“Máa Jọ́sìn Ní Ẹ̀mí àti Òtítọ́”
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 85 àti Àdúrà
10:00 “Irú Àwọn Ẹni Yìí Ni Baba Ń Wá”
10:15 Àpínsọ Àsọyé: “Máa Jọ́sìn Ní Ẹ̀mí”
• Tó O Bá Fẹ́ Lóye Ìtọ́sọ́nà Jèhófà
• Tó O Bá Rẹ̀wẹ̀sì
• Tó O Bá Fẹ́ Ṣe Púpọ̀ Sí I
11:05 Orin 88 àti Ìfilọ̀
11:15 Bá A Ṣe Ń “Fi Òtítọ́ Hàn Kedere”
11:35 Ìrìbọmi: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi?
12:05 Orin 51
Ọ̀sán
1:20 Ohùn Orin
1:30 Orin 72 àti Àdúrà
1:35 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìyàtọ̀ Láàárín Ohun Tó Tọ́ Àtohun Tí Kò Tọ́?
2:05 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:35 Orin 56 àti Ìfilọ̀
2:45 Àpínsọ Àsọyé: “Máa Jọ́sìn Ní . . . Òtítọ́”
• Nínú Ìdílé
• Nínú Ayé Táwọn Èèyàn Ò Ti Wà Níṣọ̀kan
• Nígbà Tí Nǹkan Bá Le
3:30 “Ra Òtítọ́, Má sì Tà Á”
4:00 Orin 29 àti Àdúrà