Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 10
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 10
Orin 23 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 26 ìpínrọ̀ 9 sí 15, àti àpótí tó wà lójú ìwé 208 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ìsíkíẹ́lì 42-45 (10 min.)
No. 1: Ìsíkíẹ́lì 43:13-27 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ọkọ Kò Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Kí Aya Dí Òun Lọ́wọ́ Sísin Ọlọ́run—td 6D (5 min.)
No. 3: Kí La Gbọ́dọ̀ Ṣe Ká Lè Rí Ẹ̀mí Mímọ́ Gbà? (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Ń Mú Ká Dáńgájíá Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́. Ìjíròrò tó dá lórí ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 27 sí 32.
10 min: Ohun Ìjà Yòówù Tí Wọ́n Bá Ṣe sí Ọ Kì Yóò Ṣe Àṣeyọrí. (Aísá. 54:17) Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ September 15, 2008, ojú ìwé 7, ìpínrọ̀ 1 sí 6. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
10 min: “Máa Lo Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tó Gbéṣẹ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 44 àti Àdúrà