martín), 11/8

ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN

Àwọn Eṣinṣin Akóninírìíra Wọ̀nyẹn, 3/22

Àwọn Igi Rírẹwà, 9/8

Àwọn Irú Ọ̀wọ́ Tí A Wu Léwu, 8/8

Àwọn Òkìtì Coral, 9/22

Brolga, Cassowary, Emu, Jabiru—Àwọn Ẹyẹ Australia, 11/8

Edé—Nǹkan Aládùn Láti Odò Ìdọ́sìn Kan Ni Bí?, 12/22

Ewé Pákí, 7/8

Ewu! Olóró Ni Mí (Àwọn Ejò, Àwọn Aláǹtakùn), 8/22

Ẹkùn! Ẹkùn!, 11/22

Ẹlẹgẹ́ Arìnrìn Àjò Tí Kì Í Káàárẹ̀ (Labalábá Monarch), 10/8

Ẹranko Kudu Yìí Rántí, 12/8

Ẹyẹ Tí Ó Dánìkan Wà Jù Lọ Lágbàáyé (Ayékòótọ́ Spix), 4/8

Habu—Àkòtagìrì Ejò, 7/8

Ìbápàdé Àràmàǹdà (Ẹja Òbéjé), 9/22

Ìdè Ìyá (Ológbò Gba Àwọn Ọmọ Rẹ̀ Là), 9/22

Igi Òpòpó, 5/22

Igbó Àìro fún Àwọn Monarch (Labalábá), 11/22

Irù, 5/22

Kíkẹ́kọ̀ọ́ Bibeli—Nínú Ọgbà Ẹranko!, 3/8

Lammergeier (Ẹyẹ), 2/22

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìrísí Tàn Ọ́ Jẹ (Kádínà), 11/8

‘Ojú Odò’ (Àwọn Ọ̀nì), 1/22

Platypus, 12/8

Robin (Ẹyẹ), 2/8

Rọ́bà Kíkọ, 8/22

Ṣèbé, 3/22

Tulip—Òdòdó Tí Ó Ti La Pákáǹleke Kọjá, 7/8

Wọ́n Ń Fi Ẹṣin Ro Ilẹ̀, 10/22

Yímíyímí Ilẹ̀ Áfíríkà, 3/8

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Àwọn Eré Àṣedárayá Orí Kọ̀m̀pútà àti Fídíò, 8/22

