JÓÒBÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìwà títọ́ Jóòbù àti ọrọ̀ rẹ̀ (1-5)
Sátánì fẹ̀sùn kan Jóòbù (6-12)
Jóòbù pàdánù ohun ìní rẹ̀ àtàwọn ọmọ rẹ̀ (13-19)
Jóòbù ò dá Ọlọ́run lẹ́bi (20-22)
2
Sátánì tún fẹ̀sùn kan Jóòbù (1-5)
Ọlọ́run fàyè gba Sátánì pé kó kọlu ara Jóòbù (6-8)
Ìyàwó Jóòbù sọ pé: “Sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run, kí o sì kú!” (9, 10)
Àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù mẹ́ta dé (11-13)
3
4
5
6
Jóòbù fèsì (1-30)
Ó sọ pé òun ò jẹ̀bi bí òun ṣe ń ké jáde (2-6)
Ọ̀dàlẹ̀ ni àwọn tó ń tù ú nínú (15-18)
“Òótọ́ ọ̀rọ̀ kì í dunni!” (25)
7
8
9
Jóòbù fèsì (1-35)
Ẹni kíkú ò lè bá Ọlọ́run fà á (2-4)
‘Ọlọ́run ń ṣe àwọn ohun àwámáridìí’ (10)
Èèyàn ò lè bá Ọlọ́run jiyàn (32)
10
11
12
Jóòbù fèsì (1-25)
“Mi ò kéré sí yín” (3)
‘Mo wá di ẹni tí wọ́n fi ń ṣe ẹlẹ́yà’ (4)
‘Ọgbọ́n wà lọ́dọ̀ Ọlọ́run’ (13)
Ọlọ́run ga ju àwọn adájọ́ àti ọba lọ (17, 18)
13
14
15
16
17
18
19
Jóòbù fèsì (1-29)
Ó kọ ìbáwí àwọn “ọ̀rẹ́” rẹ̀ (1-6)
Ó ní wọ́n pa òun tì (13-19)
“Olùràpadà mi wà láàyè”(25)
20
21
22
23
Jóòbù fèsì (1-17)
Ó fẹ́ ro ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Ọlọ́run (1-7)
Ó ní òun ò rí Ọlọ́run (8, 9)
“Mò ń rìn ní ọ̀nà rẹ̀ ṣáá, mi ò sì yà kúrò níbẹ̀” (11)
24
25
26
Jóòbù fèsì (1-14)
“Wo bí o ṣe ran ẹni tí kò lágbára lọ́wọ́!” (1-4)
‘Ọlọ́run fi ayé rọ̀ sórí òfo’ (7)
‘Bíńtín lára àwọn ọ̀nà Ọlọ́run’ (14)
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
Jóòbù dá Jèhófà lóhùn (1-6)
Ọlọ́run bínú sí àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta (7-9)
Jèhófà pa dà bù kún Jóòbù (10-17)