ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w04 12/15 ojú ìwé 31
  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2004

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2004
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
  • BÍBÉLÌ
  • ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
  • ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
  • ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
  • JÈHÓFÀ
  • JÉSÙ KRISTI
  • KÀLẸ́ŃDÀ
  • LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
w04 12/15 ojú ìwé 31

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2004

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Fi Ògo fún Ọlọ́run,” 1/15

“Àwọn Ẹni Ìgbàgbé” Ti Wá Di Ẹni Ìrántí, 9/1

Àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ Mẹ́síkò, 8/15

Àwọn Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run Làwọn Erékùṣù Tonga, 12/15

Àwọn Tó Dúró Ṣinṣin Tí Wọn Ò Bọ́hùn (Poland), 10/15

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 6/15, 12/15

Ayọ̀ Tó Wà Nínú Ṣíṣètọrẹ, 11/1

Ẹ̀rí Ọkàn Tó Dára (fóònù alágbèérìn tí wọ́n dá padà), 2/1

‘Ẹ Wá, Kí Ẹ sì Ràn Wá Lọ́wọ́’ (Bolivia), 6/1

Kì Í Ṣe Eré Lásán (àwọn ọmọdé), 10/1

Lẹ́tà Tí Alejandra Kọ (Mẹ́síkò), 10/1

Liberia, 4/1

Lílọ Wàásù Fáwọn Èèyàn Níbi Iṣẹ́ Wọn, 4/1

Ó Bá Àwọn Ọmọ Kíláàsì Rẹ̀ Sọ̀rọ̀ Nípa Ẹ̀sìn Rẹ̀ (Poland), 10/1

‘O Kọ́ Wa Láti Ṣe Ohun Tó Bá Ìgbàgbọ́ Rẹ̀ Mu’ (Ítálì), 6/15

Ṣíṣe Oore Fáwọn Èèyàn Lákòókò Ìṣòro, 6/1

Wíwàásù Láìjẹ́-Bí-Àṣà Fáwọn Tó Ń Sọ Èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Mẹ́síkò, 4/15

Wọ́n Ń Gbèrú, 3/1

Wọ́n Pé Jọ sí ‘Agbedeméjì Ayé’ (Erékùṣù Easter), 2/15

BÍBÉLÌ

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì—Apá Kìíní, 1/1

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì—Apá Kejì, 1/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ẹ́kísódù, 3/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Léfítíkù, 5/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Númérì, 8/1

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Diutarónómì, 9/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóṣúà, 12/1

Bíbélì Elédè Púpọ̀ ti Complutensian, 4/15

Bíbélì Tí Ò “Láfiwé” (Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Gẹ̀ẹ́sì), 12/1

Ìṣúra Chester Beatty, 9/15

Onígboyà “Tó Lọ Káàkiri Nítorí Ìhìn Rere” (G. Borrow), 8/15

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

Àjẹkì, 11/1

“Aláìgbàgbọ́” (2Kọ 6:14), 7/1

Àwọn ẹ̀mí èṣù nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún, 11/15

Báwo la ṣe lè kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́? (Ef 4:30), 5/15

Báwo ni Hánámélì ṣe wá ta pápá fún Jeremáyà? (Jer 32:7), 3/1

‘Ẹ máa wínni láìretí ohunkóhun padà’ (Lk 6:35), 10/15

Ibo ni ẹyẹ àdàbà ti rí ewé ólífì? (Jẹ 8:11), 2/15

Ìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì láti fẹ́ obìnrin tí wọ́n mú lóǹdè, 9/15

Ìdí tí Jésù fi jẹ́ kí Tọ́másì fọwọ́ kan òun àmọ́ tí ò gbà kí Màríà Magidalénì ṣe bẹ́ẹ̀, 12/1

“Ìfẹ́ pípé” (1Jo 4:18), 10/1

Ìpín kékeré tá a mú jáde látinú ẹ̀jẹ̀, 6/15

Kí ló ṣẹlẹ̀, ta sì ni ẹ̀mí rẹ̀ wà nínú ewu? (Ẹk 4:24-26), 3/15

Kí nìdí tí Júdà fi bá obìnrin tó kà sí aṣẹ́wó lò pọ̀? (Jẹ 38:15), 1/15

Kí nìdí tí Míkálì fi ní ère Tẹ́ráfímù? (1Sa 19:13), 6/1

Ohun tí ọdún Júbílì ṣàpẹẹrẹ, 7/15

‘Sátánì ti já bọ́ láti ọ̀run’ (Lk 10:18), 8/1

Ṣé erékùṣù Málítà ni ọkọ̀ ti ri Pọ́ọ̀lù? 8/15

Ṣé ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ló ṣubú ni àbí ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún? (1Kọ 10:8; Nu 25:9), 4/1

