Atọ́ka Àwọn Kókó-Ẹ̀kọ́ Fún Ilé-Ìṣọ́nà 1994
Tí ń tọ́ka ọjọ́ ìtẹ̀jáde nínú èyí tí ọ̀rọ̀-ẹ̀kọ́ farahàn
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JEHOFA
Àgbègbè Tí Kò fi Bẹ́ẹ̀ Lajú ní Alaska, 4/15
Alákòókò Kan Náà fún Ọdún Mẹ́wàá! 4/1
Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá,” 1/15, 7/1, 8/15
Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ìbẹ̀rù Ọlọrun,” 5/1
Àwọn Aṣáájú-Ọ̀nà Ń Fìbùkún Jíǹkí Ẹni Wọ́n Sì Ń Rí I Gbà, 1/15
“Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa Dáàbòbò Mí!” 5/15
‘Àwọn Ìṣe Rẹ̀ Ń Tọ̀ Ọ́ Lẹ́yìn’ (G. Gangas), 12/1
Àwọn Olùwá-Ibi-Ìsádi Láyọ̀ Láti Máa Ṣiṣẹ́sin Ọlọrun (Central African Republic), 10/15
Àwọn Ọ̀dọ́ tí Wọ́n ‘Gbẹ́kẹ̀lé Jehofa,’ 1/1
Bahamas, 3/15
Colombia, 7/15
Èéṣe tí Àwọn Ẹlẹ́rìí fi Ń Ṣèbẹ̀wò Lemọ́lemọ́? 8/15
Èmi ti Pa Ìgbàgbọ́ Mọ́” (B. Inconditi), 7/1
Ethiopia, 8/15
Ẹgbẹ́ Awo Tàbí Òjíṣẹ́ Ọlọrun? 2/15
“Ẹja Pípa” Nínú Àwọn Omi Fiji, 6/15
Fífi Ìmọrírì Wo “Ilé Ọlọrun” (Beteli), 6/15
Ìgbàgbọ́ Onígboyà ti Àwọn Ará ní Rwanda, 11/1
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Gileadi, 6/1, 12/1
Ìlà-Oòrùn Pàdé Ìwọ̀-Oòrùn, 1/1
Ìlú Aláààrẹ ti Philippines, 1/15
Malawi, 5/15
Nigeria, 9/15
Ọ̀ràn Ìbànújẹ́ ní Rwanda, 12/15
Poland, 11/15
Ṣíṣèrànwọ́ fún Àwọn Onígbàgbọ́ ní Bosnia, 11/1
Thailand, 5/15
ÀWỌN ÌTÀN ÌGBÉSÍ-AYÉ
Aṣálẹ̀ kan Di Ilẹ̀ Ẹlẹ́tùlójú (A. Melin), 10/1
A ti Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́ (O. Springate), 2/1
Ìgbésí-Ayé Dídọ́ṣọ̀, Elérè-Ẹ̀san, Nínú Iṣẹ́-Ìsìn Jehofa (L. Kallio), 4/1
Mo Láyọ̀ Ninu Ojúlówó Ẹgbẹ́-Àwọn-Ará Kárí-Ayé (W. Davis), 9/1
Mo Rí Ìṣúra tí Ìníyelórí Rẹ̀ Tayọlọ́lá (F. Widdowson), 1/1
Ọlọrun náà tí Kò Lè Ṣèké Tì Mí Lẹ́yìn (M. Willis), 5/1
Ọ̀nà Ìgbésí-Ayé kan tí Ó Ní Ète Nínú (M. Wieland), 12/1
‘Ọwọ́ Jehofa’ Nínú Ìgbésí-Ayé Mi (L. Thompson), 3/1
Ṣíṣiṣẹ́sìn Pẹ̀lú Ètò-Àjọ tí Ń Tẹ̀síwájú Jùlọ (R. Hatzfeld), 8/1
Wọ́n Fi Àpẹẹrẹ Lélẹ̀ fún Wa (C. Zanker), 6/1
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 8/1, 9/1, 10/1
BIBELI
Bibeli Lédè Goth, 5/15
‘Ewé Ìwé Kanṣoṣo Lè Jáwọ Inú Òkùnkùn Lọ Bí Ìràwọ̀,’ 5/15
