MÁTÍÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Àwọn awòràwọ̀ wá (1-12)
Wọ́n sá lọ sí Íjíbítì (13-15)
Hẹ́rọ́dù pa àwọn ọmọdékùnrin (16-18)
Wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì (19-23)
3
4
Èṣù dán Jésù wò (1-11)
Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (12-17)
Ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ (18-22)
Jésù ń wàásù, ó ń kọ́ni, ó sì ń woni sàn (23-25)
5
ÌWÀÁSÙ ORÍ ÒKÈ (1-48)
Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ni lórí òkè (1, 2)
Ohun mẹ́sàn-án tó ń múni láyọ̀ (3-12)
Iyọ̀ àti ìmọ́lẹ̀ (13-16)
Jésù máa mú Òfin ṣẹ (17-20)
Ìmọ̀ràn lórí ìbínú (21-26), àgbèrè (27-30), ìkọ̀sílẹ̀ (31, 32), ìbúra (33-37), ẹ̀san (38-42), nínífẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀tá (43-48)
6
7
8
Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (1-4)
Ọ̀gágun fi hàn pé òun nígbàgbọ́ (5-13)
Jésù wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn ní Kápánáúmù (14-17)
Bí a ṣe lè tẹ̀ lé Jésù (18-22)
Jésù mú kí ìjì dáwọ́ dúró (23-27)
Jésù lé àwọn ẹ̀mí èṣù lọ sínú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ (28-34)
9
Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (1-8)
Jésù pe Mátíù (9-13)
Ìbéèrè nípa ààwẹ̀ gbígbà (14-17)
Ọmọbìnrin Jáírù; obìnrin kan fọwọ́ kan aṣọ àwọ̀lékè Jésù (18-26)
Jésù wo afọ́jú àti ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀ sàn (27-34)
Ìkórè pọ̀, àmọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ò tó nǹkan (35-38)
10
Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (1-4)
Ìtọ́ni tó wà fún iṣẹ́ ìwàásù (5-15)
Wọ́n máa ṣe inúnibíni sí àwọn ọmọ ẹ̀yìn (16-25)
Ẹ bẹ̀rù Ọlọ́run, ẹ má bẹ̀rù èèyàn (26-31)
Mo wá láti mú idà wá, kì í ṣe àlàáfíà (32-39)
Gbígba àwọn ọmọ ẹ̀yìn (40-42)
11
Ó yin Jòhánù Arinibọmi (1-15)
Ó dẹ́bi fún ìran aláìgbọràn (16-24)
Jésù yin Bàbá rẹ̀ torí pé ó ṣojúure sí àwọn tó rẹlẹ̀ (25-27)
Àjàgà Jésù ń tuni lára (28-30)
12
Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (1-8)
Ó wo ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (9-14)
Ìránṣẹ́ tí Ọlọ́run fẹ́ràn (15-21)
Ó fi ẹ̀mí mímọ́ lé ẹ̀mí èṣù jáde (22-30)
Ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì (31, 32)
Èso igi la fi máa mọ̀ ọ́n (33-37)
Àmì Jónà (38-42)
Tí ẹ̀mí àìmọ́ bá pa dà wá (43-45)
Ìyá Jésù àtàwọn arákùnrin rẹ̀ (46-50)
13
14
Wọ́n gé orí Jòhánù Arinibọmi (1-12)
Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (13-21)
Jésù rìn lórí omi (22-33)
Ó ṣèwòsàn ní Jẹ́nẹ́sárẹ́tì (34-36)
15
Ó tú àṣírí àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ (1-9)
Inú ọkàn ni ohun tó ń sọni di aláìmọ́ ti ń wá (10-20)
Ìgbàgbọ́ obìnrin ará Foníṣíà lágbára gan-an (21-28)
Jésù wo ọ̀pọ̀ àìlera sàn (29-31)
Jésù bọ́ 4,000 èèyàn (32-39)
16
Wọ́n ń wá àmì (1-4)
Ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí (5-12)
Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba náà (13-20)
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (21-23)
Bí a ṣe lè jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn tòótọ́ (24-28)
17
Ìyípadà ológo (1-13)
Ìgbàgbọ́ bíi hóró músítádì (14-21)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (22, 23)
Wọ́n fi owó ẹnu ẹja san owó orí (24-27)
18
Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba náà (1-6)
Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (7-11)
Àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù (12-14)
Bí o ṣe lè jèrè arákùnrin (15-20)
Àpèjúwe ẹrú tí kò dárí jini (21-35)
19
Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-9)
Ẹ̀bùn wíwà láìlọ́kọ tàbí láìláya (10-12)
Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-15)
Ìbéèrè ọ̀dọ́kùnrin ọlọ́rọ̀ (16-24)
Àwọn ohun tí a fi sílẹ̀ nítorí Ìjọba náà (25-30)
20
Àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà gba iye owó kan náà (1-16)
Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (17-19)
Wọ́n ń wá ipò nínú Ìjọba náà (20-28)
Ó wo ọkùnrin afọ́jú méjì sàn (29-34)
21
Jésù wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ (1-11)
Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-17)
Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́ (18-22)
Wọ́n béèrè àṣẹ tí Jésù fi ń ṣe nǹkan (23-27)
Àpèjúwe àwọn ọmọ méjì (28-32)
Àpèjúwe àwọn tó ń dáko, tí wọ́n sì pààyàn (33-46)
22
Àpèjúwe ayẹyẹ ìgbéyàwó (1-14)
Ọlọ́run àti Késárì (15-22)
Ìbéèrè nípa àjíǹde (23-33)
Àṣẹ méjì tó tóbi jù (34-40)
Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (41-46)
23
Ẹ má tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí (1-12)
Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí gbé (13-36)
Jésù dárò lórí Jerúsálẹ́mù (37-39)
24
25
26
Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1-5)
Ó da òróró onílọ́fínńdà sára Jésù (6-13)
Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn àti ẹni tó máa da Jésù (14-25)
Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (26-30)
Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (31-35)
Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (36-46)
Wọ́n mú Jésù (47-56)
Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (57-68)
Pétérù sẹ́ Jésù (69-75)
27
Wọ́n fa Jésù lé Pílátù lọ́wọ́ (1, 2)
Júdásì pokùnso (3-10)
Jésù dé iwájú Pílátù (11-26)
Wọ́n fi ṣẹlẹ́yà ní gbangba (27-31)
Wọ́n kàn án mọ́gi ní Gọ́gọ́tà (32-44)
Ikú Jésù (45-56)
Wọ́n sìnkú Jésù (57-61)
Wọ́n sé ibojì rẹ̀ mọ́ (62-66)
28