Ṣe iye gidi ni ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì? 9/1

Ṣé ràkúnmí gidi àti abẹ́rẹ́ ìránṣọ ni? (Mt 19:24; Mk 10:25; Lk 18:25), 5/15

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Ábúráhámù àti Sárà—O Lè Fara Wé Ìgbàgbọ́ Wọn! 5/15

“Afọgbọ́nhùwà Yóò Fi Ìmọ̀ Hùwà” (Òwe orí 13), 7/15

“Àgọ́ Àwọn Adúróṣánṣán Yóò Gbilẹ̀” (Òwe orí 14), 11/15

Àwọn Ohun Tó Ò Ń Lé Nípa Tẹ̀mí, 7/15

Bá A Ṣe Ń Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, 3/1

Ẹ̀mí Ìdúródeni, 10/1

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Jẹ́ Káwọn Òbí Yín Ràn Yín Lọ́wọ́ Kẹ́ Ẹ Lè Dáàbò Bo Ọkàn Yín! 10/15

Ìlànà Ta Ló Yẹ Kó O Tẹ̀ Lé Láti Ṣe Ohun Tó Tọ́? 12/1

Ìtùnú fún Àwọn Tó Wà Nínú Ìpọ́njú, 2/15

“Ja Ìjà Àtàtà ti Ìgbàgbọ́,” 2/15

Ǹjẹ́ Àìdá-sí-Ìṣèlú Dí Ìfẹ́ Kristẹni Lọ́wọ́? 5/1

Ogún Tó Yẹ Kéèyàn Fi Sílẹ̀ fún Àwọn Ọmọ, 9/1

Ohun Tó O Lè Ṣe Nígbà Tí Nǹkan Bá Tojú Sú Ọ, 9/1

O Lè Borí Iyèméjì, 2/1

Ọmọ Títọ́, 6/15

Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa, 3/15

Ṣé Ìṣòro Tó Dé Bá Ọ Ló Ń Darí Ìgbésí Ayé Rẹ? 6/1

Tẹjú Mọ́ Èrè Náà, 4/1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

A Bù Kún Wa Jìngbìnnì Nítorí Pé A ní Ẹ̀mí Míṣọ́nnárì (T. Cooke), 1/1

Àwọn Nǹkan Díẹ̀ Tá A Yááfì Jẹ́ Ká Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún (G. àti A. Aljian), 4/1

Ẹ̀kọ́ Tí Mo Ti Ń Kọ Láti Kékeré (H. Gluyas), 10/1

Ìgbà Tí Mo Fọ́jú Lójú Mi Tó Là! (E. Hauser), 5/1

Ìṣàkóso Ọlọ́run Làwá Fara Mọ́ (M. Žobrák), 11/1

Mo Gbé Ìgbésí Ayé Aláyọ̀ Láìfi Ìrora Ọkàn Pè (A. Hyde), 7/1

Mo Gbọ́kàn Lé Jèhófà Pé Á Bójú Tó Mi (A. Denz Turpin), 12/1

Mo Jáde Látinú Àjàalẹ̀ Lọ sí Switzerland (L. Walther), 6/1

Mo Ń Gbádùn Inú Rere àti Àbójútó Jèhófà (F. King), 2/1

Níní Ìtẹ́lọ́rùn Tí Ọlọ́run Ń Fúnni Ti Mẹ́sẹ̀ Mi Dúró (I. Osueke), 3/1

Okun Jèhófà La Gbára Lé (E. Haffner), 8/1

Yíyọ̀ǹda Ara Wa Ti Jẹ́ Kí Ayé Wa Dára Kó sì Láyọ̀ (M. àti R. Szumiga), 9/1

JÈHÓFÀ

“Àwọn Iṣẹ́ Rẹ Mà Pọ̀ O!” 11/15

Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, 11/1

‘Kí Ìfẹ́ Rẹ Ṣẹ Lórí Ilẹ̀ Ayé,’ 4/15

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Tiẹ̀ Bìkítà Nípa Wa? 1/1

O Lè Múnú Ọlọ́run Dùn, 5/15

Ọlọ́run Bìkítà fún Ọ Lóòótọ́, 7/1

JÉSÙ KRISTI

Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Rẹ̀—Ṣóòótọ́ Ni Àbí Ìtàn Àròsọ? 7/15