Ìníyelórí Rẹ̀ Gidi, 10/1
Ìwé kan tí A Níláti Kà, 5/15
Ìwọ Ha Mọyì Bibeli Bí? 5/15
Ó Yẹ Kí A Lóye Rẹ̀, 10/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn ọmọ-ogun Saulu tí wọ́n jẹ ẹran tẹ̀jẹ̀tẹ̀jẹ̀, 4/15
Déètì fún “ìgbà mẹ́ta àti ààbọ̀” (Ìfi 11:3), 8/1
“Ẹ̀ṣẹ̀ ba ní ẹnu ọ̀nà” (Gen 4:7), 2/1
Gbólóhùn náà “tajúkán rí,” 10/15
Jesu “gbòǹgbò” Jesse àti Dafidi, 8/15
Ó ha yẹ láti gba omi-abẹ́rẹ́ albumin tí ó ti inú ẹ̀jẹ̀ wá? 10/1
“Ọmọdékùnrin aláìníbaba” ha fi ìdàníyàn tí ó dínkù fún àwọn ọmọdébìnrin hàn bí? 1/15
Pípẹjọ́ fún ìwọkogbèsè, 9/15
ÌGBÉSÍ-AYÉ ÀTI ÀWỌN ÀNÍMỌ́ KRISTIAN
Àkójọ-Ìwé ti Ìṣàkóso Ọlọrun, 11/1
Àyẹ̀wò Ìlera, 12/15
Báwo Ni Ìwọ Ṣe Ń Yanjú Aáwọ̀? 7/15
Buyì fún Àwọn Ẹlòmíràn Nígbà Tí O Bá Ń Fún Wọn Nímọ̀ràn, 2/1
Èéṣe tí A Fi Níláti Máa Dáríjini? 9/15
Fífi Ìfẹ́ Kristian Hàn sí Àwọn Àgbàlagbà, 8/1
Ìdákẹ́kọ̀ọ́, 6/15
Ìdíje Ha Ni Kọ́kọ́rọ́ náà sí Àṣeyọrísírere Bí? 3/1
Ìkálọ́wọ́kò Ha Ń Mú Ọ Rẹ̀wẹ̀sì Bí? 9/1
Ìkanisí—Olórí Àìní Ẹ̀dá Ènìyàn, 12/1
Ìwọ Ha Ń Ṣe Ìfẹ́-Inú Ọlọrun Bí? 3/1
Kíkojú Àárò Ilé, 5/15
Mọrírì Iṣẹ́-Ìsìn Mímọ́ Ọlọ́wọ̀ Rẹ, 9/1
Olè Jíjà Ha Ni Nítòótọ́ Bí? 4/15
Orísun Ìgboyà tí Kìí Ṣákìí, 9/15
Owó-Orí, 11/15
Pípa Ìṣọ̀kan Mọ́ Láàárín Àwọn Alàgbà àti Ìránṣẹ́ Iṣẹ́-Òjíṣẹ́, 8/15
Ríran Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Lati Yan Jehofa, 10/1
Sùúrù, 5/15
Ṣọ́ra fún Fífọ́nnu, 9/1
Takété Nígbà Tí Ewu Bá Fẹjúmọ́ Ọ, 2/15
Wọ́n Pinnu Láti Ṣiṣẹ́sin Jehofa! 4/15
JEHOFA
Àkọlé tí Ó Ní Ìtumọ̀ Àrà-Ọ̀tọ̀, 8/15
Kíkẹ́kọ̀ọ́ Lati Ọ̀dọ̀ Atóbilọ́lá Olùkọ́ni Wa, 9/15
JESU KRISTI
Jesu Ha Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọrun Bí? 10/15
O Ha Níláti Gbàdúrà sí Jesu Bí? 12/15
“Oluwa”—Báwo àti Nígbà Wo? 6/1
LÁJORÍ ÀWỌN Ọ̀RỌ̀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Níláti Kọ́kọ́ Wàásù Ìhìnrere Yìí, 8/15
Àríyànjiyàn Jehofa Pẹ̀lú Àwọn Orílẹ̀-Èdè, 3/1
Awọn Ìránṣẹ́ Ọlọrun—Awọn Ènìyàn Aláyọ̀ tí Wọ́n Wà Létòlétò, 10/1
Àwọn Olùpòkìkí Ìjọba Jẹ́ Aláápọn ní Gbogbo Ilẹ̀-Ayé, 5/1
Àwọn Olùṣọ́-Àgùtàn àti Àwọn Àgùtàn Nínú Ìṣàkóso Ọlọrun, 1/15
Bí Ó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Erùpẹ̀ Ni Wá, Ẹ Jẹ́ Kí A Máa Tẹ̀síwájú! 9/1