Àwọn Ọ̀dọ́ Mìíràn Ń Gbádùn Gbogbo Ìmóríyá Náà, 7/22

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ní Àkókò Ìṣefàájì?, 9/22

Èé Ṣe Tí Ọlọ́run Ń Jẹ́ Kí Ohun Búburú Ṣẹlẹ̀?, 10/22

Èé Ṣe Tí Ọ̀rẹ́ Kòríkòsùn Mi Fi Kó Lọ Síbòmíràn?, 12/22

Ẹgbẹ́ Eléré Ìdárayá, 2/22, 3/22

Kí Ló Dé Tí N Kò Lè Kẹ́kọ̀ọ́?, 6/22

N kò Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́ Pẹ́ Títí?, 5/22

Orin Rọ́ọ̀kì Àfidípò, 11/22

Ọ̀rẹ́ Tó Wọ Gàù, 1/22

Tábà Tí Kò Ní Èéfín Ha Léwu Bí?, 4/22

ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́

Àìríṣẹ́ṣe, 3/8

Bíbójú Tó Ọ̀ràn Ìnáwó Rẹ, 12/22

ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN

Aláàbọ̀ Ara—Tí Ó Sì Tún Lè Wakọ̀, 5/8

Àrùn AIDS ní Áfíríkà—Kirisẹ́ńdọ̀mù Ló Lẹ̀bi Bí?, 4/22

Àrùn Arunmọléegun, 10/8

Àrùn Kíndìnrín, 11/22

Àrùn Lyme, 6/22

Àwọn Àrùn Panipani, 2/22

“Èso Ápù Kan Lóòjọ́ Máa Ń Mára Le,” 2/8

Etí Híhó, 9/22

Fáírọ́ọ̀sì Panipani Kọ Lu Zaire, 5/8

Fèrèsé Ṣí Ilé Ọlẹ̀ Payá, 8/8

Fi Ọgbọ́n Lo Oògùn, 9/22

Ìdíwọ́ Ìwé Kíkà, 8/8

Ìkọlù Ìpayà, 6/8

Ìkọlù Àrùn Ọkàn-Àyà, 12/8

Ìlera àti Àyíká, 3/22

Ìmúwàdéédéé (Ti Ara), 3/22

Ìrírí Agbonijìgì Tí Maggy Ní (Ìyá Ní Àrùn Jẹjẹrẹ, Oṣù Ọmọ Kò Pé), 12/22

Irù, 5/22

Iṣẹ́ Abẹ Ọkàn-Àyà Sunwọ̀n Sí I, 1/22

Ìwà Àìlèkóra-Ẹni-Níjàánu, 2/8

Jíjẹ Nǹkan Tí Yóò Fa Ìpalára (Èròjà Pan), 10/8

Kíkojú Ọ̀ràn Ìṣègùn Àìròtẹ́lẹ̀ (Gígé Lẹ́sẹ̀), 6/22

Sìgá—O Ha Máa Ń Kọ̀ Ọ́ Bí?, 10/22

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN

Àṣà Ìṣẹ̀dálẹ̀ Àwọn Amerind Kan, 3/8

Àwọn Amerind, 9/8

Àwùjọ Onílé Orí Òpó (Benin), 9/22

Etiopia, 2/22

“Fàdákà Ń Bẹ ní Potosí!” (Bolivia), 8/8

Ibùdókọ̀ Òfuurufú “Kanku” (Japan), 1/8

“Ìgbéyàwó Ìbílẹ̀” ní Gánà, 12/8

Ilé Ẹjọ́ Jákèjádò Àwọn Orílẹ̀-Èdè Europe, 3/8

“Ilé Gogoro Tí Ń Kọrin” ní Australia (Carillon), 6/22

Ìpakúpa ní Èbúté Arthur (Tasmania), 12/22

Iṣin—Oúnjẹ Orílẹ̀-Èdè Jàmáíkà, 10/22

Lahar—Àtúbọ̀tán Òkè Ńlá Pinatubo (Philippines), 5/22

Matterhorn (Switzerland), 2/8

Omi London—Apá Tuntun Kan, 8/22

Orin “Matilda Ẹlẹ́rù” (Australia), 6/8

Pompeii—Ibi Tí Ohunkóhun Kò Yí Padà, 9/8

ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀

Àgbàyanu Àgbáálá Ayé, 1/22

Àwọn Ẹ̀là Ilẹ̀ Tí Ó Fara Sin, 4/8

Àwọn Oníṣẹ́ Mẹ́fà Láti Gbalasa Òfuurufú (Ìrànyòò Ìgbì Ìtànṣán), 3/8

Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ Sánmà Ni Ìgbòkègbodò Àfipawọ́ Mi, 8/8

Ìmúwàdéédéé (Ti Ara), 3/22

Louis Pasteur—Ohun Tí Iṣẹ́ Rẹ̀ Ṣí Payá, 12/8

O Ha Rí Ìbùyẹ̀rì Aláwọ̀ Ewéko Rí Bí? (Wíwọ̀ Oòrùn), 5/22

Rédíò—Ìhùmọ̀ Tó Yí Ayé Padà, 10/8

ÌSÌN

Àwọn Akọrin Tí A Tẹ̀ Lọ́dàá, 2/8

Àwọn Alárìnkiri àti Ìlàkàkà Wọn Láti Dòmìnira, 11/22

Àwùjọ Àlùfáà Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ha Wà Lójúfò Bí?, 9/8

Gbọ̀ngàn Àpéjọ àti Àsọtẹ́lẹ̀ Bibeli, 2/22

Ìbẹ̀wò Póòpù sí Àjọ UN, 7/8

Ìdí Tí Àwọn Ilé Ìjọsìn Fi Ń Kógbá Sílé (Wales), 9/8

Ìsìn Ha Já Mọ́ Nǹkan Kan Mọ́ Bí?, 4/8

Ìsìn Ha Ń Lọ Sópin Rẹ̀ Bí?, 11/8

Ìwọ́ Ha Ti Ṣe Kàyéfì Rí Bí? (Àlọ́ Bíbélì Nípa Màríà), 5/8

Kíkàn sí Ilẹ̀ Ọba Ẹ̀mí, 11/22

Kíkẹ́kọ̀ọ́ Bibeli—Nínú Ọgbà Ẹranko!, 3/8

Ǹjẹ́ O Mọyì Òmìnira Ìsìn Bí?, 4/22

Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ilẹ̀ Gíríìkì—Ó Pín Yẹ́lẹyẹ̀lẹ, 1/8

OJÚ-ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ààbò Àtọ̀runwá, 4/8

Àwọn UFO, 7/8

Ayẹyẹ Carnival, 6/8

Bí O Bá Ṣẹ Ẹlòmíràn, 2/8

Ìfẹ́ Tí Ń Soni Pọ̀, 10/8

Ìfìyà-Ikú-Jẹni, 3/8

Ijó Jíjó, 5/8

Ìtẹríba Aya, 12/8

Ìtọ́sọ́nà Ta Ni O Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé?, 11/8

Ìyọnilẹ́gbẹ́, 9/8

O Ha Ń Bẹ̀rù Òkú Bí?, 8/8

Ṣé “Ìyá Ọlọrun” Ni Maria?, 1/8

Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN

A Dá Wa Nídè Kúrò Nínú Lahar!, 5/22

Àwọn Òkè Ayọnáyèéfín—Ìwọ́ Ha Wà Nínú Ewu Bí?, 5/8

Bí O Ṣe Lè Ra Àlòkù Ọkọ̀, 4/8

Dáàbò Bo Ara Rẹ Lọ́wọ́ Mànàmáná!, 3/8

Fọ́tò, 11/8

Iná Mọ́ Àwọn Ilé Iṣẹ́ Tábà, 1/22

Ipò Wúńdíá—Èé Ṣe?, 8/22

Ìsinmi, 6/22

Kúbùsù Òtútù (Òjò Dídì), 2/8

Mú Agbára Ìrántí Rẹ Sunwọ̀n Sí I, 4/8

Músítádì—Kókó Ọ̀rọ̀ Gbígbóná Janjan, 8/8

100 Ọdún Sinimá, 7/22

Ṣọ́ra fún Ìmọ̀ọ́kàmáfẹ̀ẹ́kà, 1/22

Ta Ló Hùmọ̀ Táì Ọrùn?, 5/8

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́