NỌ́ŃBÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Wọ́n forúkọ àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun sílẹ̀ (1-46)
Àwọn ọmọ Léfì ò ní wọṣẹ́ ológun (47-51)
Bí wọ́n á ṣe pàgọ́ wọn létòlétò (52-54)
2
3
4
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Kóhátì (1-20)
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì (21-28)
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Mérárì (29-33)
Àròpọ̀ iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ (34-49)
5
Yíya àwọn aláìmọ́ sọ́tọ̀ (1-4)
Ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti sísan nǹkan dípò (5-10)
Lílo omi láti mọ̀ bóyá ẹnì kan ti ṣe àgbèrè (11-31)
6
7
8
Áárónì tan fìtílà méje (1-4)
Wọ́n wẹ àwọn ọmọ Léfì mọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ (5-22)
Ọjọ́ orí àwọn ọmọ Léfì tó lè ṣiṣẹ́ (23-26)
9
10
Kàkàkí tí wọ́n fi fàdákà ṣe (1-10)
Wọ́n kúrò ní Sínáì (11-13)
Bí wọ́n ṣe máa tò tẹ̀ léra tí wọ́n bá ń lọ (14-28)
Mósè ní kí Hóbábù fi ọ̀nà han Ísírẹ́lì (29-34)
Àdúrà Mósè tí wọ́n bá ń tú àgọ́ ká (35, 36)
11
Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run torí wọ́n ń ráhùn (1-3)
Wọ́n ń sunkún torí wọ́n fẹ́ jẹ ẹran (4-9)
Mósè wò ó pé òun ò kúnjú ìwọ̀n (10-15)
Jèhófà fi ẹ̀mí sára 70 àgbààgbà (16-25)
Ẹ́lídádì àti Médádì; Jóṣúà ń jowú torí Mósè (26-30)
Àwọn ẹyẹ àparò wá; Ọlọ́run fìyà jẹ wọ́n torí ìwọra wọn (31-35)
12
13
14
Wọ́n fẹ́ pa dà sí Íjíbítì (1-10)
Jèhófà bínú; Mósè bá wọn bẹ̀bẹ̀ (11-19)
Ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn: 40 ọdún nínú aginjù (20-38)
Àwọn ọmọ Ámálékì ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (39-45)
15
Òfin nípa ọrẹ (1-21)
Ọrẹ tí ẹni tó bá ṣèèṣì dẹ́ṣẹ̀ máa mú wá (22-29)
Ìyà tó máa jẹ ẹni tó bá mọ̀ọ́mọ̀ dẹ́ṣẹ̀ (30, 31)
Wọ́n pa ẹni tó rú òfin Sábáàtì (32-36)
Kí wọ́n máa ṣe wajawaja sí etí aṣọ wọn (37-41)
16
17
18
Ojúṣe àwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì (1-7)
Ìpín àwọn àlùfáà (8-19)
Kí àwọn ọmọ Léfì máa gba ìdá mẹ́wàá, kí wọ́n sì máa san án (20-32)
19
20
21
Wọ́n ṣẹ́gun ọba Árádì (1-3)
Ejò tí wọ́n fi bàbà ṣe (4-9)
Ísírẹ́lì lọ yí ká Móábù (10-20)
Wọ́n ṣẹ́gun Síhónì ọba àwọn Ámórì (21-30)
Wọ́n ṣẹ́gun Ógù ọba àwọn Ámórì (31-35)
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
Ìlú àwọn ọmọ Léfì (1-8)
Àwọn ìlú ààbò (9-34)
36