Èrè Jobu—Orísun Kan Fún Ìrètí, 11/15
Ẹ̀kọ́ Arannilọ́wọ́ fún Àwọn Àkókò Lílekoko Wa, 4/15
Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá ní Ìdojú Ìjà Kọ Ẹ̀kọ́ Àwọn Ẹ̀mí Èṣù, 4/1
Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá Ṣẹ́gun, 2/1
Ẹ Kó Gbogbo Àníyàn Yín Lé Jehofa, 11/15
Ẹ Kọrin Ìyìn sí Jehofa, 5/1
Ẹ Máa Ṣe Ìpolongo Ní Gbangba sí Orúkọ Jehofa, 9/15
Ẹ Máa Yọ̀ Ninu Jehofa! 9/1
Ẹ Mú Awọn Wòlíì Ọlọrun Gẹ́gẹ́ Bí Àpẹẹrẹ Àwòṣe, 9/15
Ẹ Mú Ìfòyebánilò Dàgbà, 8/1
Ẹ Ní Ìyọ́nú Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́, 11/1
Ẹrù-Iṣẹ́ Ń Bá Mímọ Ìsìn tí Ó Tọ̀nà Rìn, 6/1
‘Ẹ Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Nípasẹ̀ Ọrọ̀ Àìṣòdodo,’ 12/1
Ẹ̀yin Èwe—Ẹ̀kọ́ Ta Ni Ẹ Ń Kọbiara Sí? 5/15
Ẹ̀yin Òbí, Àwọn Ọmọ Yín Nílò Àfiyèsí Àrà-Ọ̀tọ̀, 5/15
Fi Jehofa Ṣe Ààbò-Ìsádi, 1/1
Fífayọ̀ Tẹríba fún Ọlá-Àṣẹ, 7/1
Fífi Ìfẹ́ Ṣe Olùṣọ́ Àgùtàn Agbo Ọlọrun, 10/1
Gbádùn Àwọn Àǹfààní Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá, 2/1
Gbígbógunti Ìwàmú Ẹ̀ṣẹ̀ Lórí Ẹran-Ara Ẹlẹ́ṣẹ̀, 6/15
Ìdájọ́ Jehofa Lòdìsí Àwọn Olùkọ́ni Èké, 3/1
Ìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa Fi Ń Báa Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà, 5/1
Ilé-Ìṣọ́nà àti Jí!—Àwọn Àkànṣe Ìwé-Ìròyìn Òtítọ́ Bíbọ́sákòókò, 1/1
Ipò Pàtàkì tí Ó Yẹ Ìjọsìn Jehofa Nínú Ìgbésí-Ayé Wa, 12/1
Ìṣùpọ̀-Èso—Dídára àti Búburú, 3/1
Ìwọ Ha Ń Dáríjini Bí Jehofa ti Ń Ṣe Bí? 10/15
Ìwọ Ha Ń Gbéjàko Ẹ̀mí Ayé Bí? 4/1
Ìwọ Ha Ń Kọ́ni Bí Jesu Ti Ṣe Bí? 10/15
Ìwọ Ha Ti Rí Ìsìn tí Ó Tọ̀nà Bí? 6/1
Jehofa—Bàbá Wa Oníyọ̀ọ́nú Lọ́nà Jẹ̀lẹ́ńkẹ́, 11/1
Jehofa Lè Sọ Ọ́ Di Alágbára, 12/15
Jehofa Ń Fòyebánilò! 8/1
Jehofa Ń Ṣàkóso—Nípasẹ̀ Ìṣàkóso Ọlọrun, 1/15
Jehofa—Ọlọrun Ète, 3/15
Jíjẹ́rìí fún “Gbogbo Awọn Orílẹ̀-Èdè,” 8/15
Jobu Lo Ìfaradà—Àwa Pẹ̀lú Lè Ṣe Bẹ́ẹ̀! 11/15
‘Kí Ni Yóò Ṣe Àmì Wíwàníhìn-ín Rẹ?’ 2/15
Lórí Tábìlì Wo Ni Ìwọ ti Ń Jẹun? 7/1
Mú Kí Ìgbéyàwó Rẹ Jẹ́ Ìsopọ̀ Wíwàpẹ́títí, 7/15
Ní Ìgbẹ́kẹ̀lé Pé Jehofa Yóò Mú Ète Rẹ̀ Ṣẹ, 3/15
Ojú-Ìwòye Kristian Nípa Ọlá-Àṣẹ, 7/1
Rìn Ní Ìbámu Pẹ̀lú Ìtọ́ni Ọlọrun, 4/15
