MÁÀKÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Jòhánù Onírìbọmi ń wàásù (1-8)
Jésù ṣèrìbọmi (9-11)
Sátánì dán Jésù wò (12, 13)
Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (14, 15)
Ó pe àwọn tó kọ́kọ́ di ọmọ ẹ̀yìn (16-20)
Ó lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde (21-28)
Jésù wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn ní Kápánáúmù (29-34)
Ó gbàdúrà níbi tó dá (35-39)
Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (40-45)
2
Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (1-12)
Jésù pe Léfì (13-17)
Wọ́n béèrè nípa ààwẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ (18-22)
Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (23-28)
3
Ó wo ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (1-6)
Èrò rẹpẹtẹ wá sí èbúté (7-12)
Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (13-19)
Ọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́ (20-30)
Ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ (31-35)
4
5
6
Wọn ò tẹ́wọ́ gba Jésù ní ìlú rẹ̀ (1-6)
Ó fún àwọn Méjìlá náà ní ìtọ́ni nípa iṣẹ́ ìwàásù (7-13)
Wọ́n pa Jòhánù Onírìbọmi (14-29)
Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (30-44)
Jésù rìn lórí omi (45-52)
Ó ṣe ìwòsàn ní Jẹ́nẹ́sárẹ́tì (53-56)
7
Ó tú àṣírí àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn èèyàn (1-13)
Inú ọkàn ni ohun tó ń sọni di aláìmọ́ ti ń wá (14-23)
Ìgbàgbọ́ obìnrin tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Foníṣíà ní Síríà (24-30)
Ó wo adití sàn (31-37)
8
Jésù bọ́ 4,000 èèyàn (1-9)
Wọ́n béèrè àmì (10-13)
Ìwúkàrà àwọn Farisí àti ti Hẹ́rọ́dù (14-21)
Ó wo afọ́jú kan sàn ní Bẹtisáídà (22-26)
Pétérù pè é ní Kristi (27-30)
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (31-33)
Ojúlówó ọmọ ẹ̀yìn (34-38)
9
A yí Jésù pa dà di ológo (1-13)
Ó wo ọmọkùnrin tí ẹ̀mí èṣù ń yọ lẹ́nu sàn (14-29)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (30-32)
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń jiyàn nípa ẹni tó tóbi jù (33-37)
Ẹni tí kò bá ta kò wá, tiwa ló ń ṣe (38-41)
Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (42-48)
“Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín” (49, 50)
10
Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-12)
Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-16)
Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ (17-25)
Àwọn ohun tí a yááfì torí Ìjọba náà (26-31)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (32-34)
Ohun tí Jémíìsì àti Jòhánù béèrè (35-45)
Ó wo Báátíméù afọ́jú sàn (46-52)
11
Jésù gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (1-11)
Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́ (12-14)
Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (15-18)
Ohun tí a rí kọ́ lára igi ọ̀pọ̀tọ́ tó rọ (19-26)
Wọ́n béèrè ẹni tó fún Jésù ní àṣẹ (27-33)
12
Àpèjúwe àwọn tó ń dáko tí wọ́n sì pààyàn (1-12)
Ọlọ́run àti Késárì (13-17)
Ìbéèrè nípa àjíǹde (18-27)
Àṣẹ méjì tó tóbi jù (28-34)
Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (35-37a)
Ó ní kí wọ́n ṣọ́ra fún àwọn akọ̀wé òfin (37b-40)
Opó aláìní fi ẹyọ owó méjì sílẹ̀ (41-44)
13
14
Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1, 2)
Ó da òróró onílọ́fínńdà sórí Jésù (3-9)
Júdásì da Jésù (10, 11)
Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn (12-21)
Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (22-26)
Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (27-31)
Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (32-42)
Wọ́n mú Jésù (43-52)
Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (53-65)
Pétérù sẹ́ Jésù (66-72)
15
Jésù dé iwájú Pílátù (1-15)
Wọ́n fi ṣẹlẹ́yà ní gbangba (16-20)
Wọ́n kàn án mọ́gi ní Gọ́gọ́tà (21-32)
Ikú Jésù (33-41)
Wọ́n sìnkú Jésù (42-47)
16