ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 8
  • November 28 sí December 4

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 28 sí December 4
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 8

November 28 Sí December 4

ORIN SÓLÓMỌ́NÌ 1-8

  • Orin 106 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọmọbìnrin Ṣúlámáítì Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Tá A Lè Tẹ̀ Lé”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Orin Sólómọ́nì.]

    • Sol 2:7; 3:5​—Ọmọbìnrin Ṣúlámáítì pinnu láti dúró dìgbà táá fi rí ẹni tó máa nífẹ̀ẹ́ tọkàntọkàn (w15 1/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 11 sí 13)

    • Sol 4:12; 8:8-10​—Ní gbogbo àkókò tó fi dúró, ó jẹ́ adúróṣinṣin àti oníwà mímọ́ (w15 1/15 ojú ìwé 31 àti 32 ìpínrọ̀ 14 sí 16)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sol 2:1​—Ànímọ́ wo ló gbé ẹwà Ṣúlámáítì yọ dáadáa? (w15 1/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 13)

    • Sol 8:6​—Kí nìdí tí Bíbélì fi pe ìfẹ́ tòótọ́ ní “ọwọ́ iná Jáà”? (w15 1/15 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 3; w06 11/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 7)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sol 2:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh​—Lo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? láti fi nasẹ̀ ìwé náà. (Àkíyèsí: Ẹ má ṣe wo fídíò yìí nígbà àṣefihàn náà.)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 30 àti 31 ìpínrọ̀ 8 àti 9

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 115

  • “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé​—Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?”: (9 min.) Àsọyé tó dá lórí àpilẹ̀kọ tá a pè àkòrí rẹ̀ ní “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé​—Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?”

  • Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán?: (6 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó tá a pe àkọlé rẹ̀ ní, Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán? kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 16 sí 23, pótí náà “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 34 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́