ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g20 No. 1 ojú ìwé 16
  • “Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”
  • Jí!—2020
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ÀWỌN TỌKỌTAYA
  • ÀWỌN ÒBÍ
  • ÀWỌN Ọ̀DỌ́
  • Ṣó O Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I?
    Jí!—2021
  • Ìbànújẹ́ Túbọ̀ Ń Dorí Ọ̀pọ̀ Àwọn Ọ̀dọ́ Kodò​—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Kíyè Sára Tó Bá Ń Lo Íńtánẹ́ẹ̀tì
    Jí!—2014
  • Ìwà Àpọ́nlé Ti Dàwátì Nínú Ọ̀pọ̀ Ìdílé!
    Jí!—2024
Àwọn Míì
Jí!—2020
g20 No. 1 ojú ìwé 16

“Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń mú Kí Ara Lókun”

Tọkọtaya kan ń kàwé lórí tablet wọn.

Inú Òwe 14:30 ni ọ̀rọ̀ yìí wà, wọ́n sì ti kọ ọ́ ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ọdún sẹ́yìn! Ó jẹ́ ara ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wúlò nígbà gbogbo tó wà nínú Bíbélì. Tó o bá fẹ́ mọ púpọ̀ sí i, lọ wo ìkànnì jw.org. Wàá rí àwọn fídíò, eré bèbí, ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àtàwọn àpilẹ̀kọ tó dá lé oríṣiríṣi ẹ̀kọ́ tó lè ranni lọ́wọ́, títí kan béèyàn ṣe lè ní ìbàlẹ̀ ọkàn. Àwọn àpẹẹrẹ kan ló wà nísàlẹ̀ yìí:

ÀWỌN TỌKỌTAYA

  • Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Yanjú Ọ̀rọ̀

  • Bí Ẹ Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Láàárín Ẹ̀yin Àtàwọn Mọ̀lẹ́bí Yín

  • Bó O Ṣe Lè Dárí Ji Ọkọ Tàbí Aya Rẹ

ÀWỌN ÒBÍ

  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀

  • Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Nǹkan Bá Tojú Sú Ọmọ Rẹ Obìnrin

  • Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Kíyè Sára Tó Bá Ń Lo Íńtánẹ́ẹ̀tì

ÀWỌN Ọ̀DỌ́

  • Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láìbá A Jà

  • Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí N Lè Máa Sùn Dáadáa?

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Jẹ́ Kí Àlàáfíà Máa Wà Láàárín Èmi àti Àbúrò Tàbí Ẹ̀gbọ́n Mi?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́