ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NEHEMÁYÀ 5-8
Alábòójútó Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Ni Nehemáyà
Oṣù Tíṣírì, ọdún 455 Ṣ.S.K.
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé àkókò yìí ni Nehemáyà sọ fáwọn èèyàn náà pé kí wọ́n kóra jọ láti jọ́sìn Ọlọ́run
Àwọn èèyàn náà yọ ayọ̀ ńláǹlà
Àwọn olórí ìdílé kóra jọ láti sọ̀rọ̀ lórí bí wọ́n á ṣe máa pa Òfin Ọlọ́run mọ́ délẹ̀délẹ̀
Àwọn èèyàn náà kóra jọ láti ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà