ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CA-copgm24 ojú ìwé 1-3
  • ‘Máa Retí Jèhófà’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Máa Retí Jèhófà’
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024 Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́”!
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2021-2022—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Ìdílé Jèhófà Tó Wà Níṣọ̀kan
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2022-2023—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024 Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
CA-copgm24 ojú ìwé 1-3

‘Máa Retí Jèhófà’

SÁÀMÙ 130:6

Àárọ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 88 àti Àdúrà

  • 9:50 Báwo La Ṣe Lè Máa “Retí Jèhófà”?

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fara Wé Àwọn Tó Retí Jèhófà

    • • Hábákúkù

    • • Jòhánù

    • • Ánà

  • 11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Kí Ló Ń Dá Ẹ Dúró Láti Ṣe Púpọ̀ Sí I?

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 28

Ọ̀sán

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 54 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Pé Ká Ní Sùúrù?

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 143 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Retí Jèhófà . . .

    • • Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Dá Wà

    • • Tó O Bá Ṣàṣìṣe

    • • Tí Nǹkan Bá Ń Lọ Dáadáa Fáwọn Ẹni Burúkú

  • 3:40 “Èrè Wà fún Olódodo”

  • 4:15 Orin 140 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́