Sọ Ẹ̀kọ́ Afúnninílera Di Ọ̀nà Ìgbésí-Ayé Rẹ, 6/15
“Sọ Fún Wa, Nígbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹ?” 2/15
Ṣiṣẹ́ Kára fún Ìgbàlà Agbo-Ilé Rẹ, 7/15
Wọ́n Wà Ní Ìṣọ̀kan Nínú Ìdè Ìfẹ́ Pípé, 12/15
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Abrahamu—A Sin Ín Síhìn-ín, Síbẹ̀ Ó Wàláàyè Kẹ̀? 6/15
Àìgbàgbọ́ Nínú Wíwà Ọlọrun, 12/1
A San Èrè-Ẹ̀san fún Wọn fún Rírìn Láìlẹ́bi (Sekariah, Elisabeti), 7/15
Àwọn Ẹgbẹ́ Awo—Kí Ni Wọ́n Jẹ́? 2/15
Àwọn Ẹ̀mí Búburú, 2/1
Àwọn Ìwé Ìtàn Fífanimọ́ra ti Josephus, 3/15
Àwọn Òkú Ha Lè Pa Àwọn Alààyè Lára Bí? 10/15
Àwọn Òkú Ha Ń Rí Wa Bí? 11/15
Àwọn Olólùfẹ́ tí Wọ́n Ti Kú—A Ha Tún Lè Rí Wọn Bí? 6/15
Ayé Dídára Jù Kan—Àlá kan Lásán Ha Ni Bí? 4/1
Àyẹ̀wò Ìlera, 12/15
Ayẹyẹ Ọjọ́-Ìbí, 7/15
Báwo Ni Ènìyàn Ṣe Lè Jẹ́ Ní Àwòrán Ọlọrun? 4/1
‘Bọ́ Ẹnu, Kìí Ṣe Ẹsẹ̀’ (àṣà ìsìnkú àtọwọ́dọ́wọ́ Africa), 3/15
Ẹfolúṣọ̀n Ń Jẹ́jọ́, 9/1
Ìbẹ̀rù Gbá Aráyé Mú, 7/15
Ibojì Peteru—Ní Vatican Kẹ̀? 10/15
Ìdánìkanwà, 9/15
Ìgbàgbọ́ Aláìjampata ti Ìgbàsókè-Ọ̀run, 2/15
Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Gíga Jùlọ ti Àwọn Ìsìn Àgbáyé, 2/1
Ìjìyà Ẹ̀dá Ènìyàn—Ìdí Tí Ọlọrun Fi Fàyègbà Á, 11/1
Ìmọ̀-Ìjìnlẹ̀, Ìsìn, ati Wíwá Òtítọ́ Kiri, 9/1
Ìrètí fún Àwọn Afọ́jú, 8/15
Ìrọ̀dẹ̀dẹ̀ Ewu Agbára Átọ́míìkì, 8/1
Ìsìn Ha Ń Kúnjú Àwọn Àìní Rẹ Bí? 5/1
Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìbànújẹ́ ní Rwanda, 12/15
Ìtọ́sọ́nà Tí Ó Ṣeé Gbáralé, 4/15
Ìwákiri fún Ìsìn Tí Ó Tọ̀nà, 6/1
Jehofa Ṣe Ojúrere sí I Lọ́nà Gíga (Maria), 11/15
Kàlẹ́ńdà Àwọn Ju, 7/15
Keresimesi—Ó Ha Bá Ìsìn Kristian Mú Nítòótọ́ Bí? 12/15
Kí Ni Ó Ti Ṣẹlẹ̀ sí Ọlá-Àṣẹ? 7/1
Kò Dàgbà Jù Láti Ṣiṣẹ́sin Jehofa (Anna), 5/15
“Kọ̀ Láti Gba Àwọn Ìtàn Èké,” 4/1
Lílajú sí Ìhìnrere, 8/15
Níbo Ni Àwọn Òkú Wà? 11/15
Ogun Yóò Ha Dópin Láé Bí? 1/15
Ó Rí Ìmúṣẹ Ìfẹ́-Ọkàn Rẹ̀ (Simeoni), 3/15
Oúnjẹ Alẹ́ Oluwa—Báwo Ni A Ṣe Níláti Ṣe É Lemọ́lemọ́ Tó? 3/15
Ṣọ́ọ̀ṣì kan tí Ìyapa Wà—Ó Ha Lè Làájá Bí? 7/1
William Whiston—Aládàámọ̀ Tàbí Ọ̀mọ̀wèé Akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ Aláìlábòsí? 3/15
“Wọ́n Mọ Ohùn Rẹ̀,” 7/15