ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w23 April ojú ìwé 32
  • Ohun Tó o Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó o Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé ò ń jàǹfààní àwọn ẹsẹ Bíbélì tá a ṣàlàyé nínú Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?
  • Ǹjẹ́ Ò Ń Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìwé Ìwádìí Tuntun
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Máa Lo Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
w23 April ojú ìwé 32

Ohun Tó o Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́

Ṣé ò ń jàǹfààní àwọn ẹsẹ Bíbélì tá a ṣàlàyé nínú Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Àwọn àlàyé tá a ṣe lórí àwọn ẹsẹ Bíbélì náà máa jẹ́ kó o túbọ̀ lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Àlàyé náà máa ń sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ẹsẹ Bíbélì kan, ìdí tí wọ́n fi kọ ọ́, ẹni tó ń sọ nípa ẹ̀ àti ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn kan.

ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower àti JW Library® máa jẹ́ kó o rí àwọn ìwé tó ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì kan nínú Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Tó o bá lo èyíkéyìí lára Bíbélì tó wà níbẹ̀, wàá rí àwọn ìwé tó o lè fi ṣèwádìí ní abala ìkẹ́kọ̀ọ́ lápá ọ̀tún.

Tó o bá ń lo àwọn ìwé náà, kíyè sí déètì tí wọ́n ṣe wọ́n. Àwọn àpilẹ̀kọ tó dé kẹ́yìn tó sọ̀rọ̀ nípa àwọn ẹsẹ Bíbélì kan máa ń wà lókè pátápátá. Àwọn àpilẹ̀kọ tó ti pẹ́ ló máa ń wà nísàlẹ̀, àwọn ọ̀rọ̀ tó wà nínú ẹ̀ sì lè jẹ́ òye tá a ní tẹ́lẹ̀ nípa ọ̀rọ̀ kan àmọ́ tá a ti ṣàtúnṣe ẹ̀.

  • Àwọn ìwé tó ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì tó wà nínú Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń hàn lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ.

  • Kó o tó lè rí àwọn ìwé tó ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì lórí JW Library, wa Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà jáde sórí fóònù tàbí kọ̀ǹpútà ẹ, kó o lè rí àwọn ìwé tuntun tó wà níbẹ̀. Bó o ṣe máa ṣe é ni pé kó o tẹ bọ́tìnì tó wà lókè pátápátá ní abala ìkẹ́kọ̀ọ́ tó wà lápá ọ̀tún orí Bíbélì tó o ṣí.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́