Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2011
Àṣírí Tú! Irọ́ Márùn-ún Táwọn Èèyàn Ń Pa Mọ́ Ọlọ́run
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Wọ́n Ti Parọ́ fún Ẹ Rí?
4 Ọlọ́run Kò Ṣeé Mọ̀—Ṣé Òótọ́ Ni?
5 Ọlọ́run Kò Bìkítà—Ṣé Òótọ́ Ni?
6 Ọlọ́run Kì Í Dárí Jini—Ṣé Òótọ́ Ni?
7 Ọlọ́run Kò Ṣe Ohun Tó Tọ́—Ṣé Òótọ́ Ni?
8 Gbogbo Ìjọsìn Tó Wá Látọkàn Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà—Ṣé Òótọ́ Ni?
9 Òtítọ́ Lè Yí Ìgbésí Ayé Rẹ Pa Dà
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
11 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
12 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
15 Sún Mọ́ Ọlọ́run—O Lè Rí “Ìmọ̀ Ọlọ́run”
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Rẹ Jẹ́ Aláyọ̀?
18 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Gbèjà Àwọn Èèyàn Ọlọ́run
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Àkókò Tí Kò Yẹ Ká Sùn
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
14 “Wọ́n Kọ̀ Jálẹ̀—Ó Yẹ Ká Bọ̀wọ̀ fún Wọn”
26 Ìgbà Wo Ni Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Àtijọ́ Run?—Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Rẹ̀; Àwọn Ẹ̀rí Tá A Rí