Ìṣẹ̀lẹ̀ Mánigbàgbé Kan, 12/15

KÀLẸ́ŃDÀ

“Àwọn Igi Jèhófà Ní Ìtẹ́lọ́rùn,” 1/15

“Àwọn Iṣẹ́ Rẹ Mà Pọ̀ O!” 11/15

‘Àwọn Odò Pàtẹ́wọ́,’ 5/15

‘Ìgbà Ẹ̀rùn àti Ìgbà Òtútù Kì Yóò Kásẹ̀ Nílẹ̀ Láé,’ 7/15

‘Ìwọ Ní Ọlá Ńlá Ju Àwọn Òkè Ńlá Lọ,’ 3/15

“Ọ̀pọ̀ Jaburata Ọlá Àwọn Òkun,” 9/15

LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Aláyọ̀ Ni Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà, 11/1

“Àṣẹ Àgbékalẹ̀ Jèhófà” Kò Lè Kùnà, 7/15

Àwámáridìí Ni Títóbi Jèhófà, 1/15

Àwọn Àgbàlagbà—Ẹni Ọ̀wọ́n Ni Wọ́n Nínú Ẹgbẹ́ Ará, 5/15

Àwọn Wo Ló Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run Lónìí? 10/1

Bí A Ṣe Lè Máa Finú Rere Hàn Nínú Ayé Oníwà Òǹrorò Yìí, 4/15

Bí A Ṣe Lè Ní Èrò Kristi Nípa Ipò Ọlá, 8/1

Bíbójútó Àwọn Àgbàlagbà—Ojúṣe Àwọn Kristẹni, 5/15

‘Ẹ Kọ́ Wọn Láti Pa Gbogbo Ohun Tí Mo Ti Pa Láṣẹ fún Yín Mọ́,’ 7/1

“Ẹ Gbé Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀,” 9/15

Ẹ Jẹ́ Onígboyà Bíi Jeremáyà, 5/1

‘Ẹ Lọ, Kí Ẹ Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn’ 7/1

“Ẹ Máa Bá A Lọ Ní Gbígba Agbára Nínú Olúwa,” 9/15

Ẹ Máa “Fi Ẹnu Kan” Yin Ọlọ́run Lógo, 9/1

Ẹ Máa fún Ara Yín Lókun, 5/1

“Ẹ Ní Ìfẹ́ni Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún Ara Yín,” 10/1

Ẹ Wá Jèhófà, Olùṣàyẹ̀wò Ọkàn, 11/15

‘Ẹrú Olóòótọ́’ Náà Yege Nígbà Àbẹ̀wò! 3/1

“Ẹrú” Tí Ó Jẹ́ Olóòótọ́ àti Olóye, 3/1

Ẹ Ṣọ́ra fún “Ohùn Àwọn Àjèjì,” 9/1

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ǹjẹ́ Ẹ Ń Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Ọ̀la? 5/1

Fi Ìgboyà Wàásù Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 11/15

Fi Ojú Pàtàkì Wo Ẹ̀bùn Ìwàláàyè Rẹ, 6/15

Gbára Lé Ẹ̀mí Ọlọ́run Nígbà Tí Nǹkan Bá Yí Padà, 4/1

Ìbùkún Ni fún Àwọn Tó Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run, 6/1

