ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 7-8
“Àlùfáà Títí Láé Ní Ọ̀nà Ti Melikisédékì”
Báwo ni Melikisédékì ṣe ṣàpẹẹrẹ Jésù?
7:1—Ọba àti àlùfáà
7:3, 22-25—Kò sí àkọsílẹ̀ kankan nípa ẹni tó wà ní ipò yẹn ṣáájú rẹ̀, kò sì sí àkọsílẹ̀ kankan nípa ẹni tó gbapò rẹ̀
7:5, 6, 14-17—Ó jẹ́ àlùfáà tá a yàn sípò, kì í ṣe torí pé ó ṣẹ̀ wá láti ìran àwọn àlùfáà
Báwo ni ipò àlùfáà Kristi ṣe ju ti ipò àlùfáà Áárónì lọ? (it-1 1113 ¶4-5)