ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 8/11 ojú ìwé 7
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 29

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 29
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 29
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
km 8/11 ojú ìwé 7

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 29

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 29

Orin 33 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

bt orí 8 ìpínrọ̀ 17 sí 24, àti àpótí tó wà lójú ìwé 67 (25 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Sáàmù 110-118 (10 min.)

Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run (20 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 128

10 min: Àwọn Ìfilọ̀. Lo àbá tó sọ nípa bá a ṣe lè gbọ́rọ̀ kalẹ̀, tó wà lójú ìwé 8, láti ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Saturday àkọ́kọ́ lóṣù September, kó o sì fún gbogbo àwọn ará ní ìṣírí láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Lẹ́yìn náà, sọ àsọyé tó dá lórí “Ẹ Lè Fún Un Ní Àwọn Ìwé Ìròyìn Tí Ọjọ́ Wọn Ti Pẹ́ Tàbí Ìwé Pẹlẹbẹ Èyíkéyìí Tó Sọ̀rọ̀ Nípa Ohun Tí Onílé Nífẹ̀ẹ́ Sí.”

15 min: Wọ́n Jẹ́ Onítara Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Wọ́n Ti Darúgbó. Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ August 1, 1998, ojú ìwé 32; January 15, 2007 ojú ìwé 32; June 1, 2007 ojú ìwé 22 sí 23 àti December 15, 2010, ojú ìwé 25. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.

10 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Àwọn Ìwé Ìròyìn Lóṣù September. Ìjíròrò. Fi ìṣẹ́jú kan tàbí méjì sọ̀rọ̀ lórí ohun tó wà nínú àwọn ìwé ìròyìn náà. Lẹ́yìn náà, yan àpilẹ̀kọ méjì tàbí mẹ́ta, kó o wá ní kí àwọn ará sọ àwọn ìbéèrè àti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tí wọ́n lè fi gbé ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀. Ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè lo ìtẹ̀jáde kọ̀ọ̀kan.

Orin 122 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́