“Ẹ Máa Hùwà Lọ́nà Tó Yẹ Ìhìn Rere”
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 35 àti Àdúrà
10:00 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Jẹ́ Kí Ayé Wa Dáa Sí I?
10:15 Àpínsọ Àsọyé: Ohun Tí Ìhìn Rere Mú Kí Wọ́n Ṣe
• Sítéfánù
• Fílípì
• Ákúílà àti Pírísílà
• Títù
11:05 Orin 76 àti Ìfilọ̀
11:15 Máa Tẹ̀ Síwájú Lẹ́nu “Iṣẹ́ Ìfọkànsin Ọlọ́run”
11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere”
12:05 Orin 37
Ọ̀sán
1:20 Ohùn Orin
1:30 Orin 56 àti Àdúrà
1:35 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Ló Mú Kó O Gbà Pé Òótọ́ Lohun Tó O Gbà Gbọ́?
2:05 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:35 Orin 24 àti Ìfilọ̀
2:45 Àpínsọ Àsọyé: “À Ń Dámọ̀ràn Ara Wa Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run . . . ”
• Tá A Bá Ní Ìfaradà
• Tá A Bá Jẹ́ Onínúure
• Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́
3:30 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Kọ́ Wa?
4:00 Orin 29 àti Àdúrà