ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 November ojú ìwé 6
  • Wà Lójúfò Kó O sì Máa Sin Jèhófà Nìṣó

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wà Lójúfò Kó O sì Máa Sin Jèhófà Nìṣó
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Àkókò Tó Ṣẹ́ Kù Fún Àwọn Olubi Ti Pọ̀ Tó?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Kó O Lè Wà Láàyè!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Wòlíì​—Hábákúkù
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Náhúmù, Hábákúkù àti Sefanáyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 November ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NÁHÚMÙ 1–HÁBÁKÚKÙ 3

Wà Lójúfò Kó O sì Máa Sin Jèhófà Nìṣó

Hab 1:5, 6

Bí wọ́n ṣe kìlọ̀ pé àwọn ará Bábílónì máa pa ilẹ̀ Júdà run lè dá bí ohun tí kò lè ṣẹlẹ̀. Torí pé nígbà yẹn, ilẹ̀ Júdà gbára lé orílẹ̀-èdè Íjíbítì tó jẹ́ alágbára. Àwọn ará Kálídíà ò sì lágbára tó orílẹ̀-èdè Íjíbítì. Láfikún sí èyí, àwọn Júù ò gbà pé Jèhófà lè fàyè gbà á kí wọ́n pa Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpílì rẹ̀ run. Síbẹ̀, àsọtẹ́lẹ̀ yìí máa ṣẹ, Hábákúkù sì gbọ́dọ̀ wà lójúfò kó sì máa bá iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ sí Jèhófà lọ.

Wòlí ì Hábákúkù wà lójúfò nípa tẹ̀mí bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn burúkú ló yí i ká

Kí ló mú kó dá mi lójú pé ìparí ètò àwọn nǹkan yìí ti sún mọ́lé?

Báwo ni mo ṣe lè wà lójúfò kí n sì máa sin Jèhófà nìṣó?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́