“Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”
ÒWÚRỌ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 9 àti Àdúrà
10:00 “Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà, Kí Inú Yín sì Máa Dùn”
10:15 O Lè Láyọ̀ Bó O Tiẹ̀ Ní Ìṣòro
10:30 Ẹ Máa Ní ‘Ìdùnnú Tó Kún Rẹ́rẹ́’ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
10:55 Orin 76 àti Ìfilọ̀
11:05 Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun “Di Ẹrù Pa” Ọkàn Yín
11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 Orin 51