Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kọkànlélọ́gọ́rin Ti Jí!
ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ
Àwọn Èèyàn Tí Wọ́n Dá Lóró, 1/8
Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá, 2/8
Èdè—Òun Ló Ń Ṣínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀, Òun Náà Ló Ń Dènà Rẹ̀, 8/8
Ẹ̀rín Músẹ́—Á Ṣe Ẹ́ Láǹfààní! 7/8
Ìpadàṣọ̀kan Ìdílé, 6/8
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Fi Ẹ̀dùn Ọkàn Hàn? 8/8
Títọ́ Àwọn Ọmọ Di Ẹni Tó Lẹ́kọ̀ọ́, 8/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
‘Ayé Yìí Ì Bá Yàtọ̀,’ 3/8
Ìfẹ́ Kristẹni Nígbà Tí Òkè Ayọnáyèéfín Bú Gbàù (Cameroon), 6/8
Ìgbàgbọ́ Tí Kò Yingin Nígbà Ìpọ́njú (P. Esch), 4/8
Ìrànwọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Ìpáǹle (Faransé), 9/8
Irin Iṣẹ́ Tí A Fi Ń Kọ́ni Ní Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn (Jí!), 4/8
Lẹ́yìn Ìjì Tó Jà (Faransé), 7/8
Òun Ló Gba Ẹ̀mí Rẹ̀ Là (Jí!), 12/8
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
Ẹyẹ Ń Kọ́ Ẹlẹ́wọ̀n Kẹ̀? 5/8
“Ẹyẹ Tó Lẹ́wà Jù Lọ Tó Ń Gbé Inú Igbó” (òwìwí Lapland), 9/8
Ìgbà Tí Ìfẹ́ Fọ́jú (ọba àfòpiná), 5/8
Ìrèké, 8/8
“Òkú” Tó Jíǹde (òdòdó), 10/8
Píà Avocado, 1/8
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Àwọn Ewu Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, 4/8
Àwọn Ìsáǹsá Bàbá Ọmọ, 6/8, 12/8
Èé Ṣe Tí Mo Fi Rí Tẹ́ẹ́rẹ́ Báyìí? 10/8
Fífi Ọ̀ranyàn Báni Tage, 9/8
Ìsoríkọ́, 11/8
Kéèyàn Bímọ, 5/8
Kí Ló Dé Táwọn Ọ̀rẹ́ Mi Fi Máa Ń Ṣe Nǹkan Tó Dùn Mí? 3/8
Ṣé Kí N Lọ Gbé Lókè Òkun? 7/8, 8/8
ÀWỌN Ọ̀RÀN ÀTI IPÒ AYÉ
“Àṣà Ká Máa Pààyàn,” 7/8
Àwọn Èèyàn Tí Wọ́n Dá Lóró, 1/8
Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá, 2/8
Ayé Tí A Mú Ṣọ̀kan—Ṣé Ilẹ̀ Yúróòpù Ló Ti Máa Bẹ̀rẹ̀ Ni? 5/8
Gbígbẹ̀mí Ara Ẹni, 3/8
Ìfiniṣẹrú Lóde Òní, 3/8
Ìgbìyànjú Láti Yọ Ìjọba Póòpù Kúrò Nínú Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè, 11/8
Ìpolongo Èké, 10/8
Ìṣòro Àwọn Ọmọdé, 12/8
Ìwà Ọmọlúwàbí Dà? 4/8
Ìyàtọ̀ Tó Wà Láàárín Ọlọ́rọ̀ àti Tálákà, 3/8
Jíjí Èèyàn Gbé Ti Di Òwò Tó Kárí Ayé, 1/8
Ọ̀tọ̀ Làwọn Tó Ń Bógun Lọ Lóde Òní, 2/8
Ṣé Ẹ̀mí Èèyàn Kò Jẹ́ Nǹkan Kan Mọ́ Ni? 7/8
ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́
Ibo Lọ̀ràn “Iṣẹ́ Àfìgbésí Ayé Ẹni Ṣe” Ń Lọ Báyìí? 10/8
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àjàkálẹ̀ Àrùn Black Death, 2/8
Àrùn Éèdì ní Áfíríkà, 5/8
Àwọn Ìlànà Ìtọ́jú Àfirọ́pò, 11/8
Àwọn Ìyá Tó Ní Àrùn Éèdì, 1/8
Àwọn Nọ́ọ̀sì, 11/8
Báa Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Sìgá Mímu, 4/8
