Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 8
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 8
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Kíróníkà 21-25
No. 1: 1 Kíróníkà 22:11-19
No. 2: Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Wa fún Òtítọ́ Máa Pọ̀ Sí I?
No. 3: Bá A Ṣe Lè Dá Àwọn Ànímọ́ Ọlọ́run Mọ̀ (td 34D)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Máa Wá Onírúurú Ọ̀nà Láti Jẹ́rìí. (Ìṣe 16:13) Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ June 15, 2008, ojú ìwé 16 sí 17. Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá jíròrò ìrírí náà, ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n kọ́.
15 min: “Àwọn Pápá Ti Funfun fún Kíkórè.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.