Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní July 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JULY 23
Orin 43 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 24 ìpínrọ̀ 1 sí 9, àti àpótí tó wà ní ojú ìwé 193 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ìsíkíẹ́lì 18-20 (10 min.)
No. 1: Ìsíkíẹ́lì 19:1-14 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìrántí Ikú Kristi—td 28A (5 min.)
No. 3: Kí Ni Ọ̀rọ̀ Tó Wà Nínú Mátíù 21:43 Túmọ̀ Sí? (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Máa Lo Àwọn Ohun Tí A Lè Fojú Rí Lọ́nà Tó Múná Dóko. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 247 sí 249, ìpínrọ̀ 2. Ní ṣókí, ṣe àṣefihàn kókó kan tàbí méjì látinú àpilẹ̀kọ náà.
20 min: Jèhófà Ni Olùgbọ́ Àdúrà. (Sm. 66:19) Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ May 1, 2003 ojú ìwé 4 sí 7. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
Orin 56 àti Àdúrà