Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní March 12
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MARCH 12
Orin 40 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 18 ìpínrọ̀ 1 sí 5, àti àpótí tó wà ní ojú ìwé 142 àti 144 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jeremáyà 5-7 (10 min.)
No. 1: Jeremáyà 5:15-25 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ṣé Ẹ̀sìn Tuntun Ni Ẹ̀sìn Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?—td 12A (5 min.)
No. 3: Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Lọ́wọ́ Àwọn Ohun Tó Lè Ba Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Rẹ̀ Jẹ́? (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Kọ́ Bí A Ṣe Ń Jẹ́ Olùkọ́ Tó Múná Dóko—Apá 2. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 57, ìpínrọ̀ 3, sí ìsọ̀rí tó wà lójú ìwé 59.
10 min: Máa Rú Ẹbọ Ìyìn sí Ọlọ́run Nígbà Gbogbo. (Héb. 13:15) Ìjíròrò. A gbé e ka Ilé Ìṣọ́ June 15, 2008, ojú ìwé 16 àti 17. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n kọ́.
10 min: “Ẹ Máa Ṣe Èyí.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ibi tẹ́ ẹ ti máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi àti àkókó tẹ́ ẹ máa ṣe é.
Orin 109 àti Àdúrà