JÒHÁNÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara (1-18)
Jòhánù Arinibọmi jẹ́rìí (19-28)
Jésù ni Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run (29-34)
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù kọ́kọ́ yàn (35-42)
Fílípì àti Nàtáníẹ́lì (43-51)
2
Ìgbéyàwó ní Kánà; omi di wáìnì (1-12)
Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (13-22)
Jésù mọ ohun tó wà nínú èèyàn (23-25)
3
4
Jésù àti obìnrin ará Samáríà (1-38)
Ọ̀pọ̀ àwọn ará Samáríà gba Jésù gbọ́ (39-42)
Jésù wo ọmọkùnrin òṣìṣẹ́ ọba kan sàn (43-54)
5
Ó wo ọkùnrin kan sàn ní Bẹtisátà (1-18)
Jésù gba àṣẹ lọ́dọ̀ Baba rẹ̀ (19-24)
Àwọn òkú máa gbọ́ ohùn Jésù (25-30)
Àwọn ẹ̀rí nípa Jésù (31-47)
6
Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (1-15)
Jésù rìn lórí omi (16-21)
Jésù ni “oúnjẹ ìyè” (22-59)
Ọ̀pọ̀ èèyàn kọsẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Jésù (60-71)
7
Jésù lọ síbi Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn (1-13)
Jésù ń kọ́ni níbi àjọyọ̀ náà (14-24)
Oríṣiríṣi ohun tí àwọn èèyàn ń sọ nípa Kristi (25-52)
8
Baba ń jẹ́rìí nípa Jésù (12-30)
Àwọn ọmọ Ábúráhámù (31-41)
Àwọn ọmọ Èṣù (42-47)
Jésù àti Ábúráhámù (48-59)
9
Jésù wo ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú sàn (1-12)
Àwọn Farisí ń bi ọkùnrin tó wò sàn ní ìbéèrè (13-34)
Àwọn Farisí fọ́jú (35-41)
10
Olùṣọ́ àgùntàn àti ọgbà àgùntàn (1-21)
Àwọn Júù ta ko Jésù níbi Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ (22-39)
Ọ̀pọ̀ àwọn Júù ò gbà gbọ́ (24-26)
“Àwọn àgùntàn mi máa ń fetí sí ohùn mi” (27)
Ọmọ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba (30, 38)
Ọ̀pọ̀ àwọn tó wà ní òdìkejì Jọ́dánì gbà gbọ́ (40-42)
11
Ikú Lásárù (1-16)
Jésù tu Màtá àti Màríà nínú (17-37)
Jésù jí Lásárù dìde (38-44)
Wọ́n gbìmọ̀ láti pa Jésù (45-57)
12
Màríà da òróró sí ẹsẹ̀ Jésù (1-11)
Jésù gun ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (12-19)
Jésù sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (20-37)
Àìnígbàgbọ́ àwọn Júù mú àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ (38-43)
Jésù wá gba ayé là (44-50)
13
Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-20)
Jésù fi hàn pé Júdásì ló máa da òun (21-30)
Àṣẹ tuntun (31-35)
Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (36-38)
14
15
Àpèjúwe àjàrà tòótọ́ (1-10)
Kristi pàṣẹ pé kí wọ́n ní irú ìfẹ́ tí òun ní (11-17)
Ayé kórìíra àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (18-27)
16
Wọ́n lè pa àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (1-4a)
Iṣẹ́ tí ẹ̀mí mímọ́ máa ṣe (4b-16)
Ìbànújẹ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn máa di ayọ̀ (17-24)
Jésù ti ṣẹ́gun ayé (25-33)
17
18
Júdásì da Jésù (1-9)
Pétérù lo idà (10, 11)
Wọ́n mú Jésù lọ sọ́dọ̀ Ánásì (12-14)
Ìgbà àkọ́kọ́ tí Pétérù sẹ́ (15-18)
Jésù dé iwájú Ánásì (19-24)
Pétérù sẹ́ lẹ́ẹ̀kejì àti lẹ́ẹ̀kẹta (25-27)
Jésù dé iwájú Pílátù (28-40)
19
Wọ́n na Jésù, wọ́n sì fi ṣe yẹ̀yẹ́ (1-7)
Pílátù tún bi Jésù léèrè ọ̀rọ̀ (8-16a)
Wọ́n kan Jésù mọ́ òpó igi ní Gọ́gọ́tà (16b-24)
Jésù ṣètò bí wọ́n ṣe máa bójú tó ìyá rẹ̀ (25-27)
Ikú Jésù (28-37)
Wọ́n sìnkú Jésù (38-42)
20
Ibojì ṣófo (1-10)
Jésù fara han Màríà Magidalénì (11-18)
Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (19-23)
Tọ́másì ṣiyèméjì, àmọ́ ó pa dà dá a lójú (24-29)
Ìdí tí wọ́n fi kọ àkájọ ìwé yìí (30, 31)
21
Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-14)
Pétérù fi dá Jésù lójú pé òun nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ (15-19)
Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́ (20-23)
Ọ̀rọ̀ ìparí (24, 25)