ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Orin Sólómọ́nì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Orin Sólómọ́nì

    • Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍ JERÚSÁLẸ́MÙ (3:6–8:4)

Orin Sólómọ́nì 4:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:1; Di 3:12; Sol 6:5-7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2006, ojú ìwé 19

Orin Sólómọ́nì 4:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ̀bátí.”

Orin Sólómọ́nì 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “apata ribiti.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sol 1:10
  • +Ne 3:25; Sol 7:4
  • +2Sa 8:7; 2Ọb 11:10

Orin Sólómọ́nì 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sol 7:3

Orin Sólómọ́nì 4:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Títí ọjọ́ yóò fi bẹ̀rẹ̀ sí í mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:5

Orin Sólómọ́nì 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sol 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 30

    11/15/2006, ojú ìwé 20

Orin Sólómọ́nì 4:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Òkè Lẹ́bánónì Kejì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:25
  • +Di 3:8, 9; Sm 133:3

Orin Sólómọ́nì 4:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 5:18, 19

Orin Sólómọ́nì 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sol 7:12
  • +Sol 1:2, 4
  • +Ẹst 2:12; Sol 1:12

Orin Sólómọ́nì 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:24
  • +Sol 5:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 30

    11/15/2006, ojú ìwé 19

Orin Sólómọ́nì 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 32

    11/15/2006, ojú ìwé 20

    11/1/2000, ojú ìwé 11

Orin Sólómọ́nì 4:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Awọ.”

  • *

    Tàbí “párádísè pómégíránétì.”

Orin Sólómọ́nì 4:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Esùsú tó ń ta sánsán.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 12:3
  • +Ais 43:24
  • +Owe 7:17
  • +Sm 45:8
  • +Ẹk 30:23, 24, 34; Isk 27:2, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2014, ojú ìwé 10

Orin Sólómọ́nì 4:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 18:14

Orin Sólómọ́nì 4:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Fẹ́ yẹ́ẹ́.”

Àwọn míì

Orin Sól. 4:1Nọ 32:1; Di 3:12; Sol 6:5-7
Orin Sól. 4:4Sol 1:10
Orin Sól. 4:4Ne 3:25; Sol 7:4
Orin Sól. 4:42Sa 8:7; 2Ọb 11:10
Orin Sól. 4:5Sol 7:3
Orin Sól. 4:6Onw 2:5
Orin Sól. 4:7Sol 4:1
Orin Sól. 4:8Di 3:25
Orin Sól. 4:8Di 3:8, 9; Sm 133:3
Orin Sól. 4:9Owe 5:18, 19
Orin Sól. 4:10Sol 7:12
Orin Sól. 4:10Sol 1:2, 4
Orin Sól. 4:10Ẹst 2:12; Sol 1:12
Orin Sól. 4:11Owe 16:24
Orin Sól. 4:11Sol 5:1
Orin Sól. 4:14Jo 12:3
Orin Sól. 4:14Ais 43:24
Orin Sól. 4:14Owe 7:17
Orin Sól. 4:14Sm 45:8
Orin Sól. 4:14Ẹk 30:23, 24, 34; Isk 27:2, 22
Orin Sól. 4:15Jer 18:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Orin Sólómọ́nì 4:1-16

Orin Sólómọ́nì

4 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi.

Wò ó! O rẹwà gan-an.

Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà, lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú.

Irun rẹ dà bí agbo ewúrẹ́

Tí wọ́n ń rọ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè Gílíádì.+

 2 Eyín rẹ dà bí agbo àgùntàn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ gé irun wọn,

Tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ wẹ̀ fún,

Gbogbo wọn bí ìbejì,

Ọmọ ìkankan nínú wọn ò sì sọ nù.

 3 Ètè rẹ rí bí òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò,

Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ sì dùn.

Ẹ̀rẹ̀kẹ́* rẹ rí bí awẹ́ pómégíránétì

Lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú.

 4 Ọrùn rẹ+ dà bí ilé gogoro Dáfídì,+

Tí wọ́n fi òkúta kọ́,

Tí wọ́n gbé ẹgbẹ̀rún apata kọ́ sí ara rẹ̀,

Gbogbo apata* tó jẹ́ ti àwọn ọkùnrin alágbára.+

 5 Ọmú rẹ méjèèjì dà bí ọmọ àgbọ̀nrín méjì,

Ó dà bí ọmọ egbin+ tí wọ́n jẹ́ ìbejì,

Tí wọ́n ń jẹko láàárín àwọn òdòdó lílì.”

 6 “Màá lọ sórí òkè òjíá,

Màá gba ọ̀nà òkè tùràrí lọ,+

Títí afẹ́fẹ́ yóò fi bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ́,* tí òjìji kò sì ní sí mọ́.”

 7 “O rẹwà látòkè délẹ̀, olólùfẹ́ mi,+

Kò sí àbààwọ́n kankan lára rẹ.

 8 Jẹ́ ká jọ máa bọ̀ láti Lẹ́bánónì, ìyàwó mi,

Jẹ́ ká jọ máa bọ̀ láti Lẹ́bánónì.+

Sọ̀ kalẹ̀ láti téńté òkè Ámánà,*

Láti téńté òkè Sénírì, téńté òkè Hámónì,+

Látinú ihò kìnnìún, látorí àwọn òkè tí àwọn àmọ̀tẹ́kùn ń gbé.

 9 O ti gbà mí lọ́kàn,+ arábìnrin mi, ìyàwó mi,

Bí o ṣe ṣíjú wò mí báyìí, tí mo rí ọ̀kan nínú ẹ̀gbà ọrùn rẹ,

Bẹ́ẹ̀ lo gbà mí lọ́kàn.

10 Arábìnrin mi, ìyàwó mi, ìfẹ́ tí ò ń fi hàn sí mi mà dára o!+

Ìfẹ́ tí ò ń fi hàn sí mi dára ju wáìnì lọ,+

Kò sì sí lọ́fínńdà tó ń ta sánsán bíi tìrẹ!+

11 Oyin inú afárá+ ń kán tótó ní ètè rẹ, ìyàwó mi.

Oyin àti wàrà wà lábẹ́ ahọ́n rẹ,+

Aṣọ rẹ sì ń ta sánsán bíi ti Lẹ́bánónì.

12 Arábìnrin mi, ìyàwó mi, dà bí ọgbà tí wọ́n tì,

Ọgbà tí wọ́n tì, orísun omi tí wọ́n sé pa.

13 Àwọn ẹ̀ka* rẹ dà bí ọgbà pómégíránétì,*

Tó ní àwọn èso tó dára jù, àwọn ewé làálì pẹ̀lú ewé sípíkénádì,

14 Sípíkénádì+ àti òdòdó sáfúrónì, pòròpórò*+ àti igi sínámónì,+

Pẹ̀lú oríṣiríṣi igi tùràrí, òjíá àti álóè+

Àti gbogbo lọ́fínńdà tó dára jù.+

15 Orísun omi inú ọgbà ni ọ́, kànga omi tó mọ́

Àti odò tó ń ṣàn láti Lẹ́bánónì.+

16 Jí, ìwọ atẹ́gùn àríwá;

Wọlé wá, ìwọ atẹ́gùn gúúsù.

Fẹ́* sórí ọgbà mi.

Jẹ́ kí ìtasánsán rẹ̀ gbalẹ̀ kan.”

“Jẹ́ kí olólùfẹ́ mi wá sínú ọgbà rẹ̀

Kó sì jẹ àwọn èso rẹ̀ tó dára jù lọ.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́