Ìdájọ́ Jèhófà Yóò Dé Sórí Àwọn Ẹni Ibi, 11/15

Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pọ̀, 1/15

“Ìrísí Ìran Ayé Yìí Ń Yí Padà,” 2/1

“Ìró Wọn Jáde Lọ sí Gbogbo Ilẹ̀ Ayé,” 1/1

Ìṣẹ̀dá Ń Polongo Ògo Ọlọ́run! 6/1

Jèhófà Ni Olùrànlọ́wọ́ Wa, 12/15

Jèhófà Ń Pèsè Àwọn Ohun Tá A Nílò Lójoojúmọ́ (Àdúrà Olúwa), 2/1

Jèhófà Ń Ṣí Ògo Rẹ̀ Payá Fáwọn Onírẹ̀lẹ̀, 8/1

Jèhófà, ‘Odi Agbára Wa Ní Àkókò Wàhálà,’ 8/15

Jẹ́ Kí Ọlọ́run Alààyè Tọ́ Ẹ Sọ́nà, 6/15

Jẹ́ Oníwà Mímọ́ Nípa Dídáàbò Bo Ọkàn Rẹ, 2/15

Kí Gbogbo Ènìyàn Máa Kéde Ògo Jèhófà, 1/1

Kí Nìdí Tó O Fi Gbà Pé Párádísè Ń Bọ̀? 10/15

Kọ Ẹ̀mí Ayé Tó Ń Yí Padà Yìí, 4/1

“Lọ Káàkiri La Ilẹ̀ Náà Já,” 10/15

Máa Rìn Ní Ọ̀nà Ìwà Títọ́, 12/1

Ǹjẹ́ O Mọrírì Ìrànlọ́wọ́ Jèhófà? 12/15

Ǹjẹ́ O Ní Inú Dídùn sí “Òfin Jèhófà”? 7/15

“Olúwa, Kọ́ Wa Bí A Ṣe Ń Gbàdúrà” (Àdúrà Olúwa), 2/1

Ó Ń Rẹ̀ Wa àmọ́ A Kì Í Ṣàárẹ̀, 8/15

Ó Yẹ Kí Èèyàn Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Inú Rere, 4/15

“Ṣàṣeparí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Ní Kíkún,” 3/15

“Ṣe Iṣẹ́ Ajíhìnrere,” 3/15

Ṣọ́ra fún Ọtí Àmujù, 12/1

Ṣọ́ra fún Ẹ̀tàn, 2/15

Wọ́n Kórìíra Wa Láìnídìí, 8/15

Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni sí Wa Síbẹ̀ À Ń Láyọ̀, 11/1

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Àdúrà Olúwa, 9/15

Àlàáfíà, 1/1

Àmì 666 Kì Í Ṣe Àdììtú Àmì, 4/1

Ánábatíìsì, 6/15

Aṣáájú Rere, 11/1

Àwọn Eré Ìdárayá Ayé Àtijọ́, 5/1

Àwọn Ìránṣẹ́ Ọlọ́run Dà Bí Igi, 3/1

Àwọn Nǹkan Tẹ̀mí, 10/15

‘Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Jogún Ayé,’ 10/1

Àwọn Ọlọ Tó Pilẹ̀ Oúnjẹ, 9/15

Éhúdù, 3/15

Ẹranko Ẹhànnà Náà àti Àmì Rẹ̀, 4/1

Ibi Tá A Ti Lè Rí Ìmọ̀ràn Tó Ṣeni Láǹfààní, 8/15

Ìjọba Rere, 8/1

Ìjọba Ọlọ́run Ń Gbé Nǹkan Ṣe Lónìí, 8/1

Ìjọsìn Tòótọ́ àti Ìbọ̀rìṣà Forí Gbárí (Éfésù), 12/15

Ìlérí Ta Lo Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé? 1/15

Ìpàdé Àlàáfíà Westphalia, 3/15

Ipò Rẹ Nípa Tẹ̀mí àti Ìlera Rẹ, 2/1

Kapadókíà, 7/15

Kí Ló Ń Mú Kí Ayé Ẹni Dára? 8/1

Lẹ́tà Tí Ọmọbìnrin Kan Kọ sí Nóà, 7/1

Ǹjẹ́ Àdúrà Lè Yí Ìṣòro Rẹ Padà? 6/15

Ǹjẹ́ A Lè Yọ Ṣọ́ọ̀ṣì Nínú Ìṣòro? 3/1

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Àwọn Áńgẹ́lì? 4/1

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Ní Ẹ̀sìn Tìrẹ? 6/1

Ǹjẹ́ Ó Wù Ọ́ Láti Wà Láàyè Títí Láé? 11/15

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Àlùfáà Máa Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú? 5/1

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀, 9/1

Ohun Tó O Nílò Nípa Tẹ̀mí, 2/1

“Ọ̀kan Lára Àwọn Àgbà Iṣẹ́,” 1/15

“Ọlọ́run Tòótọ́ Náà àti Ìyè Àìnípẹ̀kun” (1Jo 5:20), 10/15

Rèbékà, 4/15

Ṣé Ìsìn Ló Fa Ìṣòro Aráyé? 2/15

‘Wọ́n Ṣíkọ̀ Lọ sí Kípírọ́sì,’ 7/1

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́