ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb16 ojú ìwé 177
  • Ìrántí Ikú Kristi—Friday, April 3, 2015

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìrántí Ikú Kristi—Friday, April 3, 2015
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi Ní March 1
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi Ní March 22
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2015
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • A Máa Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi Bẹ̀rẹ̀ Láti April 2
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
Àwọn Míì
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
yb16 ojú ìwé 177
Ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fún ẹnì kan ní ìwé pé kó wá sí Ìrántí Ikú Kristi

Ìrántí Ikú Kristi​—Friday, April 3, 2015

LÁTỌJỌ́ Sátidé, March 7, 2015, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé bẹ̀rẹ̀ sí í pe àwọn èèyàn pé kí wọ́n wá síbi tá a ti máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi kí wọ́n sì gbọ́ àlàyé nípa bí ikú Jésù Kristi ṣe ṣaráyé làǹfààní. Ọ̀sẹ̀ mẹ́rin gbáko la fi lọ káàkiri láti pe àwọn èèyàn. Ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù ìwé ìkésíni la fún àwọn èèyàn, a sọ fáwọn mí ì lórí fóònù tàbí nípasẹ̀ lẹ́tà. Ṣé àwọn èèyàn wá àbí wọn ò wá? Ẹ wo bí inú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti dùn tó nígbà tí 19,862,783 èèyàn pé jọ síbi Ìrántí Ikú Kristi ní Friday, April 3, 2015. A ti túbọ̀ ń koná mọ́ ìsapá wa ká lè ṣèrànwọ́ fún gbogbo àwọn tó wá lọ́jọ́ yẹn kí wọ́n lè máa dara pọ̀ mọ́ àwa èèyàn Jèhófà déédéé, káwọn náà lè máa jọ́sìn Ọlọ́run tòótọ́ kí wọ́n sì rí ojúure àti ìbùkún rẹ̀.​—Míkà 4:2.

Onírúurú ọ̀nà tí àwọn 19,862,783 tó wà sí Ìrántí Ikú Kristi gbà rí ìwé ìkésíni gbà
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́