Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
1. Irú àwọn èèyàn wo ni Jèhófà ń wá? (Jòh. 4:23, 24)
2. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ ká lè ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà? (Ìṣe 16:6-10; 1 Kọ́r. 2:10-13; Fílí. 4:8, 9)
3. Báwo la ṣe lè máa “fi òtítọ́ hàn kedere”? (2 Kọ́r. 4:1, 2)
4. Kí ló túmọ̀ sí láti jọ́sìn Jèhófà ní òtítọ́? (Òwe 24:3; Jòh. 18:36, 37; Éfé. 5:33; Héb. 13:5, 6, 18)
5. Báwo la ṣe lè ‘ra òtítọ́ ká má sì tà á’? (Òwe 23:23)
© 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-copgm26-YR