Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 15, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
SEPTEMBER 24-30, 2012
OCTOBER 1-7, 2012
Ẹ Máa Bá A Nìṣó Gẹ́gẹ́ Bí Ọmọ Ìjọba Ọlọ́run!
OJÚ ÌWÉ 11 • ÀWỌN ORIN: 16, 98
OCTOBER 8-14, 2012
OJÚ ÌWÉ 20 • ÀWỌN ORIN: 61, 25
OCTOBER 15-21, 2012
Ẹ Dúró Gbọn-in Kẹ́ Ẹ sì Sá fún Àwọn Ohun Tí Sátánì Fi Ń Múni!
OJÚ ÌWÉ 25 • ÀWỌN ORIN: 32, 83
OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 OJÚ ÌWÉ 3 sí 7
Dáníẹ́lì sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé “ìmọ̀ tòótọ́” yóò di púpọ̀ ní “àkókò òpin.” (Dán. 12:4) Àsọtẹ́lẹ̀ yẹn ti ní ìmúṣẹ lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀, àpilẹ̀kọ yìí sì ṣàlàyé bó ṣe rí bẹ́ẹ̀. Ó tún fi ẹ̀rí hàn pé Jésù wà pẹ̀lú àwọn tó ń sin Jèhófà Ọlọ́run.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2 OJÚ ÌWÉ 11 sí 15
Àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kó o mọ àwọn tó jẹ́ ojúlówó ọmọ Ìjọba Ọlọ́run. Ó jíròrò ohun tí Ọlọ́run fẹ́ kí wọ́n ṣe. Ó sì tún ṣàlàyé bí wọ́n ṣe ń fi hàn pé àwọn nífẹ̀ẹ́ àwọn ìlànà Jèhófà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 29
Sátánì sábà máa ń fi ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ lo àwọn ohun tó fara sin láti mú wa bó ti ń sapá láti dojú ìgbàgbọ́ wa dé. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bá a ṣe lè dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ márùn-ún lára àwọn ohun tó fi ń múni. Irú bíi sísọ̀rọ̀ gbàùgbàù, ìbẹ̀rù àti ẹ̀mí ṣohun-tẹ́gbẹ́-ń-ṣe, ìmọ̀lára ẹ̀bi tó kọjá bó ṣe yẹ, ìfẹ́ ọrọ̀ àlùmọ́nì àti ìdẹwò láti ṣe panṣágà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
8 “Ẹ̀san Wà fún Ìgbòkègbodò Yín”
16 Ìpàdé Tó Fi Ìṣọ̀kan Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Hàn Tó sì Sọ Nípa Àwọn Ìwéwèé Tó Wúni Lórí
Àwòrán Ẹ̀yìn Ìwé: Akéde Ìjọba Ọlọ́run tó ń wàásù fún darandaran kan ní àgbègbè Bafatá ní orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau
ORÍLẸ̀-ÈDÈ GUINEA-BISSAU
IYE ÈÈYÀN
1,515,000
IYE AKÉDE
120
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
389