ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 7
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú “Ilẹ̀kùn Ńlá”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú “Ilẹ̀kùn Ńlá”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀yin Èwe—Kí Ni Àwọn Góńgó Yín Nípa Tẹ̀mí?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1997
  • Gbé Àwọn Góńgó Tí Wàá Lépa ní Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Tuntun Kalẹ̀
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2003
  • Bọ́wọ́ Rẹ Ṣe Lè Tẹ Àwọn Àfojúsùn Rẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́run
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2006
  • Fi Àwọn Ohun Tó Ò Ń lé Nípa Tẹ̀mí Yin Ẹlẹ́dàá Rẹ Lógo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú “Ilẹ̀kùn Ńlá”

Ó máa ń rọrùn fún àwọn ọ̀dọ́ láti ronú pé kokooko lara àwọn le àti pé “àwọn ọjọ́ oníyọnu àjálù” tó máa ń bá ọjọ́ ogbó rìn nínú ayé Sátánì yìí kò lè dé bá àwọn. (Onw 12:1) Tó o bá jẹ́ ọ̀dọ́, ǹjẹ́ o máa ń ronú pé o ṣì ní àkókò tó pọ̀ tó o lè fi lé àwọn àfojúsùn tẹ̀mí bá, irú bíi ṣíṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún?

Gbogbo wa pátá, àtọmọdé àtàgbà ni “ìṣẹ̀lẹ̀ tí a kò rí tẹ́lẹ̀” máa ń ṣẹlẹ̀ sí. (Onw 9:11) Ìwé Jákọ́bù 4:14 sọ pé: “Ẹ kò mọ ohun tí ìwàláàyè yín yóò jẹ́ lọ́la.” Torí náà, má ṣe sún lílépa àwọn nǹkan tẹ̀mí síwájú láìnídìí. Gba ẹnu “ilẹ̀kùn ńlá tí ń ṣamọ̀nà sí ìgbòkègbodò” wọlé nígbà tó ṣì wà ní ṣíṣí sílẹ̀. (1Kọ 16:9) O kò ní kábàámọ̀ láé pé o ṣe bẹ́ẹ̀.

Àwọn àfojúsùn tẹ̀mí tó o lè máa lé:

  • Arábìnrin kan ń wàásù ní èdè mí ì

    Wíwàásù ní èdè míì

  • Arábìnrin àti arákùnrin tó ń ṣiṣẹ́ aṣáájú ọ̀nà

    Iṣẹ́ ìsìn aṣáájú-ọ̀nà

  • Arábìnrin àti arákùnrin tó wà ní ilé ẹ̀kọ́ ètò Ọlọ́run

    Lílọ sí ilé ẹ̀kọ́ ètò Ọlọ́run

  • Arábìnrin àti arákùnrin tó ń ṣiṣẹ́ ìkọ́lé

    Iṣẹ́ ìkọ́lé

  • A young brother in Bethel service

    Iṣẹ́ ìsìn Bẹ́tẹ́lì

  • Arákùnrin tó ń ṣiṣẹ́ alábòójútó àyíká

    Iṣẹ́ alábòójútó àyíká

Kọ àwọn àfojúsùn tẹ̀mí tó o lè máa lé:

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́