Ìdílé Jèhófà Tó Wà Níṣọ̀kan
Àárọ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 85 àti Àdúrà
9:50 Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Wà Nínú Ìdílé Jèhófà
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Mára Tu Àwọn Míì
• Élíhù
• Lìdíà
• Jésù
11:05 Orin 100 àti Ìfilọ̀
11:15 Máa Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Di Ara Ìdílé Jèhófà
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 135
Ọ̀sán
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 132 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ṣé Ayọ̀ àti Àlàáfíà Wà Nínú Ìdílé Rẹ?
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 136 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Wà
• Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró”
• “Máa Rìn Nínú Ìfẹ́”
• Má Ṣe Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Wa Dẹkùn Mú Ẹ
3:40 ‘Máa Dúpẹ́ Nígbà Gbogbo’ Nítorí Ìdílé Wa Nípa Tẹ̀mí
4:15 Orin 107 àti Àdúrà