Bí Àwọn Ìdílé Ṣe Lè Kojú Ìṣòro Àìsàn Bára Kú, 6/8
Ẹsẹ̀ Rírinni Wìnnìwìnnì, 12/8
Ilé Elégbòogi Kan ní China, 11/8
Iṣẹ́ Abẹ́ Láìlo Ẹ̀jẹ̀—Àpẹẹrẹ Kan Tó Yọrí sí Rere, 9/8
Ìtọ́jú àti Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀, 1/8
Oògùn Aspirin Lójoojúmọ́, 7/8
“Wàá Kàn Kú Dànù Ní!” (ọ̀ràn ẹ̀jẹ̀), 5/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Àràmàǹdà Itẹ́ Òkú (Ecuador), 3/8
Àrùn Éèdì ní Áfíríkà, 5/8
Àwọn Òkè Aboríṣóńṣó-Bìdírẹ̀kẹ̀tẹ̀ ní Mẹ́síkò, 10/8
Àwọn Olùgbé Inú Hòrò Lóde Òní (Lesotho), 6/8
Ilé Elégbòogi Kan ní China, 11/8
“Ìlú Tọ́jọ́ Rẹ̀ Pẹ́ Jù Lọ ní Rọ́ṣíà” (Novgorod), 9/8
Ìsẹ̀lẹ̀! (Taiwan), 9/8
Ìtàn Odò Méjì (Ganges àti Indus), 7/8
Òkè Ayọnáyèéfín, Di Erékùṣù Tó Pa Rọ́rọ́ (Santorini, ilẹ̀ Gíríìsì), 9/8
Òmìnira Ẹ̀rí-Ọkàn (Mẹ́síkò), 3/8
Pátímọ́sì—Erékùṣù Àpókálíìsì, 8/8
Sísọ Igbó Amazon Dọ̀tun, 12/8
ÌSÌN
Bíbá Ẹ̀mí Lò—Ṣé Ó Ń Ranni Lọ́wọ́ Ni Tàbí Ó Ń Pani Lára? 8/8
Kò Gbàgbé Orin Náà (Orúkọ Jèhófà), 3/8
Ríríran Ré Kọjá Ohun Tó Hàn sí Ojúyòójú, 9/8
Wọ́n Ti Gbà Báyìí Pé Àwọn Ò Gba Ẹ̀sìn Míì Láyè (ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì), 4/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Bí Loida Ṣe Di Ẹni Tó Ń Sọ̀rọ̀, 9/8
Bí Mo Ṣe Sapá Láti Ṣe Yíyàn Tó Bọ́gbọ́n Mu (G. Sisson), 9/8
Ìdánwò Ìgbàgbọ́ ní Poland (J. Ferenc), 12/8
“Ìjà Ogun Náà Kì Í Ṣe Tiyín, Bí Kò Ṣe Ti Ọlọ́run” (W. G. How), 5/8
Ìrètí Ló Ń Fún Mi Lókun Láti Fara Da Àwọn Àdánwò (M. Ogawa), 2/8
Jíjẹ́ Adúróṣinṣin Lolórí Àníyàn Mi (A. Davidjuk), 10/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Àṣàrò Tó Ṣàǹfààní, 9/8
Àwọn Àṣà Olókìkí, 1/8
Bí A Ṣe Lè Kápá Àìnírètí, 5/8
“Eré Ìdárayá Àṣejù,” 10/8
Ìgbàgbọ́ Tòótọ́—Kí Ló Jẹ́? 3/8
Irọ́ Pípa—Ǹjẹ́ Àwíjàre Kankan Wà fún Un? 2/8
Ǹjẹ́ Ó Tọ̀nà Láti Máa Jọ́sìn Jésù? 4/8
Ǹjẹ́ Sáyẹ́ǹsì Lè Mú Ìyè Àìnípẹ̀kun Wá? 12/8
Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Yí Padà? 6/8
Ṣíṣe Ara Lọ́ṣọ̀ọ́, 8/8
Ta Ni Òjíṣẹ́? 7/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Àwọn Ewu Tó Wà Nínú Wíwọkọ̀ Ọ̀fẹ́ Kiri, 7/8
Fífárùngbọ̀n, 1/22
Ìròyìn Orí Tẹlifíṣọ̀n, 5/8
Lílo Àkàbà, Àyẹ̀wò Tó Lè Dáàbò Bò Ẹ́, 2/8
Lílo Tẹlifíṣọ̀n Tìṣọ́ratìṣọ́ra, 6/8
Ǹjẹ́ Ó Ti Tó Àkókò Láti Ní Bẹ́ẹ̀dì Tuntun? 8/8
Ǹjẹ́ O Mọ̀?, 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8
Ṣé Òṣùpá Ló Ń Darí Ayé Rẹ? 6/8
SÁYẸ́ǸSÌ
Ǹjẹ́ Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Bọ́gbọ́n Mu? 6/8
Ríríran Ré Kọjá Ohun Tó Hàn sí Ojúyòójú, 9/8
Wọ́n Gbé Òtítọ́ Pa Mọ́ fún Àádọ́ta Ọdún (ìmọ̀ nípa ewéko), 8/8